YO/Prabhupada 1062 - Awa sin'iwa lati fe ni idari lori iseda aye yi: Difference between revisions

(Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1062 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
 
(Vanibot #0019: LinkReviser - Revised links and redirected them to the de facto address when redirect exists)
 
Line 10: Line 10:
[[Category:Yoruba Language]]
[[Category:Yoruba Language]]
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- END CATEGORY LIST -->
<!-- BEGIN NAVIGATION BAR -- DO NOT EDIT OR REMOVE -->
{{1080 videos navigation - All Languages|Yoruba|YO/Prabhupada 1061 - Ninu Bhagavad-gita, lati ni oye nipa ooto oro marun orisirisi ni koko oro re je|1061|YO/Prabhupada 1063 - Funwa ni irorun lati ise ati abajade ise wa|1063}}
<!-- END NAVIGATION BAR -->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<!-- BEGIN ORIGINAL VANIQUOTES PAGE LINK-->
<div class="center">
<div class="center">
Line 18: Line 21:


<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
<!-- BEGIN VIDEO LINK -->
{{youtube_right|dUNonnye1zk|We Have the Tendency of Controlling Over the Material Nature - Prabhupāda 1062}}
{{youtube_right|dUNonnye1zk|Awa sin'iwa lati fe ni idari lori iseda aye yi<br />- Prabhupāda 1062}}
<!-- END VIDEO LINK -->
<!-- END VIDEO LINK -->


<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<!-- BEGIN AUDIO LINK -->
<mp3player>File:660219BG-NEW_YORK_clip06.mp3</mp3player>
<mp3player>https://s3.amazonaws.com/vanipedia/clip/660219BG-NEW_YORK_clip06.mp3</mp3player>
<!-- END AUDIO LINK -->
<!-- END AUDIO LINK -->


Line 30: Line 33:


<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
<!-- BEGIN TRANSLATED TEXT -->
Sugbon asise wa niyen. Nigbat'awa ba ri awon nkan iyanu ton sele ninu iseda aye yi, oye koye wa wipe lehin gbogbo awon nkan wanyi, oludari kan wa. Kosi nkankan tele dasile lai ni idari lori re. Ironu omode loje teyan ba rowipe kos'Olori kankan. gege bi oko to da gan, to yara, pelu erop inu re to da gan, ton saare lopju titi. Omode le ronu wipe "bawo ni oko yi sen sare, laisi esin kankan ton fa?" sugbon eyan toba logbon tabi agba, o mo wipe pelu gbogbo ero towa ninu oko na, laisi oniwako, kosi bosele rin. Ero towa ninu oko, tabi ninu ile-ina monamona.. Nisin lasi asiko tawayi, asik awon ero lawa, sugbon oye ko ye wa pe lehin gbogbo awon ero wanyi, leyin ise nla t'ero yi n'se, oni oniwako to wa n'be. Beena Olorun ni oniwako na, adhyaksa. Oun ni Eledumare labe eni ti gbogbo nkan tin sise. Nisin awon jiva wanyi, tabi awon eda towa laaye, Olorun ti gba won ninu Bhagavad-gita, base ma ri ninu awon apa iwe to kan, pe nkankana lon je pel'Olorun. Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ ([[Vanisource:BG 15.7|BG 15.7]]). Apa ati nkankana nitumo Aṁśa. Nisin gege bi iwonba wura die seje wura na, omi iwonba die lat'okun si ni iyo bi omi okun na, beena, awa, awon eda, nkankana laje pel'olori to gaju, īśvara, Bhagavān, tabi Oluwa Śrī Kṛṣṇa, Awa sini, awon iwa Olorun sugbon ni iwonba die. nitoripe isvara kekere niwa, awon isvara kekere. Awa na si fe ni idari lori awon nkan. Awa na fe ni idari lori iseda aye yi. Nisin eyin fe ni idari lori ofurufu. Eyin fe jeki awon isogbe te daa le fo lori ofurufu. Beena iwa lati daa nkan sile tabi lati ni idari lori nkan si wa nitoripe awa na sini awon iwa lati ni idari lori nkan na. Sugbon oye ka mo wipe iwa yi nikan kole to. Awa si ni iwa lati ni idari lori iseda aye yi, lati ni idari lori ile aye yi, sugbon oludari to gaju ko niwa. Beena wanti salaaye ninu Bhagavad-gita.  
A n'ifẹ lati jẹ oluwa lori awọn ohun elo ti isẹda aye Sugbon asise wa niyen. Nigba ti a ba ri awọn ohun iyanu ti nṣẹlẹ ni agba isẹda, o yẹ ki a mọ pe oludari kan wa lẹhin agba isẹda yi. Ko si ohun ti o wa ni ode aye lai ni idari. Lati ro wipe kosi oludari jẹ ọrọ ọmọde. Fun apẹẹrẹ, ki ọkọ mọto ma sare ṣiṣẹ, pelu ina-akanṣe mọto ti o dara, ti o si nsaare loju titi. ọmọde le ro pe o jẹ ohun iyanu "bawo ni oko yi se nsare, laisi ẹṣin tabi ẹranko miiran to nfa? sugbọn eniyan ti o loye tabi agbalagba, O fi gbakan mọ wipé koda lẹhin gbogbo ina-akanse mọto, laisi awakọ, ẹrọ na o le rin. Ero towa ninu oko, tabi ninu ile-ina monamona.. Nisin ni asiko tawayi, asiko awon ẹrọ lawa, sugbon oye ko ye wa pe lehin gbogbo awọn erọ wọnyi, leyin isẹ nla t'erọ yi n'se, awakọ ni o wa n'bẹ. Bakan naa Ọlọrun Ọba ni awakọ, adhyaksa. Oun ni Eledumare ti ohun gbogbo nsisẹ labẹ itọsọna Rẹ. Ni bayi, Oluwa ti gba awọn jīvas tabi awọn ẹda alãye ninu Bhagavad-gītā, bi a o ṣe kiyesi ninu awọn ori iwe ti wọn nbọ lẹhin, bi awọn ẹya ara Rẹ, Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ ([[Vanisource:BG 15.7 (1972)|BG 15.7]]). Apa ati nkankana nitumo Aṁśa. Nisin gege bi ẹrun wura, wura na lo jẹ, omi iwonba die lat'okun si ni iyo bi omi okun na, bakanna si ni awa ẹda alãye, bi a se jẹ ẹya ara ti oludari to ga julọ, īśvara, Bhagavān, tabi Oluwa Śrī Kṛṣṇa, Awa ti ni, mo lero lati wi, gbogbo awọn agbara ti Ọlọrun Ọba niwọn kinkini nitori ti a jẹ īśvaras kinkini, īśvaras ti wọn nse itẹriba Awa na si fe ni idari lori awon nkan. A ngbiyanju lati dari isẹda, gẹgẹ bi a se ngbiyanju ni iwoyi lati sakoso lori ofurufu tabi awọn aye ọrun. Eyin fe jeki awon isogbe te daa le fo lori ofurufu. bẹ si ni ifẹ lati sakoso si wa nibẹ nitori b se wa ninu Ọlọrun o wa ninu awa na niwonba. Sugbon o yẹ ki a mọ peko jamọ nkankan. Awa si ni iwa lati ni idari lori iseda aye yi, lati ni idari lori ile aye yi, awa ki ise oludari to ga julọ Be ni o ti ni alaaye ninu Bhagavad-gita.  


Lehin na kini ile aye yi? Wanti salaaye nipa re na. Iseda aye yi, wanti salaaye re ninu Bhagavad-gita pe agbara to kere loje, prakrti to kere. Prakrti to kere, ati awon eda si je prakrti to gaju. Oun ton ni idari lori re nitumo Prakrti, Itumo gidi fun prakrti ni obirin tabi abo. Gege bi oko se ni idari lori ise iyawo re, beena, prakrti wa labe idari yi. Olorun, Eledumare, loni idari yi, prakrti yi, awon eda aye yi ati iseda na, prakrti orisirisi lonje, tabi ton wa labe idari Olorun. Beena gege bi Bhagavad-gita se so,, awon eda aye yi, botilejepe nkankana lonje pelu Olorun, prakrti na niwon. Wanti salaaye ninu apa meje ti Bhagavad-gita, apareyam itas tu viddhi aparā ([[Vanisource:BG 7.5|BG 7.5]]). aparā iyam ni ile aye yi je. Itas tu,prakrti imi si wa na. kini prakrti? Jiva-bhuta,...  
Kini isẹda aye? Eleyi na ti ni alaye. Isẹda aye, na ti ni alaye ninu iwe mimọ Gita bi prakriti ti o rẹlẹ-ju, prakrti ti o rẹlẹ-ju, wọn ti salaye ẹda alààyè bi prakriti to ga ju Prakriti wa labẹ iṣakoso nigbagbogbo, ti o wa labẹ... Itumo gidi fun prakrti ni obirin tabi abo. Gege bi oko se ni idari lori ise iyawo re, beena, prakrti wa labe idari yi. Olorun, Eledumare, loni idari yi, prakrti yi, awon eda aye yi ati iseda na, awọn ẹda alãye ati isẹda ni wọn wa ni itẹriba labẹ, Ọlọrun Ọba Ni ibamu pẹlu iwe mimọ Gita, biotilẹjẹpe awọn ẹda alãye, jẹ ẹya ara Ọlọrun Ọba, wọn kà wọn kun si prakriti. Eleyi ti wa ni mẹnuba ni kedere ninu ori iwe Keje ti Bhagavad Gita. apareyam itas tu viddhi aparā ([[Vanisource:BG 7.5 (1972)|BG 7.5]]). apara iyam ni ile aye yi je. Itas tu, prakriti miran tun kọja eyi. kini prakrti? Jiva-bhuta, ..  


Beena prakrti yi, prakrti yi ni amuye meta: ipo rere, ipo ifekeufe, ati ipo aimokan. lori gbogbo awon ipo wanyi, ipo meta orisirisi lowa, rere, ifekufe ati aimokan, asiko tayeraye. Asiko tayeraye. ipaarapo awon ipo iseda wanyi labe idari asiko tayeraye, awon ise wa. Ise, tonpe ni karma. Awon ise tonse lati aimoye asiko awa sin jiya fun tabi awa sin gbadun awon ibajade ise wanyi.  
Iwa mẹta ni Isẹda aye fara rẹ jọ: ipo rere, ipo ifẹ ati ipo aimọkan. Eyi ti o leri awọn wọnyi, lori gbogbo awọn ipo wọnyi, ipo rere, ifẹ ati aimọkan, ni akoko ayeraye. Akoko tayeraye. ati nipa apapọ awọn ipo isẹda wọnyi ati labẹ iṣakoso ati idari akoko ayeraye, awọn akitiyan si wa Awọn akitiyan wa, ti a npe ni karma. Awọn akitiyan wọnyi ti nlọ lati igba lailai, a si ti njiya tabi ngbádùn awọn eso ti akitiyan wa na.
<!-- END TRANSLATED TEXT -->
<!-- END TRANSLATED TEXT -->

Latest revision as of 00:29, 14 June 2018



660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

A n'ifẹ lati jẹ oluwa lori awọn ohun elo ti isẹda aye Sugbon asise wa niyen. Nigba ti a ba ri awọn ohun iyanu ti nṣẹlẹ ni agba isẹda, o yẹ ki a mọ pe oludari kan wa lẹhin agba isẹda yi. Ko si ohun ti o wa ni ode aye lai ni idari. Lati ro wipe kosi oludari jẹ ọrọ ọmọde. Fun apẹẹrẹ, ki ọkọ mọto ma sare ṣiṣẹ, pelu ina-akanṣe mọto ti o dara, ti o si nsaare loju titi. ọmọde le ro pe o jẹ ohun iyanu "bawo ni oko yi se nsare, laisi ẹṣin tabi ẹranko miiran to nfa? sugbọn eniyan ti o loye tabi agbalagba, O fi gbakan mọ wipé koda lẹhin gbogbo ina-akanse mọto, laisi awakọ, ẹrọ na o le rin. Ero towa ninu oko, tabi ninu ile-ina monamona.. Nisin ni asiko tawayi, asiko awon ẹrọ lawa, sugbon oye ko ye wa pe lehin gbogbo awọn erọ wọnyi, leyin isẹ nla t'erọ yi n'se, awakọ ni o wa n'bẹ. Bakan naa Ọlọrun Ọba ni awakọ, adhyaksa. Oun ni Eledumare ti ohun gbogbo nsisẹ labẹ itọsọna Rẹ. Ni bayi, Oluwa ti gba awọn jīvas tabi awọn ẹda alãye ninu Bhagavad-gītā, bi a o ṣe kiyesi ninu awọn ori iwe ti wọn nbọ lẹhin, bi awọn ẹya ara Rẹ, Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). Apa ati nkankana nitumo Aṁśa. Nisin gege bi ẹrun wura, wura na lo jẹ, omi iwonba die lat'okun si ni iyo bi omi okun na, bakanna si ni awa ẹda alãye, bi a se jẹ ẹya ara ti oludari to ga julọ, īśvara, Bhagavān, tabi Oluwa Śrī Kṛṣṇa, Awa ti ni, mo lero lati wi, gbogbo awọn agbara ti Ọlọrun Ọba niwọn kinkini nitori ti a jẹ īśvaras kinkini, īśvaras ti wọn nse itẹriba Awa na si fe ni idari lori awon nkan. A ngbiyanju lati dari isẹda, gẹgẹ bi a se ngbiyanju ni iwoyi lati sakoso lori ofurufu tabi awọn aye ọrun. Eyin fe jeki awon isogbe te daa le fo lori ofurufu. bẹ si ni ifẹ lati sakoso si wa nibẹ nitori b se wa ninu Ọlọrun o wa ninu awa na niwonba. Sugbon o yẹ ki a mọ peko jamọ nkankan. Awa si ni iwa lati ni idari lori iseda aye yi, lati ni idari lori ile aye yi, awa ki ise oludari to ga julọ Be ni o ti ni alaaye ninu Bhagavad-gita.

Kini isẹda aye? Eleyi na ti ni alaye. Isẹda aye, na ti ni alaye ninu iwe mimọ Gita bi prakriti ti o rẹlẹ-ju, prakrti ti o rẹlẹ-ju, wọn ti salaye ẹda alààyè bi prakriti to ga ju Prakriti wa labẹ iṣakoso nigbagbogbo, ti o wa labẹ... Itumo gidi fun prakrti ni obirin tabi abo. Gege bi oko se ni idari lori ise iyawo re, beena, prakrti wa labe idari yi. Olorun, Eledumare, loni idari yi, prakrti yi, awon eda aye yi ati iseda na, awọn ẹda alãye ati isẹda ni wọn wa ni itẹriba labẹ, Ọlọrun Ọba Ni ibamu pẹlu iwe mimọ Gita, biotilẹjẹpe awọn ẹda alãye, jẹ ẹya ara Ọlọrun Ọba, wọn kà wọn kun si prakriti. Eleyi ti wa ni mẹnuba ni kedere ninu ori iwe Keje ti Bhagavad Gita. apareyam itas tu viddhi aparā (BG 7.5). apara iyam ni ile aye yi je. Itas tu, prakriti miran tun kọja eyi. kini prakrti? Jiva-bhuta, ..

Iwa mẹta ni Isẹda aye fara rẹ jọ: ipo rere, ipo ifẹ ati ipo aimọkan. Eyi ti o leri awọn wọnyi, lori gbogbo awọn ipo wọnyi, ipo rere, ifẹ ati aimọkan, ni akoko ayeraye. Akoko tayeraye. ati nipa apapọ awọn ipo isẹda wọnyi ati labẹ iṣakoso ati idari akoko ayeraye, awọn akitiyan si wa Awọn akitiyan wa, ti a npe ni karma. Awọn akitiyan wọnyi ti nlọ lati igba lailai, a si ti njiya tabi ngbádùn awọn eso ti akitiyan wa na.