YO/Prabhupada 1071 - T'aba ni asepo pelu Oluwa, ta ba sise fun, lehin na inu wa ma dun

Revision as of 11:32, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 1071 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

A le ranti pe taba soro nipa "Krsna" kon se nkan esin. Igbadun to gaju nitumo Oruko Krsna. Wanti jeerisi pe Oluwa ni orisun gbogbo igbadun aye yi. Gbogbo wa lan sa tele igbadun yi. Ānandamayo 'bhyāsāt (Vedānta-sūtra 1.1.12). Awon eda tab'Oluwa, nitoripe imoye wa po gan, niorina lasen sa tele idunnu. Idunnu. Nigbogbo'gba ni'nu Oluwa dun, taba si ni asepo pel'Oluwa, ta ni asepo pelu re, ta ni asepo pelu Re, lehin na inu wa le dun. Oluwa ti sokale wa sinu ile aye yi lati fi awon akoko idaraya re fi han to kun pelu idunnu. Nigbati Oluwa Sri Krsna wa ni Vrndavana, awon ise re pelu awon oluso maalu omo-okunrin, pelu awon omo-obirin, pelu awon ore re, awon ore obirin, pelu awon olugbe Vrndavana ati ise oluso maalu tonse nigbato kere, gbogbo awon akoko idaraya t'Oluwa Krsna yi kun fun idunnu. Gbogbo Vrndavana, gbogbo awon olugbe Vrndavana, won sa tele. Koseni kankan ninu won to mo afi Krsna. baba Krsna gan o mo, Nigbati Nanda Maharaja fe s'ebo si Indra, nitoripe o si fe salaaye fun awon eyan pe won o gbodo s'adura s'orisa kankan af'Oluwa. Nitoripe ipinnu aye yi ni lati pada s'odo metalokan. Wanti juwe nipa odo metalokan ti Krsna ninu Bhagavad-gita, apa 15, ese-iwe 6,

na tad bhāsayate sūryo
na śaśāṅko na pāvakaḥ
yad gatvā na nivartante
tad dhāma paramaṁ mama
(BG 15.6).

Nisin alaaye nipa sanmo yi to wa tayeraye.. T'aba n'soro nipa sanmo, nitoripe awa ti baramu pelu sanmo lasan, nitorina a ma bere sini ronu nipa orun, osupa, erawo, at bayi lo. Sugbon Oluwa sowipe ni sanmo tayeraye yi, orun o wulo. Na tad bhāsayate sūryo na śaśāṅko na pāvakaḥ (BG 15.6). Kode si'wulo fun osupa. Itumo Na pāvakaḥ niwipe kosi'wulo fun ina monamkna tani ina lati tanna nitoripe sanmo mimo yi, tin tanna fun ara re lati brahma-jyotir. Brahmajyoti, yasya prabhā (BS 5.40), ina lati odo metalokan. Nison lasiko tawayi, ti awon eyan fe losi awon isogbe imi, Kole lati ni oye nipa odo metalokan t'Oluwa. Odo metalokan t'Ouwa wa ninu sanmo mimo, Goloka l'oruko re je. Ninu Brahma-samhita wanti salaaye dada, goloka eva nivasaty akhilātma-bhūtaḥ (BS 5.37). Botilejepe Oluwa wa ni odo metalokan re, Goloka, beena akhilātma-bhūtaḥ loje, e le ni asepo pelu re lati bi na. nitorina ni Oluwa sen wa lati fi ara re han, sac-cid-ānanda-vigraha (BS 5.1), bayi koni sejo pe awa fe f'oju inu wo. Kosejo irori.