YO/Prabhupada 1076 - lasiko iku ale wa nibi, tabi ka pada si odo metalokan

Revision as of 14:32, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

bhāva orisirisi lowa. Nisin, ikan ninu awon bhava ni iseda aye yi, ati salaaye tele, pe ifihan ikan ninu awon agbara Eledumare ni ile aye yi je. Ninu Visnu Purana, won ti juwe gbogob agbara Eledumare nibe.

viṣṇu-śaktiḥ parā proktā
kṣetra-jñākhyā tathā par
avidyā-karma-saṁjñānyā
tṛtīyā śaktir iṣyate
(CC Madhya 6.154)

Gbogbo awon agbara, Parāsya śaktir vividhaiva śrūyate (CC Madhya 13.65, purport). Orisirisi agbara l'Oluwa ni, aimoye agbara tio le ye wa. Sugbon awon alakowe, awon eda miko won ti sewaadi won de ti salaaye gbogbo agbara wanyi pin s'ona meta. Ikini.. gbogbo awon agbara wanyi viṣṇu-śakti ni won. Lati agbara orisirisi ti Visnu ni awon agbara wanyi. Nisin, para ni agbara yi, to gaju. Ati kṣetra-jñākhyā tathā parā, ati awon eda, kṣetra-jña, awon na wa ninu apa agabra giga yi, wanti jeerisi ninu Bhagavad-gita na. Ati salaaye tele. Awon agabra iyoku, agbara ile aye yi, ṛtīyā karma-saṁjñānyā (CC Madhya 6.154). Agbara to ku wa ninu ipo aimokan. Beena agbara ile aye yi niyen. Beena bhagavd ni agbara ile aye yi na - ( ko daju). Beena lasiko iku, boya ka wa pelu agbara ile aye yi, tabi ile aye yi, tabi ka pada si odo metalokan. awon oan to wa niyen. Beena Bhagavad-gita sowipe,

yaṁ yaṁ vāpi smaran bhāvaṁ
tyajaty ante kalevaram
taṁ tam evaiti kaunteya
sadā tad-bhāva-bhāvitaḥ
(BG 8.6)

Nisin, bose ti mowa lara latii ronu, nipa agbara aye yi tabi agbara mimo, nisin, bawo lasele lo ironu yi? Ironu ile aye yi, basele le yi pada sii ironu nipa agbara mimo? Beena fun ironu nipa agabra mimo awon iwe mimo Veda wa nibe. Beena lati ronu nipa awon agbara ile aye yi, awon iwe aye yi po gan - iwe iroyin, iwe itan, ati bayi bayi lo. O kun fun iwe. Beena ironu wa, ti wole sinu awon iwe wanyi. Beena, taba fe yi ironu wa s'ona mimo, lehin na agbodo bere sini ka awon iwe mimo Veda. Nitorina awon alakowe ti ko awon iwe mimo Veda to po gan, awon Purana. Itan lasan ko ni awon Purana. Awon itan akoole niyen. Ninu Caitanya-caritamrta oni awon ese iwe ton salaaye bayi. Anādi-bahirmukha jīva kṛṣṇa bhuli' gela ataeva kṛṣṇa veda-purāṇa kailā (CC Madhya 20.117). Pe awon edfa aye yi, won ti gbagbe nipa asepo ton ni pely Eledumare, won ronu nipa awon ise ile aye yi. lati yi agbara ironu awon eyan wanyi si awon nkan mimo, Kṛṣṇa-dvaipāyana Vyāsa, ti ko awon iwe mimo to po gan. Itumo iwe mimo Veda niwipe, ni alakoko o pin awon iwe yi si merin. Lehin na o salaaye lori won pelu awon Purana. Fun awon eyan tio le ye bi awon strī, śūdra, vaiśya, o ko iwe Mahābhārata. Ninu Mahabharata o si juwe nipa Bhagavad-gita. Lehin na otun fun wa ni sonisoki nipa iwe Veda ninu Vedanta-sutra. Ati Vedantr-sutra lati le funwa ni itonisona loo jowaju, o de funwa ni Srimad-Bhagavatam to salaaye fun ara re.