YO/Prabhupada 1078 - Ton ronu t'okan t'ara wakati merin le-logun nipa Oluwa

Revision as of 14:53, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Nigbat'eyin ba ni ife to le gan fun Eledumare, lehin o daju pe ale sise wa kasii ronu nipa re. Beena agbodo ji iye ara wa soke. Gege bi Arjuna sen ronu nipa Oluwa nigbogbo'gba. Kode gbagbe Krsna fun iseju kan. Alabasepo Krsna nigbogbo'gba. Lesekana, jagunjagun. Oluwa Krsna o so fun Arjuna pe ko ma jagun mo, pe ko losinu aginju, lori Himalaya ko lo sasaro. Nigbato sofun Arjuna kose yoga, Arjuna o gba, pe "Ilana yi ti le ju fun mi." Lehin na Oluwa sowipe, yoginām api sarveṣāṁ mad-gatenāntarātmanā (BG 6.47). Mad-gatenāntarātmanā śraddhāvān bhajate yo māṁ sa me yuktatamo mataḥ. Beena enikeni toba ronu nipa Eledumare, ouin ni yogi to gaju, oun ni jnani to gaju, oun de ni olufokansi to gaju lese kanna. Olorun ti funwa ni itosona pe tasmāt sarveṣu kāleṣu mām anusmara yudhya ca (BG 8.7). " ksatriya loje kosi bosele fi ogun jija si;e. Ogbodo jagun. Beena lasiko kanna o gbodo ranti Mi nigbogbogba, lehin na o le sese." anta-kāle ca mām eva smaran (BG 8.5), "lehin t'asiko iku ba de wasii le ranti Mi." Mayy arpita-mano-buddhir mām evaiṣyasy asaṁśayaḥ. Leekan si otun sowipe kosi isiyemeji kankan. Teyan ba farafun si ise Oluwa, ninu ise ife s'Oluwa, mayy arpita-mano-buddhir (BG 8.7). Nitoripe awa o kin sise pelu ara wa nikan. Awa n'sise pel'okan wa at'ogbon. Beena ti ogbon at'okan wa ba wa ninu ironu Oluwa, leyin na iye ara wa ma ni nkan se ninu ise Oluwa. Asiri Bhagavad-gita niyen. Eyan gbodo k'ogbon yi, beyan sele fokan le nkan dada, pel'okan at'ogbon, wakati merinle logun lori ironu Oluwa. Eleyi ma ranwalowo lati pada s'odo metalokan tabi si adugbo mimo leyin igba toba f'ara eda yi sile. Awon onisayensi won sowipe o ti pe ton ti gbiyanju lori eto na, lati de isogbe osupa,sugbon titi dision won o ti dee be/ Sugbon ninu Bhagavad-gita, won ti daba fun wa. kasowipe awson okurin le wa laaye fun odun aadota si... Koseni to fe ni ilosiwaju ninu eto imoye mimo fun odun aadota. Apeere to da leleyi. sugbon teyan ba gbiyanju lati s'ise yi fun odun mewa tabi marun, mayy arpita-mano-buddhir (BG 8.7)... Oro eto adase leleyi. Eto adaase yi le bosi pelu ise ifarasi Oluwa, śravaṇaṁ. Śravaṇaṁ. Ilana to rorun ju lati gboran.

śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ
smaraṇaṁ pāda-sevanam
arcanaṁ vandanaṁ dāsyaṁ
sakhyam ātma-nivedanam
(SB 7.5.23)

Awon ilana mesan wanyi lowa. Igboran lo rorun ju ninu gbogbo won.