YO/Prabhupada 1079 - Iwe mimo ti gbogbo awon eyan gbodo ka dada ni Bhagavdad-gita je

Revision as of 15:14, 27 March 2015 by YamunaVani (talk | contribs) (Created page with "<!-- BEGIN CATEGORY LIST --> Category:1080 Yoruba Pages with Videos Category:Prabhupada 0001 - in all Languages Category:YO-Quotes - 1966 Category:YO-Quotes - Le...")
(diff) ← Older revision | Latest revision (diff) | Newer revision → (diff)


Invalid source, must be from amazon or causelessmery.com

660219-20 - Lecture BG Introduction - New York

Teyan ba gbo awon oro Bhagavad-gita tabi Srimad- Bhagavatam lati awon eda ton wa ni pipe, eleyi ma jek'eni na bere sini ronu nia Eledumara fun wakati merin le logun, eleyi asi ranlowo lati de ipo to gaju, anta-kale, lati ranti Eledumare, toba de ti f'ara eda yi sile, asi ni ara eda mimo, ara eda mimo, tole fi ni asepo pel'Oluwa. Nitorina Oluwa sowipe,

abhyāsa-yoga-yuktena
cetasā nānya-gāminā
paramaṁ puruṣaṁ divyaṁ
yāti pārthānucintayan
(BG 8.8)

Anucintayan, ton ronu nipa ara re nikan. Ilana to rorun leleyi. Eyan gbodo k'ogon yi lati awon eyan tonti ni iriri lori eto yi. Tad vijñānārthaṁ sa gurum evābhigacchet (MU 1.2.12). Eyan gbodo summo awon eyan tonti se ise adase yi. Beena abhyāsa-yoga-yuktena. Nkan ton pe ni abhyāsa-yoga, ise adase. Abhyāsa..... basele ranti Oluwa nigbogbo'gba. Cetasā nānya-gāminā. Okan, Okan wa kole duro sibikan. Beena eyan gbodo gbokan le irisi Oluwa Sri Krnsa nigbogbo'gba, tabi ninu ohun, ninu oruko re tosi rorun gan. Dipo ta ma gbokan le - okan mi o le duro sibikan, o sa kaakiri, sugbon mole f'eti si ohun Krsna, iyen na ma ranmilowo. Nkan ton pe ni abhyasa-yoga niyen. Cetasā nānya-gāminā paramaṁ puruṣaṁ divyaṁ. Paramaṁ puruṣa, Eledumare ninu odo metalokan, ninu sanmo mimo, eyan le summo, anucintayan, ton ronu nigbogbo'gba Beena awon ilana wanyi, wanti juwe won ninu Bhagavad-gita, Kode s'ihamo fun enikan kan. Konsepe awon ipo okunrin kan lole wa ninu imoye yi. Ironu ati igboran nipa Krsna, nkan ti gbogbo eyan le se niyen. Oluwa sowipe ninu Bhagavad-gita,

māṁ hi pārtha vyapāśritya
ye 'pi syuḥ pāpa-yonayaḥ
striyo vaiśyās tathā śūdrās
te 'pi yānti parāṁ gatim
(BG 9.32)
kiṁ punar brāhmaṇāḥ puṇyā
bhaktā rājarṣayas tathā
anityam asukhaṁ lokam
imaṁ prāpya bhajasva mām
(BG 9.33)

Oluwa sowipe awon eranko gan ton resile gan ninu ipo aye to kere ju, tabi obirin to niwa ti da, tabi onisowo, tabi alabasise.. Awon onisowo, alabasise, at'obirin, won wa lori ipo kanna nitoripe ogbon won o fibe po titi. Sugbon Oluwa sowipe, awon gan at'awon eyan to kere juwon lo, māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ (BG 9.32), awon nikan ko tabi awon eyan ton kere ju won lo, tabi enikeni. kosejo lori eni toje, boya obirin tab'okurin, enikeni le gba awon ofin bhakti-yoga ko gba Oluwa bi ipinnu aye re, afojusun to gaju ile aye wa.... Māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ, te 'pi yānti parāṁ gatim. param gatim ninu odo metalokan ati sanmo mimo ti gbogbo wa le summo. Eyan gbodo gbiyanju lati ko nipa eto na. Bhagavad-gita ti salaaye dada eyan le gba ilana yi lati je ki ile aye re ni ilosiwaju to da, beena o le ni ona abayo to daju fun aye re. Koko oro ninu gbogbo Bhagavad-gita niyen. Nitorina, ipari oro niwipe, iwe mimo ni Bhagavad-gita gbogbo awon eyan gbodo ka dada. Gītā-śāstram idaṁ puṇyaṁ yaḥ paṭhet prayataḥ pumān. toba tele awon ilana towa ninu iwe na dada, ibajade towa niwipe, lehin na o le bolowo gbogbo awon isoro aye yi. Bhaya-śokādi-varjitaḥ. Awon ijaya aye yi, gege bi t'aye to kan.

gītādhyāyana-śīlasya
prāṇāyama-parasya ca
naiva santi hi pāpāni
pūrva-janma-kṛtāni ca

Beena anfani imi to wa niwipe, teyan ba ka Bhagavad-gita, dada pelu okan to mo, lehin na pelu ore ofe Oluwa, beena koni jiya awon ese toti se seyin.