YO/Prabhupada 0006 - Olorun ni gbogbo wa -Orun rere awon Ode



Lecture on SB 1.15.49 -- Los Angeles, December 26, 1973

Oni kalu ku nbgeraga, wi pe " Emi mo. Emi mo gbogbo nkan. Nitorina ko s'iwulo lati lo si odo oluko igbala, guru" Bayi ni ona ati wa si odo olugbala, ojise Oluwa: Jowo emi re, wi pe "Mo mo opolopo nkan asan ti ko wu lo. Nisin yi ni pa anu re ko mi" Eyi ni a npe ni iforibale. Gege bi Ajuna ti so, śiṣyas te 'haṁ śādhi māṁ prapannam (BG 2.7). Ni gba ti Arjuna ati Krishna jo nsoro po, ati ni igbati ko si adehun, Arjuna wa fi oribale fun Krishna "Oluwa mi owon, nisin yii a jo nsoro gege bi ore. . Oro laarin ore ko si mo. Mo gba yin gegebi oluko igbala mi "Ni pa ti anu yin, e ko mi ni nkan ti onse ojuse mi" Eyi ni iwe mimo Bhagavad-Gita.

Nitorina a gbodo ko eko. Tad-vijñānārthaṁ sa gurum eva abhigacchet [MU 1.2.12]. Eyi ni ilana Vediki, pe ki ni aye yi wa fun? Bawo lo se nse yi pa da? Bawo ni a se rin irin ajo lati iku pa da si ayee lati ara kan si omiran? Tani emi nse? Se eran ara yi ni mi, tabi o ju bee, nkan kan miran? A gbodo se iwadi awon nkan won yi. Eyi ni ile aye omo eniyan. Athāto brahma jijñāsā. A gbodo se iwadi won yi. Nitorina ni igba aye ta npe ni Kali-yuga yi, lai se iwadi, lai ni oluko igbala, guru, lai ni iwe, oni kaluku ni Olorun. O pari. Bi nkan se nlo niyi, paradise awon omugo. Ntorina ele yi ko le ran wa lowo. Ni bayi, ni pa ti Vidura... Oun naa...

viduro 'pi parityajya
prabhāse deham ātmanaḥ
kṛṣṇāveśena tac-cittaḥ
pitṛbhiḥ sva-kṣayaṁ yayau
(SB 1.15.49)

Oun... Mo nsoro ni pa Vidura Vidura je angeli to ni akoso loori iku, Yamaraja. O wa sele wi pe won gbe eni mimo kan wa fun idajo niwaju Yamaraja. Ni igbati eni mimo yi wa se iwadi lowo Yamaraja, wipe "Emi... Emi ko le ranti pe mo da ese kan kan ni igbesi aye mi. Kilode ti won fi mu mi wa fun idajo ni bi yi? Ni igba naa ni Yamaraja so wi pe " Iwo ko le ranti. Ni igbati o wa lomode, iwo fi abere bo idi kokoro ti o si ku. Nitorina a gbodo da e lejo. Eri nkan bayi. Ni igba to wa lomode, ninu aimokan, o da ese, nitori eyi o gbodo gba ibawi. Bee na ni a si nfi oju koroju, ni ilodi si ilana esin, "Eyin ko gbodo pa nkan to lemi" a ti si egbe egberun ile-iperan, ti a si nje eri ti ko ni lari wi pe eranko ko ni emi E wo iwada. Eyi si nlo gege bi eto. A si fe in ibale okan.