YO/Prabhupada 0015 - Emi ki nse eran ara yi



Lecture on BG 9.34 -- New York, December 26, 1966

Awon ami mefa lo wa, ti o fi han wa pe emi mbe Idagba so ke je ikan ti o wa pataki Beeni idagbasoke. Gere ti emi ba ti jade ninu ara yi, idagbasoke pari. Si omo ba s'alaisi ko to waye, ah, ko le si idagbasoke. Ah ha, awon obi re won a ni ko wu lo. E lo so nu. Bakanna, Oluwa Olorun Krishna fi afimo akoko han Arjuna pe, E ma ro wi pe imole emi ti o wa ninu ara, ni pa ti wiwa nbe re, ara yi ndagba lati omode si odomokunrin, odomokunrin si agba, lati agba di arugbo. Nitorina, ni igbati ara yi ko ba wulo moo, lai fokan si, emi se kele kele fi ara yi si le Vāsāṁsi jīrṇāni yathā vihāya (BG 2.22). Gege bi a se nfi aso to ti gbo si le ti a si ngbe tuntun wo, bakanna, ni ase ngba ara miran a si gba ara miran yi lai se wipe ni pa isayan mi.

Isayan na duro le ofin iseda-ye Isayan na duro le ofin iseda-ye. E ko le so ni igba ti e ba nfi aye sile, sugbon e lee roo ninu E le so wi pe, nkan ti mo fe wi ni pe, onikaluku, ati pe isayan yi wa nbe. Yaṁ yaṁ vāpi smaran loke tyajaty ante kalevaram (BG 8.6). Bi, ni igba ti o ba nfi aye sile, ironu okan re, bi ero okan re ba se go ke si, iwo o ni atunbi gege bi ara naa Bee na, ologbon eniyan , ti ko nse were, gbodo ni oye wipe emi ki nse eran ara yi. La koko. Emi ki nse eran ara yii. L'eyin na a tun ni oye pe kini ise re? Ah, gege bi emi, kini ise re?

Ise re ni, Bhagavad-Gita ti mee nu kan eyi ninu ese ikeyin ti Ori kesan, won pe ise yi ni man-manā bhava. E nronu nkan kan. Eni ko kan wa, gbogbo emi ti of ara wo bi ewu, a nronu nkan kan. Laini ero okan, fun gbolohun kan, iwo ko le duro. Iyen ko see se. Bee na ni eyi se je ise.. E ro ni pa Olorun. E ro ni pa Olorun. O di dan pe a gbodo ronu si nkan kan. Ewo wa ni idamu ti e ba ronu nipa Olorun? Olorun ni ôpôlôpô isé, ôpôlôpô iwe ati awon nkan miran pupô. Oluwa so ka le wa. A ni awon iwe orisirisi. Bi è ba fè ronu ni pa Olorun, a le se ojutoo ôpôlôpô awon iwe fun yin ti è ko le kaa la ka tan, bi è ba ti lè nka won fun wakati merin-le-logun. Bee na fifi Olorun se ronu, eyi ti to. Fi Olorun se ronu. Man-manā bhava. Ah, mo le ronu re.

Gègè bii èni ti o nse isè fun ôga kan. Bèèni, a ma ronu ôga rè ni gbogbo igba. Ah, mo ni adéhun ni agogo mèsan, ti mi o ba tété dé ôga o si bi nu. Oun ronu ni pa nkan kan. Iru ironu bayi ko wulo. Nitori éyi Oluwa ni, bhava mad-bhaktaḥ. "Saa fi mi si inu ero okan rè pèlu ifè" Ni igbati ôga naa, ni igbati, mo fe wipe ni igbati ômô ôdô ba nronu ôga, kosi ifè nbè. Oun ronu si tôrô-kôbô. "Nitori ti mi o ba de ile isè ni agogo mèsan, ah, a je ifa-seyin, ma si se ofo dollar meji" Nitorina onro nu nipa, kii sé ni pa ti ôga, Oun ronu ti tôrô-kôbô Iru ironu yèn ko le gba o la. Nitorina Oluwa so wipe, bhava mad-bhaktaḥ. "Saa di omo olulosin Mi. Ni igba na ero okan re si mi a dara." Ati kini nkan ti a npe ni bhakti yi? Mad-bhaktaḥ. Ifarajin... Ifarajin tumô si isè Oluwa. Mad-yājī. Se isè kô kan fun Oluwa. Gègè bi a se nsé nibi ni gbo gbo igba. Igba ki gba ti è ba wa, è o ri wa ti a nse isè lôwô. Bee na ni a ti da awon isè silè. Lati fi Olorun sinu ero okan.