YO/Prabhupada 0018 - Igbagbo to duro sin sin loju ese guru



Lecture on SB 6.1.26-27 -- Philadelphia, July 12, 1975

Prabhupāda: Nitorina a gbôdô lo akoko yi lati se iyanju ile ayè ti a nwa ni ayi pada ti a si ngba ara miran wô. Bee ni bawo ni o sè ma yè won, afi ti won ba yà si ôdô ooluko-igbala ododo, guru. Nitori eyi, śāstra, iwè mimô sô wipè tad-vijñānārtham: " Ti o ba fé mô ohun ti o nsè isoro ayè ré gan gan ati ti o ba si fe di eni ti oni oye ni pa bi a se ndi olufokansin Oluwa, bi a se le di eni aiku, pada si ile, si odo Baba Nla wa, nitori eyi o gbodo sunmo guru,." Ati tani Guru nse? won ti se alaaye re, ni gbolohun kekere. Guru ki se eni to nda iye ti e sile wi pe " E se eleyi ki e si fun mi lowo, ki inu yin ba le dun. Iyen ki ise Guru. Ona miran ni yen lati wa owo. Nitorina won so nibi wipe, mūḍha, enikeni ti o nba gbe ile aye orun omugo, ti onda iye ara re sile bi Ajamila .... Enikan nro pe, " Isoju mi re", elomiran na nrope...Omugo ni oun se. E gbodo mo nkan ti o nse oju ise yin lati odo guru. E nkorin lojojumo,; guru-mukha-padma-vākya, cittete koriyā aikya, ār nā koriho mane āśā. Ile aye ni yi. Ile aye ni yi. Guru-mukha-pad... E gba guru ti o joo ju, ati pe e gbodo se ase re . Nigba na ni aye yin o si se aseyori. Ār nā koriho mane āśā. Iwo alaimokan, iwo ko ni ire kan kan miran. Se o ki nkorin lojojumo? Sugbon nje eyin ni oye itumo orin na? Tabi e kan nkorin lasan ni? Kini itumo re? Tani o ma se alaaye fun yin? Ko seni to mo? Beeni, Kini itumo re?

Omo eleyin ijo: "Ire mi nikan ni wi pe okan mi di mimo ni pa oro ti o njade lati enu oluko igbala mi. Emi ko ni ire miran ju eyi lo'

Prabhupāda: Bee ni. Ase na ni yi. Guru-mukha-padma-vākya, cittete koriyā aikya. Nisinyi citta tumo si isokan tabi okan. "Eleyi nikan ni emi o se, o pari. Guru Mahārāja mi so fun mi wipe; Mo ma se eleyi." Cittete koriyā aikya, ār nā koriho mane āśā. Nitorina ki se fun igberaga mi, amo mo le so wipe, fun eko yin, mo se gege bi o se wi. Nitori na, iwon-ba iseyori kekere ti e ba ri ti o ju ti awon arakunrin mi ninu oluwa, se ni ipa ese yi ni. Emi ko ni agabara kan kan, sugbon mo gba, oro guru mi, gege bi aye ati emi mi. Bee na otito ni eleyi. Guru-mukha-padma-vākya, cittete koriyā aikya. Oni kalu ku gbodo fi se wa wu. Sugbon ti o ba se afikun, ayipada, o pari fun ni yen. A ko gbodo se afikun, tabi ayipada. E gbodo sunmo guru - guru tumo si ojise ododo Oluwa, Krishna. e si gba oro re ni ipa bi e se le sise fun. Nigbana ni e o se aseyori. Ti e ba se awawi, "Emi ni oye ju guru mi lo, ati pe mo le se afikun, tabi ayipada," o ti pari fun e ni yen. Nitorina iyen ni kan ni. Bayi, e korin siwaju si.

Omo Ijo: Śrī-guru-caraṇe rati, ei se uttama-gati.

Prabhupāda: Śrī-guru-caraṇe rati, ei se, uttama-gati. Ti o ba fe se ilosiwaju gidi, nigba na o gbodo ni igbagbo to duro sin sin loju ese guru. Leyin na?

Omo ijo: Je prasāde pūre sarva āśā

Prabhupāda: Je prasāde pūre sarva āśā. Yasya prasādāt... Eyi ni ilana eko otito ti gbogbo awon Vaishnana Bee na afi ti a ba fi se iwa wu, a o le kuro nipo mūḍha, [omugo], alaaye eyi si wa ninu Ajāmila-upākhyāna yi. Bee na a nka ese yi l'oni, sa evaṁ vartamānaḥ ajñaḥ. O tun so wipe. Vyāsadeva tun so wipe " Alaimokan yi fi idi re mule ninu, o fi gbogbo okan re sinu itoju omo re, ti o npe oruko re ni Narayana" Ko mo wipe... "Kini aini itunmo Nārāyaṇa yi"? O mo omo re. Sugbon Nārāyaṇa je alaanu pupo to se wipe nitoripe o npe omo re kikan kikan, Nārāyaṇa, joo wa nbi. Nārāyaṇa, joo gba eleyi' Bee na ni Olorun ngba gege bi " O nke pe Nārāyaṇa" Olorun ni alaanu julo. Ko ni ero wipe " Emi nlo si odo Nārāyaṇa" Oun pe omo re nitoripe o ni ife re. Sugbon nipa eyi o ni orirere ati pe oruko mimo Olorun, Nārāyaṇa. Ori rere re ni yi. Ntorina, idi re ni yi, ti a fi nyi oruko pada. Fun kini? Nitoripe gbogbo oruko gbodo wa fun pe ki a di ojise Olorun. Bee na gege bi Upendra. Upendra tumo si Vamanadeva. Nitorina, ti e ba pe "Upendra" tabi bakanna, oruko na di akoso. A o se alaaye eleyi ni igba to ba ya.