YO/Prabhupada 0049 - Awon ofin eda ti fi wa si idande



Arrival Talk -- Aligarh, October 9, 1976

Bee na iyinlogo ni idapo yi ni okiki. Ibukun ti Oluwa Chaitanya Maahaprabhu ni yi. Paraṁ vijayate śrī-kṛṣṇa-saṅkīrtanam. Ibukun Re ni yi: ni ki-korin lapapo lasan ni akoko yi. Eyi je nkan ti won tenumo ninu awon iwe vediki, ninu Vedanta sutra. Śabdād anāvṛtti. Anāvṛtti, igbala, Ipo wa nisinyi je ti idande Ofin eda ohunkohun fi wa si idande. A le so laini ironu wipe a ti ni ominira - iyen ni aimokan wa - sugbon daju daju awon ofin eda ohunkohun fi wa si idande.

prakṛteḥ kriyamāṇāni
guṇaiḥ karmāṇi sarvaśaḥ
ahaṅkāra vimudhātmā
kartāham...
(BG 3.27)

Awon ofin eda ohunkohun ti fi wa si idande, sugbo awon omugo, vimudhātmā, ninu ti igberaga asan, iru eniyan be yen ro wipe ohun ni ominira. Rara. Ki ise be. Nitorina eyi je ede aigbede. Bee ni ede aigbede yi ni lati ni iyanju. Eyi ni ifojusi ile aye. Ni idi eyi Oluwa Chaitanya Mahaprabhu fi ase si wipe ti e ba se ipe Hare Krishna maha-mantra, anfani akoko ti e ma mu sile ni ceto-darpaṇa-mārjanam (CC Antya 20.12). Nitoripe ede aigbede je nkan ti okan. Ti aya ba di mimo, okan di mimo, ni igba na ko ni si ede aigbede. Nitorina okan yi gbodo di mimo. Iyen si ni ere akoko fun pipe Hare Krishna. Kīrtanād eva kṛṣṇasya mukta-saṅga paraṁ vrajet (SB 12.3.51). Ni iwonba pipe Krishna, Krsnasya, oruko mimo Olorun, Hare Krishna. Hare Kṛṣṇa, Hare Rāma, nkan kan ni. Rama ati Krishna ko si iyato. Rāmādi-mūrtiṣu kalā-niyamena tiṣṭhan (Bs. 5.39). Eyi je nkan ti e nilo. Ipo isinyi ni ede aigbede, wipe "Mo je eso ti eda ohunkohun," "Emi ni ara yi," "Omo India ni mi," Omo Amerika ni mi," "Omo ajagun ni mi, " ati be be lo.... Opolopo isoni loruko. Sugbon ko si eyi ti a je nbe. Eyi ni ipare. Ceto-darpaṇa. Ni igbati o ba ye yin daju pe " Emi ki nse omo India, emi ki nse omo Amerika, Emi ki nse alufah, emi ki nse ajagun" - eyi tumo si "Emi ki nse ara yi" - okan a wa je ahaṁ brahmāsmi.. Brahmā-bhūtaḥ prasannātmā na śocati na kāṅkṣati (BG 18.54). Eyi ni a nfe. Eyi ni aseyori aye.