YO/Prabhupada 0069 - Emi o ni ku



Conversation Pieces -- May 27, 1977, Vrndavana

Kīrtanānanda: Inu wa o le dun ti ara yin ko ba ya.

Prabhupāda: Ara mi le nigbogbo igba.

Kīrtanānanda: Kilode ti e o ni fun wa ni arugbo yin?

Prabhupāda: Nigbati mo ba ri wipe nkan nlo dede, o mu inu mi dun. Kini nkan yi pelu ara yi? Ara ni ara. A ki nse ara yi.

Kīrtanānanda: Se ki se Purudasa lo fi odomode re fun baba re?

Prabhupāda: Hm?

Rāmeśvara: Yayati. Oba Yayati sowo arugbo re.

Kīrtanānanda: Pelu omo re. E le se be na.

Prabhupāda: (Rerin) Tani o se?

Rāmeśvara: Oba Yayati.

Prabhupāda: Ah. Yayāti. Rara, nitori kini. Eyin ni ara mi. Nitorina eyin e ma gbe igbeisi aye yin lo. Ko si iyato. Gege bi mo se nse ise, bee na ni Guru Maharaja mi wa nbe, Bhaktisidhanta Saraswati. O le ma wa nibi ninu ara, sugbon nigbogbo nkan ti a nse o wa nbe. Mo ro wipe mo ti ko nipa iyen.

Tamāla Kṛṣṇa: Bee ni, o wa ninu Bhagavatam, wipe "Eni ti o nba gbe, o wa lailai. Eniti o ba ranti awon imoran re yi o ni aye ainipekun."

Prabhupāda: Bee na emi o ni ku. Kīrtir yasya sa jīvati: "Eniti o ba ti se nkan to jo ju, o di eni ayeraye. Ko ni ku mo. Ni paapa ni aye ojojumo wa... Laise ohun meji, eyi je asan, karma phala. Eniyan gbodo gba ara miran gege bi ayanmo re. Sugbon fun olufokansin, ko si ohun ti o nje be. O ngba ara ni gbogbo igba lati fi se ise Oluwa. Nitorina ko si karma phala.