YO/Prabhupada 0110 - Oye ke di omolangidi assaju



Morning Walk -- April 19, 1973, Los Angeles

Svarūpa Dāmodara: Ti won ba gbo Śrīmad-Bhāgavatam, ni okan won a yipada.

Prabhupāda: Dajudaju. L'ana, enikan ti dupe lowo awon akeko wa: Inu wa si dunsi pe ni bi e se nfun won ni Bhāgavatam. Abi beko, enikan sobe?

Elesin: Beeni, beeeni. Tripurāri lo so be. Tripurāri.

Prabhupāda: Tripurār Beeni. Se enikan sobe?

Tripurāri: Beeni, oni awon omo-okurin meji ni papa-ọkọ ofurufu, won ra akojopo Śrīmad-Bhāgavatams.

Jayatīrtha: Akojopo won?

Tripurāri: Apa mefa. pelu Bhāgavatams l'owo, won so wipe " Ese pupo". lehinna ni won si fi won sinu atimole won si wa nduro de oko-ofurufu, ikọọkan won si ni Canto Àkọkọ lowo...

Prabhupāda: beeni. eyikeyi Okurin to lododo asi ni asepo pelu egbe wa Ise nla leyin nse fun Olorun nipa pipin awon iwe yi. O si fe so fun gbogbo eniyan: sarva-dharmān parityajya mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja (BG 18.66). Nitorina ni O se wa. Bee na enikeni ti o ba nse ise kanna, wipe: "jowo ara re fun Olorun", o si di alafojumo Olorun gidi gan. Bi o ti wa ni so ninu Bhagavad-gita : na ca tasmān manuṣyeṣu (BG 18.69). Ni awujọ awọn eniyan, ko si eni ti o s'owon ju eni na ti o nse iran lọwọ iṣẹ ìwàásù. Hare Kṛṣṇa.

Brahmānanda: Bi awon omo-langidi ni a je fun yin, Śrīla Prabhupāda. Eyin le nfunwa ni awon iwe na.

Prabhupāda: Rara. Omo-langidi ni gbogbo wa je fun Krsna. Emi na gan. Omo-langidi. Itumo. Eleyi ni asa a t'owo d'owo. A gbodo di omolangi. Gbogbo e ni yen. Gege bi mo se je omolangidi fun Guru Mahārāja temi, ti eyin na ba di omolangidi funmi, iseyori niyen. Aseyori wa je nigba ti a ba di omolangidi assaju. Tāṅdera caraṇa sevi bhakta sane vāsa. Lati gbe ni awujọ ti awọn josin ati lati diomolangidi ti awọn ācārya asiwaju. Eyi ni aseyori. A ngbiyanju wa lati se. Awujo isokan Olorun ati isin awon asiwaju. Gbogbo e niyen. Harer nāma harer nāma... (CC Adi 17.21). Awon eniyan yi o wa. Awon eniyan a se imoore ona itankale wa. Yi o gba akoko die.

Svarūpa Dāmodara: Won ti nse imoore die bayi ju awon odun to koja.

Prabhupada: Beeni, beeni.

Svarūpa Dāmodara: Won ti bere si ni oye ojúlówó imoye.