YO/Prabhupada 0127 - Bi awon eyan se ba ajo wa je pelu iwa iranu



Lecture on SB 1.2.11 -- Vrndavana, October 22, 1972

Guru Mahārāja mi ma sowipe " Ema gbiyanju ati ri Krsna; E sise toa jeki Krsna ri eyin na". Nkan tafe niyen. Asi le gan ati ni akiyesi Krsna, yat kāruṇya-katākṣa-vaibhavavatām, katākṣa-vaibhavavatām.. Prabodhānanda Sarasvatī sowipe teyan baleni akiyesi Krsna fun igba die, ile-aye re tida niyen. lesekese. Bawo lesele rigba? Bhaktyā mām abhijānāti (BG 18.55). E sise fun Krsna. E sise fun Krsna gege bi Oluko yin baso. Oluko ni asoju Krsna kosi basele sumon Krsna laisi Oluko. Yasya prasādād bhagavat-prasādaḥ. Tobaje pe Oluko yin daju, todeje asoju Krsna, koni le mo. gbogbowa lale di asoju Krsna. Bawo? teba jise Krsna laifi nkan kun. Otan.

Gege bi Caitanya Mahāprabhu seso āmāra ājñāya guru hañā (CC Madhya 7.128), "Eyin na le di Oluko teba tele nkan tin ba so". tebale jise Caitanya Mahāprabhu, Kṛṣṇa eyin na ledi guru. Āmāra ājñāya guru hañā, sugbon o daju pe awa o fe jise awon ācārya. afe da tiwa sile. Asini irohin bi awon eyan se ba ajo wa je pelu iwa iranu. lai jise Oluko wa da nkan tiwan sile, lehin na gbogbo ajo na si daru. Nitorina ni Viśvanātha Cakravartī Ṭhākura se tẹnumọ oro oluko. Vyavasāyātmikā buddhir ekeha kuru-nandana (BG 2.41). Teba fojusi ase Oluko, lai ronu boya omateyin lorun, eyin na mase aseyori.

yasya deve parā bhaktir
yathā deve tathā gurau
tasyaite kathitā hy arthāḥ
prakāśante mahātmanaḥ
(ŚU 6.23)

Ijẹrisi awon Olori leleyi agbudo jise awon asoju Krsna, lehin na ile-aye wa mani ilosiwaju. nigbana a leni oye Krsna niooto. Vadanti tat tattva-vidas tattvam (SB 1.2.11). Agbudo gbo lenu awon tattva-vit, ema loba awon alakowe tabi oloselu. Rara. Egbudo gbo latenu eni toba mo. teba tenumo ofin yi, nigbana lema ni oye gbogbo nkan.

Ese pupo.