YO/Prabhupada 0130 - Krishna ti farahan ninu orisirisi irisi



Lecture on BG 4.5 -- Bombay, March 25, 1974

Kṛṣṇa ti farahan ninu orisirisi irisi. Egbiyanju lati monipa ipo Kṛṣṇa. Owa ninu okan gbogbo wa bi Paramātmā Īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati (BG 18.61). oun lode fun gbogbo wani itosona. orisirisi iwonba eda lowa. Oun lon fun gbogbo awon eda wanyi ni itosona. sele fori ro aduro ise ton se. sugbon, Osiwa bosewa. Goloka eva nivasaty akhilātma-bhūtaḥ (Bs. 5.37). Goloka eva nivasati. Kṛṣṇa si wa ninu ijoba re ni Goloka Vṛndāvana, Osi gbadun asepo pelu Śrīmatī Rādhārāṇī.. eleyi yato si ironuokan awon Māyāvādī Nitoripe Olorun ti wole sinu okan gbogbo eda laaaye yi, Konsepe kos'Olorun mo ninu injoba re. Rara. Osi wanbe. Kṛṣṇa niyen. Pūrṇasya pūrṇam ādāya pūrṇam evāvaśiṣyate (Īśo Invocation). Oro iwe mimo Veda niyen.

Awana ti jerisi teba ni rupee kan soso, teba mu anna kan, omadi anna marunlelogun. teba si mu anna meji, adi anna merinla. teba si mu anna merindilogun adi otan niyen. Sugbon Krsna yato. Ole so ara re di pupo; sugbon Krsna t'alakoko si wan'be. Krsna niyen. awa na ti jerisi: teba yo ikan kuro ninu ikan otan niyen. sugbon ninu ijoba orun, iyato wa. teba mu ikan kuro ninu ikan, t'alakoko siwa. Kṛṣṇa niyen. Advaitam acyutam anādim ananta-rūpam (Bs. 5.33).

Kosi besele ni oye Krsna lati eko awon iwe Veda. sugbon itumo awon Veda ni Vedānta, lati ni oye Kṛṣṇa. Vedaiś ca sarvair aham eva vedyaḥ (BG 15.15). sugbon nitoripe awa ti ko lati gbarale Kṛṣṇa tabi awon elesin re, Kosi basele mo nipa idi fun awon Veda. ama salaaye lori oro yi ninu akori Keje. Mayy āsakta-manāḥ pārtha.... Mayy āsakta-manāḥ pārtha yogaṁ yuñjan mad-āśrayaḥ. Mad-āśrayaḥ. Asaṁśayaṁ samagraṁ māṁ yathā jñāsyasi tac chṛṇu (BG 7.1). Teba fe monipa Kṛṣṇa asaṁśayam ni otooro, ati samagram, egbudo bere sini se yoga.

Kini itumo yoga na? Man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). Mad-āśrayaḥ yogaṁ yuñj... Yogaṁ yuñjan, mad-āśrayaḥ. Mad-āśrayaḥ, oro yi se pataki gan. Itumo Mat niwipe " Ele bere lesekese" - sugbon ko fibe rorrun. tabi ke farale Olorun. gege bi ile-ina, pulọọgi si wan'be pulọọgi na si sopọ pelu ile-ina, teba ki okun waya bonu puloogi, oma tona. gege na ni ibere akori iwe yi, wansi sowipe evaṁ paramparā-prāptam imaṁ rājarṣayo viduḥ (BG 4.2). Teba gbarale eto paramparā.... gege bi apeere wa. teba ki okun waya bonu puloogi lesekese lema nina. gege na teba gba'aabo lowo eni towaninu eto parampara....

Eto paramparā wa. Kṛṣṇa, fun Brahmā ni oye oro yi . Brahmā na sifun Nārada. Nārada salaaye fun Vyāsadeva. Vyāsadeva slaaye fun Madhvācārya. Madhvācārya salaaye ni orisirisi ona. lehin na Mādhavendra Puri. Mādhavendra Purī, Īśvara Purī. Lati Īśvara Purī, Oluwa Caitanya. bayi ni eto paramparā seje. Vaiṣṇava sampradāya erin lowa. Rudra-sampradāya, Brahma-sampradāya, Kumāra-sampradāya, ati Lakṣmī-sampradāya, Śrī-sampradāya.

sampradāya-vihīnā ye mantrās te niṣphalā matāḥ. teyin ba gba imoye nipa Kṛṣṇa tio ti sampradāya jade, niṣphalā matāḥ, ounkoun terigba kowulo. Ko wulo. alebu towa niyen. Opolopo awoneyan lon kawe Bhagavad-gītā, awon eyan o mo eniti Kṛṣṇa je. nitoripe lati evaṁ paramparā-prāptam (BG 4.2) ko lonti rigba. Afi teba gba oro na lati paramparā.... teyin o ba gba'na lati puloogi to wa lti ile-ina, kini iwulo boolobu ati okun waya? Kowulo mo.

vedeṣu durlabha, bi Krsna sen fesi niyen. Kolesese tobajepe alakowe nikan leje. Vedeṣu durlabham adurlabham ātma-bhaktau (Bs. 5.33). Oro Brahma-saṁhitā niyen.