YO/Prabhupada 0133 - Mofe akeko eyokan pere tole tele nkan timo ba so



Arrival Lecture -- San Francisco, July 15, 1975

Nigbami awon eyan man yinmi l'ogo fun ise timon se ni gbogbo agbaye. Sugbon miorope eyan pataki nimoje. Sugbon odami loju pe nkan ti Krsna so nimon salaaye. Otan. Mio fi nkankan kuk,mio si yo nkannkan kuro. Nitorina mo ti salaaye Bhagavad-gita gege boseje. Ti awon bafe yinmi logo pe mio fi nkankan kun oro timon salaaye, mole gba yen. Emina tiripe ise yi ti ni ilosiwaju. Miofun awon ara ilu America ati Europe legunje. Talaka lati Orile-India nimo tiwa. Mowa si Orile-ede America pelu rupees ogoji nisin owo timoni ju rupees ogoji millionu lo. Kosejo agbara idan nibe. Dide kolo seyin, Oun sun. Asiri towa niyen teba fedi guru to looto lenu... teba fe tan awon eyan je, Nkanmi niyen. Nitoripe awon eyan fekan tanwan je, awon odaran na ti po gan. lesekese taba sowipe "toba fe di akeko mi egbudo fi awon nkan merin yi sile: emani asepo pelu obirin mo, ema moti tabi tii ati siga, ema jeran mo, ema ta tete mo," ton ba ti gbo bayi wansowipe, " Swamiji yi ko laju." Sugbon teba sowipe " Elese ounkoun teba fe. Egab mantra yi kefunmi ni $125", inu awon eyan madun si. Nitoripe ni Orile-ed America, owo kekere ni $ 125 je. Awon eyan lesan. Tobajepe owo nimo fe, mio bati pawo repete. Sugbon miofe. Miosi fe awon akeko to po, ti moba ri eyokan pere tole tele nkan timo ba so odafunmi. Ekas candras tamo hanti na ca tara-sahasrasah. Osupa kan ni ofurufu to lati tanna ninu gbogbo agbaye. Awon irawo si po gan sugbon koni si iwulo fun wan. Gege na nkan timo fe ni wipe, kikan ninu awon akeko mi di elesin to daju tode ya si mimo. Sugbon odamiloju pe moni akeko to po to looto lenu wansi daju. Orire daada timo ni niyen. Sugbon toba jepe ikan soso nimo ri, koba temi lorun na. Kosi iwulo fun irawo repete.

Ilana toyeke tele tiwa, osi rorun gan, tabale ni oye gbogbo awon ilana ninu Bhagavad-gita lehin na ale bere sini ka Srimad-Bhagavatam... Sugbon Caitanya Mahaprabhu ti funwa ni ilana to rorun toba le fun awon eyan lati kawe. Awon sastra na ti salaaye bayi:

harer nāma harer nāma harer nāmaiva kevalam
kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva gatir anyathā
(CC Adi 17.21

Teba fe ka wa iwe Veda, nkan toda niyen. Aw tini bi iwe adota, Teba kawaon, eyin na ledi alakowe ninu eto, imoye, esin, tabi eto awujo eda. Gbogbo nkan titide eto Oselu lowa ninu Srimad-Bhagavatam. Bayi eyin na ledi Okurin tosi l'ogbon ju Sugbon teba rowipe eyin ofibe feran iwe kika, tabi kosi asiko lati fi kawon ele korin Hare Krsna. teba gba ona kan ninu awon mejeeji, eleni aseyori. Ti iwe kika ba lee funyin ele korin Hare Krsna. Emani ilosiwaju. tebale ka awon iwe na kesi korin Hare Krsna iyen lo daaju. Sugbon kosejo aini-aseyori. tebale korin Hare Krsna maha-mantra , sugbon iwe kika sooro koburu. Kosoro ipadanu. Orin kiko yi tito. sugbon teba kawe eyin na le soro si awon tonba fe fun yin ni idamu. Eleyi mafun yn ni iranlowo ninu iwaasu teyin se. Nitoripe teyin banse iwaasu, egbudo daaun si awon ibeere, ema ba orisirisi awon eyan tonma wa fun e ni idanwo. teyin ba lagbara ninu awon iwe Veda lehin na eledi aayo Krsna. Krsna sowipe

na ca tasmāt manuṣyeṣu
kaścit me priya-kṛttamaḥ
(BG 18.69)
ya imaṁ paramaṁ guhyaṁ
mad-bhakteṣu abhidhāsyati
(BG 18.68)

Enikeni toba sewaasu imoye asiri yi, sarva-dharman parityajya mam ekam saranam vraja (BG 18.66), teyan na bale sewaasu na fun gbogbo agbaye, lesekese ni Olorun ma fojule.