YO/Prabhupada 0136 - Bayi ni imoye yi se wa lat'oke de le



Lecture with Translator -- Sanand, December 25, 1975

Olorun ni tumo Bhagavān. Lona meta: brahmeti paramātmeti bhagavān iti śabdyate (SB 1.2.11). leyan le mo Otito to daju ju laye yi Eyan leni imoye Otito yi ni alakoko bi Brahman, Kini ipo awon jñānī, ikeji ni Paramātmā, eleyi ni ipo awon yogi iketa je imoye Olorun ni ona to daju gan, oye Olorun bi eyan. Olorun ni eto tose pataki ju Tabefe mo nipa Oorun, Olorun si wanbe bi sūrya-nārāyaṇa, tabi Olori isogbe-Oorun. Wansi ti funwa ni oruko re ni Bhagavad-gītā - Vivasvān. Olorun si soro ninu iwe kerin, imaṁ vivasvate yogaṁ proktavān aham avyayam: (BG 4.1) Niibere mosalaaye gbogbo sayensi Bhagavad-gītā, si orisa-oorun, Vivasvān," Vivasvān manave prāhur manur ikṣvākave 'bravīt. orisa-oorun si salaaye fun Manu, Manu na salaaye fun omo-okurin re. bayi ni imoye yi se wa lat'oke de le. gege na taba soro nipa jñāna, agbudo gbo latenu eyan. Ninu imoye Otitio to gaju Bhagavān ni oro to kehin, Osi soro ninu Bhagavad-gītā.

bhagavān uvāca ni nkan ti Vyāsadeva feso nibe Kosi sowipe kṛṣṇa uvāca, nitoripe nigbami awon asiwere le ka itumo toyato si nkan ti Kṛṣṇa ba so. Itumo bhagavān uvāca niwipe ounkoun to baso kole si asise nibe. Awon eyan lasan bi tawa, ani alebu merin:: bhrama pramāda vipralipsā kara-ṇāpāṭava. Sugbon Olorun Krsna, tabi awon iranse Krsna ton ni oye nipa Krsna, fun awon eyan bayi kolesejo alebu. Gbogbo wan lon daju. Nitorina ni Krsna se fun wa ni ilanani yi,

tad viddhi praṇipātena
paripraśnena sevayā
upadekṣyanti tad jñānaṁ
jñāninas tattva-darśinaḥ
(BG 4.34)

Egbudo gba imoye lowo awon eyan tonti ri otito yi Agbudo sunmo awon eyan bayi. Bibeko, taba sunmo awon eyan ton so isokuso, kosi basele ri imoye gidi gba Awon onisokuso bayi, kosi bonsele ni oye Olorun. Nitorina niwonsen sowipe " Bayi ni Olorun se ri", tabi " Bayiko ni Olorun se ri". "Ko s'Olorun", " Olorun o leni Irisi". Iranu ni gbogbo awon nkan ton so yi, nitoripe koseyi ninu wan to laari. Nitorina ni Bhagavān se sowipe, avajānanti māṁ mūḍhā mānuṣīṁ tanum āśritāḥ (BG 9.11). Nitori wa ni Olorun sen wa ni irisi eyan, sugbon awon asiwere wanyi rope eyan lasan loje. Ti Bhagavān ba sowipe ahaṁ bīja-pradaḥ pitā (BG 14.4), " Emini Baba gbogbo agbaye", gbogbo lamo wipe eyan ni baba wa, baba re eyan na loje kilode teyin wa rope eyan koni Olorun je? Kilode? Agbudo ko lodo Bhagavan, eda to logbon ju. Iwe mimo Bhagavad-gītā si je iwe to kunfun imoye nipa Olorun. Kosi basele yi oro towa ninu Bhagavad-gītā. Iranu niyen. Awan tele ofin yi ninu egbe imoye Krsna wayi. Awa o lee da nkan wa sile. Ati pin oro Olorun nise tawa ni. Adeti bere sini sise na.