YO/Prabhupada 0138 - Olorun si dara gan. Ounkoun teba fe asi funyin



Ratha-yatra -- Philadelphia, July 12, 1975

Eyin iyaafin ati Okurin jeje, Ejekin dupe lowo yin kin to bere, awon ara-ilu yi, Philadelphia. Eyin dara gan, esi ni igbonaokan lati ti egbe wa siwaju. Mosi ni igbèsè ore si gbogbo yin. Mosi niigbèsè ore si eyin Okurin at'Obirin ara-ilu America teti funmi ni iranlowo to po gan lati ti egbe imoye Krsna yi siwaju ni awon Orile-ede geesi. Oluko mi si funmi nise ati wa si awon ilu geesi lati sewaasu nipa imoye Krsna. ni odun 1965 mowa si New York. Ni odun 1966 mo bere egbe wa ni New York, Lat'Odun 1967 egbe wa bere sini wa awon Orile-ede bi Europe ati Canada, titi de guusu okun Pacific, lehin na gbogbo agbaye.

Ejekin salaaye diei, nipa egbe wa yi, Imoye Krsna. Ountoni ifarafun gbogbo eyan ni itumo Krsna Gbogbo eda loni ifarasi Krsna, awon eyan nikan ko, awon eranko, eye, oyin, igi, òdòdó, eso, omi. Iworan Vṛndāvana niyen. Ile aye yi lawa. Kosi basele ni ijerisi nipa ijoba orun. sugbon ale n'ìwò die lati mo iyato laarin emi ati èlò.

Egbiyanju lati mo iyato laarin eyan towa laaye at'oku lesekese ti agbara emi ba kuro ninu ara eyan, ara na kole niwulo mo. Itumo oku niyen. Arawa mani iwulo afi ti agbara emi ba wa ninu re. gege bi awa seni oye pe ninu ara wa, emi yato si elo, beena ni ile-aye meji siwa: Ile-aye yi ati ile-aye orun. Gbogbo awon eda layeyi, gbudo pada s'orun. Ile wa ko leleyi. Sugbon bakanna ati bosinu ile-aye yi, botilejepe emi ni gbogbo wa, asi ni ara toni asepo pelu ile-aye yi, nitorina agbudo ni isoro merin: Ibimo, iku, aisan ati ojo -arugbo. gbogbo wa gbudo ga ona merin wanyi. Ninu ile-aye yi, orisirisi ara lawani, sugbon lehin igba die asi paari. gege bi ounkooun teba ni ninu ile-aye yi, fun apeere aso tewoo. Eyin si wosoo nisin, sugbon t'aso na ba darugbo tikole se woo mo, ema junu, lehin na ema wa aso tuntun mi wo. Ara wa ni aso emi wa. Sugbon nitoripe awa feran ile-aye yi, asife gbadun nibe, nitorina lasen gba orisiri ara. Bhagavad-gītā ti salaaye pe, gege bi ero ni ara seri. ninu iwe Bhagavad-gītā, wansi sowipe

īśvaraḥ sarva-bhūtānāṁ
hṛd-deśe 'rjuna tiṣṭhati
bhrāmāyān sarva-bhūtāni
yantrārūḍhāni māyayā
(BG 18.61)

"Awon eyan le gbero, sugbon Olorun lole p'ase si" Olorun si dara gan, Ounkoun teba fe, asi funyin. Oti sofunwa pe awon nkan ayeyi kole tewa lorun, sugbon gbogbo lasife awon nkan na. Nitorina ni Olorun, Krsna, sen funwa ni orisirisi ara lati gbadun ounkoun taba fe. nkan tonpe ni ile-aye Ajẹmọ́-kání. itiranyan ni itumo iyipada ara wa pelu eto itiranyan lawa sen gonke lati ara kan sikeji. Jalajā nava-lakṣāṇi sthāvarā lakṣa-viṁśati. ati koja eda 900,000 towa ninu omi. gege na awon irisi ọgọ́rùn ọkẹ́, toje igi,ohun gibin. bayi ni awa se gunke titi de ara eda eyan, lati le ji imoye wa soke. Iseda ti funwa l'aye, " Kilofe se nisin? Nisin oti l'ogbon to daju. Sofe pada si eto itiranya, tabi sofe guke losi ijoba-orun, tabi sefe pada si Krsna, Olorun tabi sefe joko sibi? Awon aṣayan orisirisi lowa, Bhagavad-gītā ti salaaye,

yānti deva-vratā devān
pitṛn yānti pitṛ-vratāḥ
bhūtejyā yānti bhūtāni
mad-yājīno 'pi yānti mām
(BG 9.25)

Emu eyi tefe, tebafe losi ijoba orun, ele lo na. teba fe duro sibi, ninu awon isogbe aye yi, ele se na. teba sife losi awon isogbe- orun apaadi, ele sebe na. teba sife losodo Olorun, Krsna, ele seyen na. Owo yin lowa. Nitorina kin iyato laarin ile-aye yi, ati ijoba orun? Itumo ijoba orun niwipe kosejo lilo nkan aye yi. Gbogbo nkan towa nibe, awon igi, awon ododo, awon eso, omi, awon eranko - gbogbo lo yasi mimo. kosejo iparẹ. ayeraye lowa fun. teba felosi ijoba orun, esi le gba'ye yi nisin teni ara eda eyan, teba sife duro si ile-aye yi, owo yin lowa.