YO/Prabhupada 0143 - Agbaye to pe repete wa ninu wa ninu agbaye wa



Sri Isopanisad, Mantra 13-15 -- Los Angeles, May 18, 1970

"Oluwa mi, olugbala fun gbogbo eda, ìmọ́lẹ̀ ara re ti bo oju re. Edakun eyo idabo yi ki awon elesin yin bale woo oju yin".

Eri lati awon Veda leleyi. Veda na ni Īśopaniṣad, apa Yajur Veda loje. wansi salaaye wipe, hiraṇmayena pātreṇa satyasya apihitam mukham. gege bi oorun. Lori plánẹ̀tì oorun, Vivasvān ni oruko orisa to gba ijoba nibe. Lati Bhagavad-gītā lati ri iroyin yi. Vivasvān manave prāha. Lori gbogbo planeti, orisa to gbajoba wa nibe. gege bi paneti wa yi, kos'orisa sugbon Olori ijoba si wa. teletele gbogbo gbogbo Olori kan nigbogbo agbaye yi ni, titi de Mahārāja Parīkṣit. Ijoba kan pere loni idari lori agbaye wa. Gege na oni orisa to se pataki lori gbogbo planeti. nibi wanti sofun wa wipe Kṛṣṇa ni Oluwa tose pataki, ni ijoba to gaju ni ijoba Oorun. Ile-aye niyen. Ikan ninu awon agbaye niyen. agbaye to pe repete wa ninu agbaye wa, planeti to po repepte wa. Yasya prabhā prabhavato jagad-aṇḍa-koṭi (Bs. 5.40). Jagad-aṇḍa. Agbaye ni itumo Jagad-aṇḍa Aṇḍa: gege bi ẹyin ni agbaye yi se ri. aimoye egberun ni itumo Koṭi. ninu brahmanjyoti orisirisi agbaye lowa, ninu agbaye tawa yi, aimoye planeti to wa ninu e.. gege na ninu ijoba orun, aimoye planeti Vaikuṇṭha towa nibe. gbogbo awon planeti Vaikuṇṭha wanyi lowa labe idari Olorun. gbogbo awon planeti Vaikuṇṭha lowa labe Nārāyaṇa, afi planeti Kṛṣṇa, ikankan ninu awon Nārāyaṇa yi loni oruko to yato, asi mo imi ninu wan. gege bi awa sen daruko Pradyumna, Aniruddha, Saṅkarṣaṇa... asi ni oruko merinlelogun, sugbon wansi po gan. Advaitam acyutam anādim ananta-rūpam (Bs. 5.33).

Gbogbo awon planeti yi si wa labe idabo ìmọ́lẹ̀ Oluwa aduro tosi wa nibi ni wipe hiraṇmayena pātreṇa satyasya apihitam. Idabo ni itumo Apihitam. Gege bi eyin o leri oorun nitori imole ton wa lati inu re gege na planeti Kṛṣṇa yi, aworan re si wa nibi. lati inu planeti Kṛṣṇa yi ni imole na tin jade. Eyan gbudo wonu imole yi. Adura ton si gba niyen. Hiraṇmayena pātreṇa satyasya. Kṛṣṇa ni otito to gaju, sugbon imole Brahman si bo planeti re. nitorina ni awon elesin sen gbadura, " Edakun eyoo kuro. Eti segbekan kin ba le ri yin. Awon eyan pelu imoye Māyāvāda, awon eyan yi o mo wipe nkan wa lehin brahmajyoti. Eri lati Veda leleyi wipe imole brahma jo ti wúrà. Hiraṇmayena pātreṇa. Idabo to wa lori oju Olorun niyen. Tat tvaṁ pūṣann apāvṛṇu. Gege na, Oni-setoju leyin je. Eyo kuro kin ba le ri oju yin."