YO/Prabhupada 0151 - Agbudo k'ogbon lowo awon Acaryas



Lecture on SB 7.6.1 -- Madras, January 2, 1976

Ki a ti wa nṣe awọn orisiris eto sugbon kole ni aseyori. moti salaye koja lalẹ ano, pe ati bere sini ronu biwipe ani ominiran ati bere sini s'eto orisirisi nkan latile ni idunnu. Kollese se. Kolese se. Ere itanra eni maya niyen. Daivī hy eṣā guṇa-mayī mama māyā duratyayā. kosi besele dakoja. ki wani ona abayo? Mām eva ye prapadyante māyām etāṁ taranti te (BG 7.14). taba si teriba fun Krsna, lehin na a le pada si ipo wa ti teletele. Iyen ni... Itumo imoye Krsna yi niwipe dipo tawa ma fi orisirisi nkan s'okan... wanti ni okan to kun fun iranu. Gbogbo wa lani imo ohun, oto oro niyen, sugbon imoye kun fun iranu. nitorina agbudo s'okan wa di mimo. Itumo bhakti niwipe agbudo s'okan wa di mimo. Wansi ti funwa ni isotunmo Bhakti ninu iwe Nārada Pañcarātra... Rūpa Gosvāmī... Rūpa Gosvāmī sowipe,

anyābhilāṣitā-śūnyaṁ
jñāna-karmādy-anāvṛtam
ānukūlyena kṛṣṇānu-
śīlanaṁ bhaktir uttamā
(Brs. 1.1.11)

bhakti ti ipo kini loje tawa o ba ni nkan imi lokan. Anyābhilā... nitoripe ninu ile-aye yi, labe idari iseda aye yi Prakṛteḥ kriyamāṇāni guṇaiḥ karmāṇi sarvaśaḥ, ahaṅkāra-vimūḍhātmā kartā... (BG 3.27). Awa labe idari prakrti, iseda ile aye yi. sugbon nitoripe awa o l'ogbon, ati gbagbe ipo wa, ahaṅkāra, ahaṅkāra eke. ahaṅkāra eke: "Omo orile-ede India nimi, Omo orile-ede America nimi, brahmana nimi, ksatriya nimi." ahaṅkāra eke leleyi je. Nitorina Nārada Pañcarātra sowipe sarvopādhi-vinirmuktaṁ (CC Madhya 19.170). Eyan gbudo yo gbogbo iranu yi kuro l'okan re, "Omo orile-ede India nimi, Omo orile-ede America nimi, Nkan bayi bayi nimi. ..." Sarvopādhi vinirmuktaṁ tat-paratvena nirmalam. toba ti yasi mimo, nirmalam, laisi awon iranu yi l'okan re, tosi ri wipe " nkankan na nimo je pelu Krsna." Ahaṁ brahmāsmi.

ahaṁ brahmāsmi leleyi. Para-brahman ni Krsna je. Wansi juwe re ninu Śrīmad-Bhagavad-gītā. Arjuna... Paraṁ brahma paraṁ dhāma pavitraṁ paramaṁ bhavān puruṣaṁ śāśvatam ādyam (BG 10.12). Arjuna si daamo lehin na o sowipe, " gbogbo awon Olori lo dayin mo" Ikan ninu awon olori wanyi ni Prahlāda Mahārāja je. Moti juwe awon olori wanyi. Olori ni Brahma je, Olori ni Siva je, Olori ni Kapila je, Kumaras, awon Kumaras merin, olori lon je, Olori na ni manu je, Olori na ni Prahlāda Mahārāja je. Olori ni Janaka Maharaja je. Olori mejila lowa. Arjuna si jerisi wipe " Eyin soro, sugbon Olorun to gaju leyin je," mattaḥ parataraṁ nānyat (BG 7.7), lati ijiriro ti Bhagavad- gita, mo gbawipe Para-brahman leje. iyeni kan ko, gbogbo awon olori si gba gbe na." Laipe yi, ni asiko tawa na, Rāmānujācārya, Madhvācārya, ati awon ācāryas, gbogbo wan lon gba wipe Olorun ni Kṛṣṇa. Ati Śaṅkarācārya gan, oun na si nigbagbo ni Krsna. Sa bhagavān svayaṁ kṛṣṇaḥ. gege na gbogbo awon acarya wanyi si gba wipe pe Olorun gbogbo agbaye ni Krsna je.

Agbudo k'ogbon lowo awon acaryas, awa o gbudo fetisile fun awon okurin lasan tabi awon ton pe ara wan ni acarya. Rara. Kole sise bayi. gege bi awa.... Nigbami ni ile-ejo ale mu idajo lati ile-ejo to yato awon eyan asi gba nitoripe, nkan to se pataki ni. Awa o le dun ara wa da idajo sile. gege na, ācāryopāsanaṁ, ninu Bhagavad-gita wanti salaaye. Agbudo loba awon acaryas. Ācāryavān puruṣo veda: " Eyan to ti gba awon acarya, eyan bayi lole mo awon nkan bonseje." gege na gbogbo awon acaryas. wanti gba Krsna bi Olorun to gaju. Narada ti gba, Vyasadeva ti gba, ati Arjuna na ti gba, oun si gbo latenu Krsna gbogbo oro ninu iwe Bhagavad-gita. ati Brahma na. Ni ano eyan kan beere wipe " boya Oruko Krsna wa ki Dvapara-yuga to bere?" Rara, ninu sastra Krsna wa nbe. Ninu Veda, ninu Atharva Veda ati awon iyoku, oruko Krsna wa nibe> Ninu Brahma-samhita - Brahma lo ko Brahma-samhita- wansi juwe nibe, īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ sac-cid-ānanda-vigrahaḥ (Bs. 5.1), anādir ādiḥ. Anādir ādir govindaḥ sarva-kāraṇa-kāraṇam (Bs. 5.1). Krsna na si sowipe, mattaḥ parataraṁ nānyat kiñcid asti dhanañjaya (BG 7.7). Ahaṁ sarvasya prabhavo (BG 10.8). Itumo Sarvasya niwipe pelu gbogbo awon devatas, ati gbogbo awon eda, gbogbo nkan. Vedanta si sowipe, janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Olorun to gaju ni Krsna je, īśvaraḥ paramam, lati Brahma. Oun lo pin gbogbo imoye Veda, Krsna si sobe na, vedaiś ca sarvair aham eva vedyam (BG 15.15). Opin to gaju niyen.