YO/Prabhupada 0153 - Lati awon ilowosi wanyi lale se'danwo fun awon eyan lati ye iru ogbon wo loni

From Vanipedia
Jump to: navigation, search
Go-previous.png Previous Page - Video 0152
Next Page - Video 0154 Go-next.png

By Literary Contribution, One's Intelligence is Tested - Prabhupāda 0153


Interview with Newsweek -- July 14, 1976, New York

Onirohin: sele salaaye awon eto meta te daruko - jijeun, sisùn ati imo ako ati abo, mosi fe ke salaaye funmi iru ofin wo lema fun awon eyan ton wa imole tole funwan ni iranlowo ninu aye wan.

Prabhupāda: Beeni. Beeni, Gbogbo eleyi wa ninu awon iwe wa. O wa ninu iwe wa. Eto na po gan, konse nkan tale mo ni iseju kan.

Onirohin: Mogbo pe fun iwonba die leyin ma sun. Eyin ma sun fun wakati meta si merin laale. Seyin rowipe awon eyan toni imole nipa eto emi gege bayi lon se mase na

Prabhupāda: Beeni, aleri lati iwa awon Gosvami. Wan o ni iwulo fun awon nkan aye yi. Jijeun, sisun, imo ako ati abo, awon nkan yi o si mo ninu aye wan. Wan foju si ise Krsna.

Onirohin: Iru ise wo lon se?

Rāmeśvara: Ise Krsna tabi ise Olorun.

Bali-mardana: On tele apẹẹrẹ awon oga ti tele ninu eto emi

Onirohin: Oda, nkan temi femo niwipe... Se wan ti sewaadi lati mo wipe wakati meta si merin nikan loye ka sun?

Bali-mardana: Ni oro imi, Obirin yi femo kilode teyin fin sun fun wakati meta si merin nikan. Bawo lese de ipo yi?

Prabhupāda: Eleyi ko kin se nkan eke. Teba mu ise emi ni pataki, beena leyin ma bolowo awon ise ile-aye yi. Idanwo towa niyen.

Onirohin: eyin de ti wa lori ipo yi....

Prabhupāda: Rara, Tara mi nikan ko nimon so, sugbon mon salaaye idanwo to wa. Bhaktiḥ pareśānubhavo viraktir anyatra syāt (SB 11.2.42). teba ni ilosiwaju ninu bhakti, ninu eto emi, lehin na lema gbokan kuro ninu awon nkan aye yi.

Onirohin: Se rowipe iyato wa laarin awon orisiri eyan ninu aye yi? nkan ti mo fe so niwipe, se rowipe awon omo-orile ede India yato si awon omo-orile ede Europe nitoripe wan le nigbagbo ju ninu imoye Krsna yi?

Prabhupāda: Rara, Enikeni toba l'ogbon lori leni imoye Krsna. Moti salaaye tele wipe, afi teyan ba l'ogbon kosi bosele gba imoye Krsna yi s'okan. Owa ni sisi fun gbogbo eyan. sugbon orisirisi ogbon lowa. Ni Orile-ede Europe, America, wan l'ogbon gan sugbon funn awon nkan ile ayi lon lo ogbon wan fun. Ni Orile-ede India awon eyan lo ogbon wan fun eto emi. Nitorina lehin sen ri awon eya pelu ipo aye to wole sinu emi gan, pelu awon iwe lori eto emi. Gege bi Vyāsadeva. Oni-ile ni Vyāsadeva na je, ninu aginju lon gbe, sugbon s'eyin na ri iwonba iwe to te jade. Koseni to le se iru e mo. Lati awon ilowosi wanyi lale se'danwo fun awon eyan lati ye iru ogbon wo loni. gbogbo awon Okurin pataki ninu aye yi, awon oni sayensi, awon Ologbon eto imoye, ati awon Onimọn ẹrọ, lati awon iwe ton ko tabi iwonba alaaye ton se lori orisirisi eto, lale fi dawon mo. Kon se pelu iru ara ton ni.