YO/Prabhupada 0155 - Gbogbo eyan lofe d'Olorun



Lecture on SB 7.6.5 -- Toronto, June 21, 1976

nisin, awa ti ri latinu Bhagavad-gita, awon oro meta yi: Sanātanaḥ, alailopin, wansi lo oro yi nibe. Nkan t'alakoko ni jiva, awon eda aye yi, wanti juwe wan bi sanātanaḥ. Mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ jīva-loke sanātanaḥ (BG 15.7). Eda ile aye yi laje, sanātanaḥ, konsepe ati di jiva-bhutah nitori iwa māyā. Awa la bosinu owo māyā fun ara wa; nitorina lase di jiva-bhutah. nioto oro sanatana laje. Itumo sanatana ni alailopin. Nityo śāśvata. wanti salaaye Jivātmā : nityo śāśvato yaṁ na hanyate hanyamāne śarīre (BG 2.20). sanātana leleyi. awa o si l'ogbon pe toba jepe alailopin niwa, sanatana, mio le ni ni ibimo tabi'ku, kilode timose bosinu isoro ibimo ati iku yi? Nkan ton pe ni brahma-jijñāsā leleyi. Sugin awa o si l'eko. sugbon agbudo keko. Agbudo gbiyanju lati mu ilana yi s'okan. Sanatana niwa. agbaye to yato siwa, wansi juwe re ninu Bhagavad-gita, paras tasmāt tu bhāvo 'nyo 'vyakto 'vyaktāt sanātanaḥ (BG 8.20). Vyakto 'vyaktāt sanātanaḥ Ile aye yi o seri, sugbon leyin re osi ni agbara to je mahāt-tattva. Eleyi o se ri. gege na vyakto 'vyaktāt. Lehin eleyi iseda imi tunwa, iseda t'emi, sanatana. Sanatana leleyi je. Paras tasmāt tu bhāvo 'nyo vyakto 'vyaktāt sanātanaḥ (BG 8.20). ati jīva-bhūtaḥ-sanātana. ninu apa iwe okankola, Arjuna ti juwe Krsna bi sanatana. gege na sanatana meta.

Ti gbogbo wa baje sanatana, sanatana-dharma si wa ati Krsna to je sanatana, sanatan lawa na je niyen. Toba de ti so wa po, nkan ton pe ni sanatana-dharma niyen. Awon eyan yi o mo nkan ton je sanatana. wan rowipe tinba mura bi awon kan, ton bimi si awujo awon eyan kan, lehin na moti di sanatana-dharma. Rara. Gbogbo eyan ledi sanatana-dharma. Sugbon awon eyan o mo itumo sanatana. Sanatana ni gbogbo eda je. Ati Krsna na, sanatana ni oLorun je. osi ni ibi tale pade - sanatana dhama nibe je. Sanātana dhāma, sanātana-bhakti, sanātana-dharma. taba tin se, sanatana-dharma loje. kini sanatana-dharma yi? Fun apeere tin ba pada si sanatana-dhama yi, Olorun de wa, sanatana, a t'emi timoje sanatana. Kinise sanatana wa? Seyen wipe tin ba losi sanatana-dhama mole di Olorun? Rara. Kosi besele di Olorun. Nitoripe Olorun kan soso lo wa. Olori gbogbo wa loje, iranse re la wa je. Caitanya Mahāprabhu: jīvera svarūpa haya nitya kṛṣṇa dāsa (CC Madhya 20.108-109). nibi gbogbo eyan lon sowipe wanti di Krsna. Sugbon afi tabale pada si sanatana-dhama - kosi basele debe lehin na a le pada si ise fun Olorun. Sanatana-dharma niyen.

Ele se igbaradi. Bhakti-yoga nitumo sanatana-dharma yi. Nitoripe ati gbagbe. Gbogbo eyan lofe d'Olorun. nisin ele bere sini s'igbaradi lati di iranse Olorun. teba si muye, O le dayin loju pe etidi Iranse Olorun, bhakti-marga niyen. gege bi Caitanya Mahāprabhu se so, gopī-bhartur pada-kamalayor dāsa-dāsa-dāsa-dāsānudāsaḥ. teba ti mo bonsen di iranse awon iranse awon iranse Olorun igba oogorun lehin awon iranse - ehin na lema daju (CC Madhya 13.80). Sugbon nibi gbogbo eyan lofe di Olorun Awon lo oro wanyi nilokulo "so 'ham," "ahaṁ brahmāsmi" nitorina moti di Olorun." Bayi ko loje. Awon oro Veda lelelyi, sugbon "Olorun nimi" konitumo so 'ham. Itumo So 'ham niwipe " amuye kanna nimoni". nitoripe mamaivāṁśo jīva-bhūtaḥ (BG 15.7). Nkankanna ni Jiva je pelu Olorun, Krsna, amuye kanna lon ni. gege bi omi kekere lat'Okun. Iwonba kemika ninu Okun ati omi kekere na nkankanna lon je Nkan ton pe ni so 'ham tabi brahmasmi. konsepe ale lonilokulo awon oro wanyi lati eya Veda, ka bere sini sowipe " Olorun nimi. Moti d'Olorun." Teyin ba je Olorun bawo lojepe eti di aja? S'olorun le di aja? Rara. Kolese se. Nitoripe iwonba kekere laje. Wansi salaaye ninu sastra:

keśāgra-śata-bhāgasya
śatadhā kalpitasya ca
jīvaḥ bhāgo sa vijñeya
sa anantyaya kalpate
(CC Madhya 19.140)

Idanimo t'emi wa niwipe ikan ninu irun ori ton pin s'ona egbaarun. O si kere gan, taba mu apa kan ta pin s'ona Ẹgbaarun, idanimo wa niyen. Idanimo to kere yi si wa ninu ara wa Gege na nibo lema ri? Eyin o ni iru ero bayi. Nitorina lase sowipe nirākāra. Rara, ākāra wa, sugbon osi kere tojepe, awa o le ri eleyi pelu oju lasan. gege na agbudo ri lati oju awon Vedas. Śāstra cakṣuṣa. ẹ̀yà Vedanta niyen. Agbudo tele sastra. pelu oju lasan ko. Kolese se