YO/Prabhupada 0157 - Afi t'okan yin ba moo, kosi besele ni oye nipa Hari



Lecture on SB 6.2.11 -- Vrndavana, September 13, 1975

Teyin o ba gba awon ilana ninu sastra,nipataki awon Ilana ti Krsna Olorun to gaju, funwa ninu Bhagavad-gita... kókó oro ninu sastra niyen. Egba be. Lehin na inuyin ma dunsi. Bibeko rara. nibi wan sowipe aghavān, awon okurin elese, kosi bonsele ni iyasi mimo, pelu awon irubo ayeye wanyi, tabi ètùtù, tabi ibura, vrataḥ. Lehin na bawo lesele se? Nitoripe gbogbo eyan... Yathā harer nāma. Nitorina lonse sofunwa wipe, harer nāma harer nāma harer nāmaiva kevalam, kalau nāsty eva nāsty eva nāsty eva (CC Adi 17.21). Nkankan na loje. Kosibi kankan ninu sastra tema ri awon oro ton takp si rawan. Ninu Agni Purana, ati Śrīmad-Bhāgavata wanti salaaye nkankanna. Agni Purāṇa sowipe, harer nāma harer nāma harer nāmaiva kevalam, nibi ninu Śrīmad Bhāgavatam wan sowipe yathā harer nāma-padair udāhṛtaiḥ tad uttamaśloka-guṇopalambhakam. Kiko oruko mimo Olorun nitumo nāma. O rorun bayi. Sugbon teba korin harer nāma eleni oye die die, nkan ti Hari je, bi irisi re seje, iru amuye wo loni ati iru ise wo lonse. Lehina lele ni oye na. nitoripe laisi harer nāma okan yin mani idọti - ceto-darpaṇa-mārjanam (CC Antya 20.12) - afi t'okan yin ba moo, kosi besele ni oye nipa Hari, kini Oruko re je, bi irisi re seri, iru amuye wo loni, iru ise wo lonse. Kosi bosele yeyin.

Ataḥ śrī-kṛṣṇa-nāmādi na bhaved grāhyam indriyaiḥ (CC Madhya 17.136). Iye-ara iranu teni, teba lo gan, kosi besele ni oye nipa Krsna. Nitorina ni awon eyan o se ni oye nipa Krsna, awon eyan o de ni oye nipa iye hari-nama. nitoripe iye-ara wan o muno, o de tini idoti pelu awon amuye maya, kosi bonsele ni oye na. sugbon ona soso towa niyen - ceto-darpaṇa-mārjanaṁ bhava-mahā-dāvāgni-nirvāpaṇam (CC Antya 20.12). nitoripe egbudo ni iyasi mimo, gege na ona soso towa niyen. Ekorin Hare Krsna. Die die eyin na ma yasi mimo. Puṇya-śravaṇa-kīrtanaḥ. Puṇya-śravaṇa-kīrtanaḥ. Śṛṇvatāṁ sva-kathāḥ kṛṣṇaḥ puṇya-śravaṇa-kīrtanaḥ (SB 1.2.17). teba gbo, teba korin nipa Krsna, Uttamasloka, wanti sowipe, tad uttamaśloka-guṇopalambhakam, orisirisi anfaani lowa. gege na egbe imoye Krsna yi se pataki gan, gbogbo eyan loye ko mu isena ni pataki. Kīrtanīyaḥ sadā hariḥ.

tṛṇād api sunīcena
taror api sahiṣṇunā
amāninā mānadena
kīrtanīyaḥ sadā hariḥ
(CC Adi 17.31)

Ilana ti Caitanya Mahāprabhu niyen. O le gaan...padaṁ padaṁ yad vipadam (SB 10.14.58). Ninu ile aye yi vipada nikan lowa. Kosi sampada. sugbon lai rori wo awan ronu wipe " Nisin moti wa dada." kilo dara ninu aye yi? Ele daku laipe yi. Kilo dara? Sugbon awon eyan yitio l'ogbon ma sowipe, " Beeni, Mo dara gan." "E beere lowo awon eyan, " Bawo ni?" " Dada ni." Kini nkan to da nibe? Eledaaku ni oola. Osi da gan. Otan. Nkan ton sele niyen. gege na padaṁ padaṁ yad vi... wan se awon iwaadi sayensi lati ni idunnu, sugbon awon asiwere wanyi, wan o mo bonsele fi ipaari si iku. gege na kini nkan to da bayi? sugbon kos'opolo lori lati fi mo. Sugbon Krsna sowipe, " Awon isoro ti moni leleyi, Edakun sa. Eyin onisayensi, orisirisi nkan leyin donwo." Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi-duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). Ni alakoko kini isoro teni. Janma-mṛtyu-jarā-vyādhi. Egbudo ni ibimo, egbudo ku, egbudo ni awon aisan, egbudo darugbo. Efi ipaari si gbogbo eleyi na; lehin na ele soro nipa ilosiwaju ninu eto sayensi. Bibeko iranu ni gbogbo yin. Ese pupo.