YO/Prabhupada 0184 - E yi ife t'eni fun ohun ile aye yi si awon ohun mimo



Lecture on SB 3.26.47 -- Bombay, January 22, 1975

Ohun je nkan pataki. Ikan ninu awon idi fun ijiya wa ninu ile-aye ni ohun. gege bi awon ilu nla, wan ni'fe fun awon ohun ton jade lati ile sinima. iyen nikan ko, ati orisirisi nkan tawa n'gbo lati ori redio. Ifarafun awon ohun wanyi. nitoripe awon ohun latinu ile-aye yi lonje, oti so wa po sinu ile aye yi. Awon si feran lati gbo ohun awon oṣere obirin, ati awon sinima, wansi son to Ẹdegbaajo rupees fun orin kan soso. Wan po gan ni ilu Bombay. Gege na se leri aduru ifarafun awon ohun ile-aye yi tani. gege na, ifarafun kanna loje, taba fe gbo nipa Hare Krsna maha-mantra, ama ni ominiran, ohun kanna. Atinu aye ni ikan je, ikan ya si mimo. E gbiyanju lati ni ifarasi ohun mimo yi. Lehin na aye yin ma ni ilosiwaju.

ceto-darpaṇa-mārjanaṁ bhava-mahā-dāvāgni-nirvāpaṇaṁ
śreyaḥ-kairava-candrikā-vitaraṇaṁ vidyā-vadhū-jīvanam
ānandāmbudhi-vardhanaṁ prati-padaṁ pūrṇāmṛtāsvādanaṁ
sarvātma-snapanaṁ paraṁ vijayate śrī-kṛṣṇa-saṅkīrtanam
(CC Antya 20.12)

Gege na egbe imoye Krsna yi wa fun ise yi, pe " Eyin ti ni ifarasi awon ohun kan. Nisin afe ke fi yi ifarafun yi si awon ohun mimo. Lehin na ile-aye yin ma ni ilosiwaju." Egbe Hare Krsna yi nko awon eyan lati yi ifarafun ohun ile aye yi si awon ohun mimo. Narottama dasa Thakura ti korin, golokera prema-dhana, hari-nama-sankirtana, rati na janmilo more tay. Ohun ton ti ijoba orun wa, golokera prema-dhana, taba korin, ta gbo ohun yi, a le jeki ife wa si Olorun jisoke. Nkan ta fe niyen. Prema pum-artho mahan. Ninu ile-aye yi awa ti gba dharmartha-kama-moksa (SB 4.8.41) bi nkan to se pataki. Purusartha. Dharma, pe a d elesin, lehin na ale ni ilosiwaju ninu eto oro aje. Dhanam dehi, rupam dehi, yaso dehi, dehi dehi. Kama. Kinidi fun dehi? Nisin kama, lati yonju awon ife okan wa, Dharmartha-kama, lehin na toba ti rewa lati yonju awon nkan tafe, lehin a ma bere lati wa moksa, lati di'kan pelu Olorun. Awon merin ninu ile aye yi leleyi. sugbon ise mimo wa ni prema pum-artho mahan. lati niife fun Olorun, ipo to gaju niyen. Prema pum-artho mahan.

Latile de ipinnu ile-aye yi, prema pum-artho mahan, ninu asiko tawayi, Kali-yuga, nitoripe awa o le se nkan imi. O le gan. Asiko yi kun fun awon alebu. Ona abayo to wa ni, harer nama harer nama harer namaiva kevalam: (CC Adi 17.21) " Ekorin Hare Krsna mantra, " kevalam, " nikan soso." Kalau nasty eva nasty eva nasty eva gatir anyatha. Ninu Kali-yuga, ise tani ni basele jade kuro ninu idimu ile-aye yi... Bhutva bhutva praliyate (BG 8.19). Awon eyan o ni oye nipa nkan toje ibanuje wa. Krsna sowipe, " Awon ibanuje yin leleyi." KIlode? Janma-mrtyu-jara-vyadhi: (BG 13.9) " Iyika ninu ibimo ati iku. ibanuje ile aye yin niyen." Kilehin ro nipa iru isoro wanyi tabi ikeji? FUn igba die nigbogbo wan wa fun. Gbogbo wan wa labe ofin iseda ile aye yi. Kosi besele jade kuro. Prakrteh kriyamanani gunaih karmani sarvasah (BG 3.27). Prakrti a tiyin lati se awon nkan nitoripe awon ipo aye yi ti jeke doti. Nitorina egbudo sise labe ilana prakrti, iseda ile-aye yi. Teyin ba wa labe iseda ile-aye yi, egbudo gba ibimo, iku, ojo arugbo at'aisan. Ibanuje teyin ni leleyi.