YO/Prabhupada 0189 - Efi awon Olufokansi lori awon guna meta



Lecture on SB 6.1.46 -- San Diego, July 27, 1975

Kosi besefe yi awon ofin iseda pada. Ija lati wa laaye: Awa fe ni idari lori awon ofin ile aye. Kolese se. Daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā duratyayā (BG 7.14). Awon eto toye ka wo leleyi. KIlode t'awon eyan kan ni idunnu tabi ibanuje? Nitori awon amuye wanyi. "ninju aye tawayi, fun iwonba orisirisi ni awon eda yi ma wa fun, gege na, guṇa-vaicitryāt, pelu awon orisirisi nkan lati guna, guṇa-vaicitryāt," tathānyatrānumīyate. Itumo Anyatra ni aye atunwa, tabi isogbe to kan, tabi ounkoun to ba tele. Gbogbo nkan lo wa labe idari yi. Traiguṇya-viṣayā vedā nistraiguṇyo bhavārjuna. Krsna ti fun Arjuna ni imọran pe " gbogbo agbaye yi lowa labe awon guna meta wanyi," guṇa-vaicitryāt. " Nitorina oye kodi nistraiguṇya, ibi ti awon guna meta yi o le sise." Nistraiguṇyo bhavārjuna. Bawo lesele fi ipaari si ise awon guna meta wanyi? Wanti salaaye ninu Bhagavad-gita:

māṁ ca vyabhicāriṇi
bhakti-yogena yaḥ sevate
sa guṇān samatītyaitān
brahma-bhūyāya kalpate
(BG 14.26)

Teba n'se ise ifarafun Oluwa laisi ipaari lehin na ele lroi awon guna meta wanyi. Gege na egbe imoye Krsna wa lati jeki awon elesin wa lori awon guna meta. Gege bi okun, teba subu sinu okun, nkan alebu gidi gan niyen. Sugbon telomi ba wa gbe yin jade kuro ninu omi okun yin tewa lori omi na, ko si nkankan lati beru nibe. Aye yi tini'gbala.

Nkan tawa fe niyen, guṇa-vaicitryāt, teba fun ara yin ni'gbala lati gbogbo awon orisirisi eda ninu ile-aye yi, ibimo, iku, ojo-arugbo ati aisan, ke gba orisirisi eda ninu aye yi... Gege beyin se sowipe oni awon igi kan ni ilu California ton gbe fun odun marun ẹgbẹrun. Iru eda imi tun niyen. Awon eyan si fe gbe fun aimoye odun. Pelu ilana iseda, igi wa ton gbe fun marun ẹgbẹrun odun. Se iru aye yi dara funyin, ke duro sibi kan fun marun ẹgbẹrun odun ninu igbo? gege kosi ikankan ninu awon orisirisi eda ninu aye yi to da, boya eje orisa tabi igi tabi teleyi tabi toun. Ikeko leleyi. Ikeko leleyi. Gege na ogbudo yewa pe, gbogbo eda ninu aye yi ni isoro ton daamu wan, koo ba je awon orisa tabi aja gan. Awon orisa gan ni isoro to po, ni opolopo igba wan lo ba Olorun. gege na nibi alebu ma wa nigbogbo igba. Padaṁ padaṁ yad vipadām (SB 10.14.58)). Ilokulo asiko wa loje taba fe yo gbogbo alebu inu ile aye yi kuro. Kolese se. Gege bi orisirisi ara eda wa, orisirisi alebu lowa, lati ikan si keji... Gege na nkan to daju ni lati fi ipaari si gbogbo nkan aye yi. Awujo Veda niyen. Lori anfaani yi lon se awujo Veda, " E fi ipaari si ise iranu wanyi, iyika ibimo, iku ojo arugbo." Nitorina Krsna sowipe, janma-mṛtyu-jarā-vyādhi duḥkha-doṣānudarśanam (BG 13.9). Imoye niyen. Iru imoye wo, se imoye nipa ise ero, iru imoye wo? Kosi besele fi ipaari si awon nkan bayi. Nitorina ise gidi tani latise ni basele fi ipaari si. sugbon nitoripe awon eyan yi o l'ogbon, wan rowipe " Kosi basele fi ipaari si awon nkan wanyi. Ejeka tesiwaju pelu eto iyika ninu ibimo ati iku yi, ninu gbogbo aye taba wa ejeka ma tiraka lati gbe ninu aye na." Awujo ile-aye yi niyen, aimokan, kosi imoye kankan.

Bhagavan Sri Krsna ti funwa ni imoye na " Ona abayo to wa leleyi: janma karma ca me divyaṁ yo janati tattvataḥ, tyaktvā dehaṁ punar janma naiti (BG 4.9)." Isoro to wa ni, punar janma, iyika ninu ibimo, teba fe fi ipaari si, e gbiyanju lati ni oye nipa Krsna. Lehin na ele fi ipaari si. Lesekese teba ni oye nipa Krsna... Teba fe ni oye nipa Krsna, kosi nkankan to baje teba kan tele gan lai rori wo. Krsna ti sofun wa pe, oun ni Olorun to gaju. Egbudo gba be. Otan. Teba ni igbagbo pe " Krsna ni Olorun gbogbo eda." Iyen nikan gan tito lati funyin ni ilosiwaju gan. Sugbon o le gan fun awon eyan to n feran awon nkan aye yi. Nitorina ni Krsna se sowipe, bahūnāṁ janmanām ante: (BG 7.19) " lehin aimoye ibimo, " bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate, "jñānavān, eyan to ba gbon, a teriba fun Krsna." Bibeko, na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ prapadyante narādhamāh: (BG 7.15) " Bibeko o le wa bi asiwere ninu gbogbo ese yi, bi awon eyan t'opolo wa ti lo." Na māṁ prapadyante: " Kole teriba fun Krsna."