YO/Prabhupada 0197 - Egbudo salaaye nipa Bhagavad-gita gege boseje



Lecture on SB 5.5.30 -- Vrndavana, November 17, 1976

Teba gbiyanju, Krsna ma fun yin l'agbara. Krsna ma fun yin ni iranlowo, teba fe gba iranlowo na. O wa n'be. Oti wa lati ran yin lowo. Bibeko kini iwulo pe Krsna wa sibi ton sowipe, sarva-dharmān parityajya mām ekam (BG 18.66)? Fun anfaani wa loje. teba teriba fun Krsna tabi rara, Ko kan Krsna. Kon sepe Krsna gbarale ise teyin se fun. Osi pe ninu ara re. Ni iseju kan o le da aimoye awon iranse sile. Kilode to se fe ise yin? Kilode to sen bere fun ise yin? Kon sepe osi fe ke sise fun titi lo bayi. Sugbon teba teriba fun, awulo fun yin. Fun dida tiyin lowa. Krsna fe ke teriba fun, ke yasi momi, ke bale pada si ijoba orun. Ise apinfunni Krsna niyen. Gege na egbe imoye Krsna yi, ise kanna loni: lati pe awon eyan jo.

dante nidhāya tṛṇakaṁ padayor nipatya
(sic) kāku-śatam kṛtvā cāhaṁ bravīmi
he sādhavaḥ sakalam eva vihāya dūrād
caitanya-candra-caraṇe kurutānurāgam

Iṣẹ apinfunni wa niyen. iṣẹ apinfunni ti Caitanya Mahaprabhu na. kilode ti Prabodhananda Sarasvatī sen bere, caitanya-candra-caraṇe kurutānurāgam: " E kon foju si ise Caitanya? " Nitoripe Krsna loje fun ara re, osi ti wa ko wa basele summon Krsna. Caitanya leleyi. Kṛṣṇaya kṛṣṇa-caitanya-namne gaura-tviṣe namaḥ. O tiye Śrīla Rūpa Gosvāmī, O de ti ye Sārvabhauma Bhaṭṭācārya.

vairāgya vidyā-nija-bhakti-yoga-
śikṣārtham ekaḥ puruṣaḥ purāṇaḥ
śrī-kṛṣṇa-caitanya-śarīra-dhārī
kṛpāmbudhir yas tam ahaṁ prapadye
(CC Madhya 6.254)

Taba ni oye nipa Krsna lati Caitanya Mahaprabhu... Caitanya Mahaprabhu sowipe " Teba le di guru." Bawo? Yāre dekha, tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa (CC Madhya 7.128). Ema yipada, ema baaje. E gbiyanju lati se iwaasu lori nkan ti Krsna ti so. Ilana Caitanya Mahaprabhu niyen. E tele awon ilana wanyi... Ema fi nkankan kun, ema yipada pelu ogbon iranu teni. Iru nkan bayi o le ran yin lowo. Egbudo salaaye nipa Bhagavad-gita gege boseje. Yāre dekha, tāre kaha 'kṛṣṇa'-upadeśa. gbogbo nkan wanbe, o si rorun gan, tabi tele ilana parampara.

Gege na agbudo ti egbe imoye Krsna yi siwaju sugobn agbudo resile gan.

tṛṇād api sunīcena
taror api sahiṣṇunā
amāninā mānadena
kīrtanīyaḥ sadā hariḥ
(CC Adi 17.31)

Kīrtanīya. kirtan nitumo iwaasu yi, kon se pelu mrdanga nikan, ale ni kirtana olorin. Rara. Kirtana na ni iwaasu je. Abhavad vaiyāsaki-kīrtane. Vaiyāsaki, omo-okurin Vyāsadeva, Śukadeva Gosvāmī, o kan salaaye nipa Śrīmad-Bhāgavatam lehin na ile-aye re si di pipe. Abhavad vaiyāsaki-kīrtane. Śrī-viṣṇu-śravaṇe parīkṣit. Parīkṣit Mahārāja kon gbo; lehin na oun na di pipe. Śukadeva Gosvāmī de salaaye. Kirtana na niyen je. Gege na kirtan na leleyi. Bi Prabodhānanda Sarasvatī se ko wa, he sādhavaḥ sakalam eva vihāya dūrād caitanya-candra-caraṇe kurutānurāgam: " Sadhu leyin je, eyan to dara gan, sugbon ibeere kan ti moni niwipe." Iresile leleyi, Teba sowipe karmi leje, mudha leje..." Amowipe mudha loje, sugbon ema so bayi fun ni'bere, teba so bayi, koni fun yin laaye lati soro mo. Mudha loje, kosejo.. Ton sise bi elede ati aja, laata ar d'aale fun igbadun, gege na mudha, karmi. Gege na jnani, wan so isokuso. Owe kan wa, kākā-taliya nyāya: se nitoripe eye kuroo joko lori igi ọpẹ lose wolule? Tabi igi ọpẹ na wolule nitoripe; nitorina ni eye kuroo o sele joko le? Ogbon ori. pandita ko sowipe, " Rara, rara. L'alakoko igi ọpẹ yi wo lule, eye kuroo si fe joko le sugbon kole se." pandita imi sowipe, Rara, rara. igi ọpẹ yi wan'be sugbon nitoripe eye kuroo yi joko nitorina lose wo lule." Ejo ogbon ori leleyi je. Wan kon lo asiko wan ni ilokulo. Kākā-taliya nyāya. Kupa-manduka-nyāya.