YO/Prabhupada 0207 - Ema huwa kuwa



Lecture on SB 6.1.16 -- Denver, June 29, 1975

Awan saalaye ilana lati se Ìpalẹ̀mọ́ ninun aye wa orisirisi awọn ọna prāyaścitta ati tapasya lati saalaye Ati saalaye ọna kevalayā bhakta ọna Bhakti ni ohun gbogbo -karma, jñāna, yoga. A ti saaalaye pe ti eyan ba se ibaramusi tabi ko gba ona mi oṣeeṣe pe o le ni aseyori, O de le se ai-ṣaṣeyọri Sugbon ti awa ba gba s'okan ona yi, Ona ifarafun iṣẹ t'Oluwa o jo wa loju pe a ma se aseyori Itumo nivṛtti-mārga ni Ona ipalemo aye wa Gege na itumo pravṛtti-mārga ni wi pe l'aisi imo awon ona won yi eyan o le te si iwaju. Ti eyan ba de se nkan to ba fe ona pravṛtti-mārga ni ye Opolopo awon eyan feran ona pravṛtti-mārga. nipataki ni aya isin, awon eyan o ni abojuto nipa nkan to ba ma sele Nitorina o si te won lorun lati ronu pe ko si aye lẹhin iku Won so wipe "E je ka si gbadun aye tawa yi" Lehin na ti iku ba de, e ma si se afani nkan to ba ma sele Ni alakoko won kọ lati ni igbabo ni aye tókàn Wan si so wipe ko kan won ti aye atun tie wa, bo ba tie je pe wa tun wa sinu aye yi bi awọn ologbo tabi aja. Iriri aye isin. Aye iwakuwa.

Sugbon ninu egbe wa t'imo Oluwa asin ko awon eyan pe e ma si se gbe ninu aye yi. fun apẹẹrẹ eyan le so wi pe "Ko si aye" Sugbon ti mo ba so wi pe "Aye nbe" Sugbon ipeere le leeyi, nitoripe opolopo awon lo ni aimokan wan o mo bo ya aye nbe tabi ko s'aye. gbogbo yin sin jiyan pe ko s'aye, sugbon eyin o mo boya aye nbe. O ye ke ro wo eyin so wipe ko s'aye rara. Teba tie gba nkon ti mo so wi pe "aye n'be" Ko si da yin loju bo ya aye nbe. awa so wipe aye n'be gege bi omode ti gba aye tuntun Omode na le so wi pe "ko si aye atunwa" Sugbon ko si otitọ ninu oro yi Otito to wa ni pe, aye n'be. omode naa asi d'agba bo ba ya to ba ya omode naa a di omo oukurin. otito ni eyi je sugbon ema si leri fun nkan nkan.. Sugbon na e si wo, to ba je wi pe aye n'be kilowade te fin gbe aye radarada E si bu fun apeere, ti omode o ba fe ke eko To ban rou pe, ko si aye atunwa, ma kon sere. kilode te fe kin lo si ile -iwe? O le ronu bayi, sugbon ti ko ba ke eko to ba ti dagba o ma jiya gan. Nitoripe aye iranu lo gbe ti gba to kere.

Nigbana ka to le gbe aye atunwa, agbudo ni ipalemo gbogbo ese ninu aye wa bibẹkọ awa o le ni aye atunwa to dara nipataki ta ba fe pa da lo si Orun, agbudo fi ipari si gbo ese ti awan se ninu aye yi Ninu iwe mimo Bhagavad-gītā, e ma ri wi pe

yeṣām tv anta-gataṁ pāpaṁ
janānāṁ puṇya-karmaṇāṁ
te dvandva-moha-nirmuktā
bhajante māṁ dṛḍha-vratāḥ
(BG 7.28)

Lati di elesin to nigbagbo Kṛṣṇa, (Oluwa) Agbudo fi ipari si gbogbo ese to wa ninu aye wa Yeṣām anta-gataṁ pāpam. awa o gbudo se awon nkan to ma gbe ese sinu aye wa To ba de fi ipari si ese ninu ayere, gbogbo ese to ti se tele asi ni idariji Ko ni jiya mo fun awon ese ti tele mo. Yeṣām tu anta-gataṁ pāpaṁ janānāṁ puṇya-karmaṇām. O de daju pe awon eyan se isekuse tabi wan se nkan to dara Awon eyan mi de wa ti wan ti jiya ton fun isekuse to se sugbon lakoko tawayi, wan se awon ise to dara yeṣāṁ tu anta-gataṁ pāpaṁ janānāṁ puṇya-karmaṇām, te, iru awon eyan ba yi dvandva-moha-nirmuktā, laisi iṣiyemeji, O daju pe wan pa da si Orun. bhajante māṁ dṛḍha-vratāḥ. Eyi je esi fun awon to ba gba so kan ise Oluwa pelu idaju ati ifarafun Awon eyan ba won yi ti bo lowo ese.