YO/Prabhupada 0214 - Teba sise yin bi olufokansi, egbe wa ma ni ilosiwaju



Room Conversation 1 -- July 6, 1976, Washington, D.C.

Prabhupāda: Ni Orile-ede India awa si ni ilẹto po sugbon ko si awon eyan lati toju re.

Svarūpa Dāmodara: Mo se gba lẹta lati ọmọ ẹgbẹ wa Kulavida Singh Okurin na si ni aájò pe awon omo aye isin won ti ni ifura fun gbogbo nkan to papo pelu ẹsin Nitorina Okurin yi fe da ile-eko

Prabhupāda: àgbo ákò ti Vivekananda ti da ni yen, yato mata tato patha

Svarūpa Dāmodara: Wan fe da egbe ISKCON ni be..

Prabhupāda: Mi oro pe a rorun... Ilu Manipur....

Svarūpa Dāmodara: A rorun nitoripe..

Prabhupāda: ...Vaiṣṇava Ton ba de ni oye, o ma da gan

Svarūpa Dāmodara: awon ijọba gan ti beere pe se wan le fun wan ni ile ka beere egbe wa

Prabhupāda: Beeni. ile Ọlọrun Govindaji ni yen?

Svarūpa Dāmodara: ijọba ti di oniwunfun ile-Olorun Govindaji

Prabhupāda: Ijoba, wan o le fo ju to.

Svarūpa Dāmodara: wan gbiyanju.

Prabhupāda: Wan o le se lesekese ti gbogbo nkan ba ti di t'ijoba gege bi Orile-ede India, O ti baje ni yen Ole ni awon ton wa ni ijoba. Bawo lon le se? Wan kan ba gbogbo nkan je. Ko si bon se le se. Wan kin se elesin. Awon elesin lon ye kan toju ile-Olorun Awon ton gba si ise ni be, owo nikan lon wa Bawo lon se fe toju ile-Olorun. a soro lati se.

Svarūpa Dāmodara: adi isoro ti oṣelu.

Prabhupāda: Otan ni yen

Svarūpa Dāmodara: Ti isori ijoba ba wo inu re, iyen o ni nkankan lati se pelu adura

Prabhupāda: Nitorina ni mo so wi pe o ye k'ijba fun awon elesin ni ile-Olorun yi. Awon eyan mo wa pe elesin ni gbogbo wa ni ISKCON ton ba fe toju be.... Awa ni ile-Olorun to po t'awan to ju, pelu awon elesin awon to gba bi ise fun owo, eyan bayi a soro lati le toju

Elesin: rara.

Prabhupāda: Ko si bon se le se Egbe wa a se aseyori afi gbogbo wa ba di elesin, bibeko o ma tan. elo mi o le se fun wa. rara awon elesin ni kan. aṣiri to wa ni yen

Elesin: Se iyen wi pe awa o le son owo fun elesin?

Prabhupāda: Eh?

Elesin: Awa o le fo wo ra elesin

Prabhupāda: ko le se se.

Elesin: Eyan le son owow fun eni to ma gba le sugbon lati fo wo ra aalufa, iyen soro

Prabhupāda: ko le se se. Afi ti aw ba je elesin, nigbana ni egeb wa ma se aseyori

Elesin: Oye ki awon elesin gba ijoba gbogbo aye.

Prabhupāda: nkan to da fun aye ni yen.

Elesin: beeni

Prabhupāda: tin awon elesin ba gba ijoba gbogbo aye, inu gbogbo eyan ma dun, nitoripe ikan ti Oluwa fe niye O fe ki awon Pandava gba ijoba Nitorina ouna si da wo si ija laarin wan Oye kon pa gbo awon Kaurava, ke si fi ijoba fun Mahārāja Yudhiṣṭhira Knan to se ni yen. Dharma-saṁsthāpanārthāya. Paritrāṇāya sādhūnāṁ vināśāya ca duṣkṛtām (BG 4.8). O fe ki aye rorun fun gbogbo eyan ki awon si ni fe Oluwa gege na aye won a dara. ètò Oluwa (Krsna) ni yen awon asiwere wonyi si ni ara eyan sugbon won lo niilokulo Nitorina mo si beere nigba kan " kini iwulo ominira? se ka ma jo bi aja? aye wan ti daru gege na ni aye atunwa wan si di aja.... Kini iwulo gbogbo ile-giga fun awon to ma di aja ni aye atunwa ka si wo pe gbogbo awon ton ko ile-giga wonyi ni aye atun wa fun wan gbogbo wan ma di aja

Svarūpa Dāmodara: sugbon awon eyan o mo pe ni aye atun wa won ma di aja

Prabhupāda: Isoro to wa ni yen. Ko ye won. Nitorina maya