YO/Prabhupada 0216 - Eyan pataki ni Krishna je, gege bi awon olufokansi re na



Lecture on SB 1.7.47-48 -- Vrndavana, October 6, 1976

iwa Vaiṣṇava ni ye. Para-duḥkha-duḥkhī. Para-duḥkha-duḥkhī ni awon Vaisnava je idayatọ ti Vaiṣṇava ni ye. Ko si ni idààmú fun awon isoro aye re Sugbon isoro to po gan lo je fun to ba ri elo mi to ni idààmú Prahlāda Mahārāja so wi pe

naivodvije para duratyaya-vaitaraṇyās
tvad-vīrya-gāyana-mahāmṛta-magna-cittaḥ
śoce tato vimukha-cetasa indriyārtha-
māyā-sukhāya bharam udvahato vimūḍhān
(SB 7.9.43)

Baba Prahlāda Mahārāja si fun ni isoro to po gan, sugbon wan si pa baba re Sugbon nigbati Nṛsiṁha-deva fun ni ibukun, ko si gba. O so wi pe, sa vai vaṇik. Oluwa mi, awa si ti ni ibimo ninu ebi to to ni rajo-guṇa, tamo-guṇa Rajo-guṇa, tamo-guṇa. awon Asura( emi esu) ni àmúyẹ meji ti o da, rajo-guṇa ati tamo-guṇa sugbon awon ton pe ni devatas(angeli) won ni àmúyẹ sattva-guna.

àmúyẹ meta lo wa ni ile-aye yi. Sattva-guṇa... Tri-guṇamayī. Daivī hy eṣā guṇamayī (BG 7.14). Guṇamayī, triguṇamayī Ni ile-aye yi, sattva-guṇa, rajo-guṇa, tamo-guṇa Awon eyan ton ni àmúyẹ t'alakoko ton pe ni sattva-guna. Awon eyan to dara ni awon yi. pe won dara, di dara ti aye yi lo je na Kon se bi ti Orun, di dara t'Orun yato si ti ile-aye yi nirguna lo je, itumo ni wi pe ko si awon àmúyẹ t'ile-aye yi ni Orun Ko soro àmúyẹ , t'alakoko, tabi, ikeji, tabi iketa. Gbogbo eyan to wa L;Orun won ni àmúyẹ to dara, t'alakoko. àmúyẹ Krsna t'alakoko lo je gege bi awon elesin re. àmúyẹ t'alakoko ni awon igi, ẹyẹ, maalu, ati mom-maalu ni Nitorina a wa so wi pe ojúlówó Ko sooro t'alakoko, ti'keji, ti'keta, ti'kerin. rara. T'alakoko ni gbogbo nkan je Ānanda-cinmaya-rasa-pratibhāvitābhiḥ (Bs. 5.37) Gbogbo nkan aye yi ānanda-cinmaya-rasa ni won je Ko soro ìṣàsọ́tọ̀. boya eyan wa ni dasya-rasa tabi owa ni sakhya-rasa tabi ko wa ni vatsalya-rasa tabi madhurya-rasa, nkan na ni gbogbo wan je Ko soro ìṣàsọ́tọ̀. Sugbon a gbudo ni orisirisi nkan eyin feran rasa yi, emi feran ikeji, nkan to da ni yen.

Sugbon ninu ile-aye yi awon ni amuye meta ta so gege na Prahlāda Mahārāja, to je omo Hiraṇyakaśipu O ronu pe, oun na ni awon amuye rajo-guna at tamo-guna Vaisnava lo je, O ti ko ja gbogbo awon auye ay yi, sugbon eyan to ba je Vaisnava ko gbudo ni igberaga amuye re. ko de ni ro pe oun ti ni ilọsiwaju ju awon eyoku lo, tabi oun ti ni oye ju awon eyoku lo Gbogbo igba lon ronu pe, " emi ni mo kere ju"

tṛṇād api sunīcena
taror api sahiṣṇunā
amāninā mānadena
kīrtanīyaḥ sadā hariḥ
(CC Adi 17.31)

Vaisnava ni eyan bayi je.