YO/Prabhupada 0221 - Awon Mayavadis, wan rope wanti di nkankanna pelu Olorun



Janmastami Lord Sri Krsna's Appearance Day -- Bhagavad-gita 7.5 Lecture -- Vrndavana, August 11, 1974

Nigbati Arjun beere lowo Krsna.. " E so wi pe imoye to wa ninu iwe-mimo Bhagavad-gītā pe eyin le ko Akunlebo-oorun. Bawo le fe kin gba bi oto ooro? -idaaun na ni wi pe " Awa meejeji si wan be, sugbon O ti gbagbe. Mo si ranti.

Iyato Laarin Krsna ati awon eda ni yen Odindin ni Oluwa, sugbon awa Oto be. Iwonba kekere la je si Oluwa. Nitorina agbudo wa labe ṣakoso Krsna Taba ko lati gba ilana Krsna , gege na ama gba ti ile-aye. bhūmir āpo 'nalo vāyuḥ (BG 7.4). pàápàá be, atinu agbara mimo lati ja de. O ye ka gba ki Oluwa si fun wa ni ilana lai s'agidi Ise ifarafun Oluwa ni yen. Ise ifarafun Oluwa ni yen atinu agbara mimo lati ja de. Emi mimo ni Krsna je beena ta gba lati tele ilana Krsna, awa O si ni Igbega si Ile-Olorun sugon ta ba gba nikan. Krsna ooni ti wa lati se nkan ti awa o ba fe Yathecchasi tathā kuru (BG 18.63). Krsna si so fun Arjuna " Se nkan to ba fe." Eyi je ominira ta ni.

Lati ominira ta ni yi, asi ti lo ni ilokulo. nitorina lase wa sinu aye yi Krsna si ti fun wa ni ominira lati se nkan to ba wun wa nkan ta den se ni ye sugbon abajade ibe ni wi pe awa o si ni isoro Ati ni ominira lati se nkan to ba wun wa ni aye yi gbogbo eyan s'aafani lati di Oga aye ta wa Koseni ton se aanfani a ti di iranse awon Vaisnava nikan lon se anfaani ati di iranse Awon karmis ati jnanis, won o feran ati di iranse wan si ba wa yi pe awa Vaisnava a ni ironu ẹru Beeni. Caitanya Mahāprabhu ti ko wa be gopī-bhartuḥ pada-kamalayor dāsa-dāsānudāsaḥ (CC Madhya 13.80) Ipo wa ni yen Kini iwulo pe an s'aanfani " Oga ni mo je" To ba je pe Oga ni mo je, ki wa ni iwulo afëfë Mo ti di iranse akoko ooru . Gege na mo ma di iranse otutu ni akoko otutu.

Nitorina iranse la je. Caitanya Mahāprabhu so wi pe, jīvera svarūpa haya nitya-kṛṣṇa-dāsa (Cc. Madhya 20.108-109). Ipo to ye wa ni ti Iranse Krsna. Krsna ni Oga wa Egbe imoye Krsna wa fun kiko awon asiwere won yi.. Emi ko ni mo so won ni asiwere..Krsna lo so wan bayi Na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ prapadyante narādhamāḥ (BG 7.15). Oun lo so be. itumo Duṣkṛtinaḥ, ni eyan ton se ẹṣẹ, ati mūḍhāḥ, awon asiwere itumo Narādhamāḥ, ni awon eyan ti oni iwulo Eyin soro ni pa awon oni sayensi awon akeko imoye po gan. sugbon se narādhamāḥ ni gbogbo wan je?" Beeni. narādhamāḥ ni won. sugbon won ni akeko Sugbon iru akeko wo lon ni? Māyayā apahṛta-jñānāḥ: Esi akeko wan maya ti muloo Bi eyan se keeko si, gege na ni okan re asi yi kuro ni Oluwa.

Lasiko ta wayi..... Itumo akeko ni wi pe agbudo ni Oye..Jñānī. itumo akeko ni Okurin to logbon, Jñānī. Sugbon itumo Jñānī to da ju ni prapadyate. Bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate (BG 7.19). Akeko gidi ni eyi je Pe adi alaigbagbọ pe ọlọrun wa oun eleyi o kin se itumo akeko. "Ko si Olorun", "Olorun ni mi, tabi Olorun ni wo" Akeko ko leleyi. ajñāna ni eyi je Awon Māyāvādīs won ro pe awon ti si nkannkan na pelu Olorun. Akeko ko le yi.