YO/Prabhupada 0236 - Awon Brahmana, awon Sannyasi wanle toro je sugbon awon Kshatriya ati Vaishya won ogbudo se bee



Lecture on BG 2.4-5 -- London, August 5, 1973

Nitorina Caitanya Mahāprabhu ti so wi pe viṣayīra anna khāile malīna haya mana (CC Antya 6.278). awon eyan pataki yi si ni isoro nitoripe wan gba owo lodo wan ti mo ba gba owo lowo eyan to ni ife aye yi ju, emi na abeere lati wu iwa bi eyan na Ma ni ife awon nkan aye yi Caitanya Mahāprabhu ti kiloo fun wa pe elesin ko ni awon viṣayī, ema gba nkankan lati odo wan nitorina awon brāhmaṇa ati Vaiṣṇava, wan kin gba owo lowo awon eyan Wan le gba bhikṣā. Śreyo bhoktuṁ bhaikṣyam apīha loke (BG 2.5). Sugbon ti eyan ba ni ife awon nka aye ema gba bhiksa lowo eyan na Sugbon awon brahmana tabi sannyasi le gba bhiksa nitorina Arjuna so wipe, dipo ta ma fi iku pa awon eyan pataki bayi, mahānubhāvān..." gege na bhaiksyam. awon brahmana ti sannyasi le toro je, sugbon ksatriya ati vaisya wan o gbudo toro je Ksatriya ni Arjuna je O si so wi pe, a dara tin ba bere ise brahmana dipo ti ma fi ma gbadun ninu ijoba ti mo gba lehin tin ba fi iku pa guru mi, ma toro kaakiri èròńgbà to wa lo okan re ni yen gege na itanran-ẹni ti mu Arjuna, nitorina O ti gbagbe ise to ye ko se Gege bi Ksatriya to je, jagujagun ni ise re. Ko ba je pe omo re gan lo ma ba ja Eyan to je ksatriya ko ni ṣiyemeji to ba ni lati fi iku pa Omo re, ti omo na ba nípàlaára gege na ti baba ba nípàlaára, omo re ko ni ṣiyemeji lati fi iku pa Ise aironu wo ti awon ksatriya leleyi Ksatriya o gbudo ṣiyemeji Nitorina Krsna si so fun wi pe " O ti di ojo " Lehin na Krsna saalaye awon ilana mimo fun ìtàkurọ̀sọ laarin awon ore meeji leleyi je.

O to bee. Ese pupo.