YO/Prabhupada 0243 - Oye ki akeko loba Guru toba fe ni ilaju okan



Lecture on BG 2.9 -- London, August 15, 1973

Pradyumna: Itumo, Sanjaya so wi pe, gege na Arjuna, jagunjagun to le ba awon Ota re wi, so fun Krsna Govinda, mi o le ja. O si daake

Prabhupāda: ni ẹsẹ-iwe kehin, Arjuna so wi pe " Ko si ere ninu ogun yi, nitoripe gbogbo awon eyan to wa ni apa keeji ebi lon je si mi Tin ba de pa wan, ti mo di olusegun. Kini iwulo? Mo ti saalaye tele pe iru iwa bayi lati aimokan loti wa Ko si ogbon ninu e evam uktvā, O si so wi pe ko ere ninu Ogun na Evam uktvā, itumo hṛṣīkeśam ni Olori iye-ara ni ese-iwe to kehi, o si so wipe, śiṣyas te 'haṁ prapannam: (BG 2.7) " Akeko re ni mo je" Krsna ti di guru, Arjuna de ti Akeko teletele wan soro bi awon ore. Sugbon eyan o leri esi to da ninu orosisi laarin awon ore Ti oro to se pataki wa lati so, laarin awon olori lo ye kan so.

Mo ti saalaye teletele itumo Hṛṣīka ni iye-ara. Oga si ni itumo īśa Hṛṣīka-īśa, papo lo di : Hṛṣīkeśa. Gege na, Guḍāka īśa. okunkun ni itumo Guḍāka.. aimokan ni itumo okunkun

ajñāna-timirāndhasya
jñānāñjana-śalākayā
cakṣur-unmīlitaṁ yena
tasmai śrī-guruve namaḥ

Akeko ni lati lo ba Oluko to ba fe ni oye. Asiwere ni gbogbo eyan ni aye yi Awon Eda eyan gan, nitoripe ati itankalẹ awon eranko lati wa gege lati kekere, awan na ni aimokan bi awon eranko Nitorina, gbogbo eyan gbudo ni eko, botieje eda eyan eyan o le fun awon eranko ni eko, sugbon awon eda eyan le gba eko nitorina sastra so wipe nāyaṁ deho deha-bhājāṁ nṛloke kaṣṭān kāmān arhate vid-bhujāṁ ye (SB 5.5.1). L'opolopo asiko ni moti ka akọsori ese-iwe yi.... Ninu igbese aye to kere ju ti awonn eda eyan lo, agbudo si ise gan fun awon koṣeemani merin won yi: ka jeun, ka sun, ka se asepo t'okurin ati t'obirin, ka si gbeja ara wa Igbadun ni idi gbogbo eleyi, Nitorina ni gbogbo eyan sen se ise sugbon ni ara eda eyan krsna ti fun wa ni opolo Asi le toju ara wa gan sugbon pelu idi lati ni oye Krsna Eyan gbudo toju ara re, sugbon ema gbe ile-aye yi bi awon eranko, ti o mu ju igbadun gbogbo ise ti awon eday eyan se wa fun igbadun ara wan asise ilajo ti ojo eni ni yen Yuktāhāra-vihāraś ca yogo bhavati siddhiḥ. Bhagavad-gita so wi pe yuktāhāra. Beeni, eyan gbudo jeun, eyan gbudo sun, eyan gbudo se idaraya, eyan gbudo gbeja ara re.. sugbon ema je ki gbogbo eleyi ni iyipada lori akiyesi yin Agbudo jeun, yuktāhāra.. Oto oroo niyen. sugbon kon se atyāhara. Rūpa Gosvāmī ti saalaye ninu iwe re Upadeśāmṛta

atyāhāraḥ prayāsaś ca
prajalpo niyamagrahaḥ
laulyaṁ jana-saṅgaś ca
ṣaḍbhir bhaktir vinaśyati
(NOI 2)

Ti eyan ba fe ni ilosiwaju ninu awon nkan mimo- gege bi eleyi se je idi igbese aye wa Ko gbudo jeun ju, atyāhāraḥ, tabi ko toju nkan ju bo se ye Atyāhāraḥ prayāsaś ca prajalpo niyamagrahaḥ. Imoye wa ni yen