YO/Prabhupada 0258 - Niotooro, iranse laje



Lecture -- Seattle, September 27, 1968

Ese-iwe Bengali to da niyen:

kṛṣṇa bhuliya jīva bhoga vāñchā kare
pāsate māyā tāre jāpaṭiyā dhare

Lesekese ti imoye wa bayikajẹ pelu igbadun ile-aye yi pe " Mo fe di Oga ninu ile-aye yi" Lesekese taba bere sini ronu bayi, isoro ma wa māyā. iru imoye bayi pe " mo le gbadun ara mi, bimo se fe... Gbogbo eyan loni iru anfanni bayi Gbogbo wa, lati kokoro to kereju de eda to gaju Brahma, gbogbo eyan lo fe di Olori gege bi Orile-ede yin, opolopo awon eyan lon fe di Olori Orile-ede yin Kilode? èrò kanna ni. Gbogbo eyan fe di olori maya Egbe imoye krsna wa yato si gbogbo eleyi Anfani tani ni basale di iranse awon iranse Krsna idakeji lo je, awa fe di iranse Olorun, awon eyan di Olori Gopī-bhartuḥ pada-kamalayor dāsa-dāsānudāsaḥ (CC Madhya 13.80).

Ni aye isin awon ma sowipe ironu eru lawani Otooro ni. " kilode ti eyan a fe d'eru? Mofe d'Oga sugbon awon eyan o mope gbogbo isoro aye wan lati ironu pe wan fe d'oga loti wa Wan gbudo ni oye iwaasu wa Nitoripe latibeere iranse Oluwa ni gbogbo wa je ni anfanni pe afe d'Oga gbogbo wa to di Eru si iye-ara wa nitoripe iranse ni wa, koseni to le gbe laise nkan gbogbo wa ta joko si ipade yi, iranse la je Awon omo-okurin wanyi ton ti fun aye wan si imoye Krsna, gbogbo wan ti di iranse Krsna isoro aye wan titan sugbon awo iyoku ton ronu pe, "kilode ti ma se di iranse Olorun tabi swamiji? Mofe d'Oga.. Sugbon ni otooro ko le se se Iranse iye-ara re lo je. Otan. eje ko ye yin Asi di iranse fun ifẹkufẹ toni iranse imọtara re, iranse ibinu re, pelu awon nkan to po Kāmādīnāṁ kati na katidhā pālitā durnideśāḥ. Ni ijoba, enikan ni lati di iranse gbogbo agbaye Enikan lati di iranse awujo awon eyan, tabi iranse fun Orile-ede na Sugbon idi to wa ni pe, awon eyan fe d'oga aisan to wa niyen awon ton fe di Olori ijoba,, wan si wa pelu Orisirisi ọrọ " Ma s'eto Orile-ede wa dada, ma di iranse Ilu wa. Ejoo e dibo fun mi" Sugbon ero ta wa lokan wan nipe " bibakan tani tabi keji moma di Olori Ilu yi" maya leleyi je sugobn ti awa aba ni oye die sinu imoye na pe" Iranse nimo je... Koseni to le sowipe "Oga nimo je, Koseni to le sobe, ti eyan ba ronu bayi, maya niyen. otooro ko lo je.