YO/Prabhupada 0263 - Teba ti gba ilani yi dada, ema se iwaasu lo titi



Lecture -- Seattle, September 27, 1968

Prabhupāda: Beeni.

Madhudviṣa: Prabhupāda, kini asọtẹlẹ ti Caitanya nipa asiko Kali ti awon eyan ba korin Hare Krsna?

Prabhupāda: Beeni. Awon eyan.. gege bi awa tin se iwaasu Hare Krsna Ni Orile-ede kosi iwaasu kankan teletele Awa ti ran awonn akeko wa lati Orile-ede Europe, Germany, London- gbogbo wan tin se iwaasu nisin nkan ti awan se lati odun 1966 ati da egbe wa ni odun 1966, odun 1968 lawa bayi Ati ni ilosiwaju sugbon arugbo nimi mosi le ku teba si gba ilana ti mo fun yin, ke se iwaasu ni gbogbo agbaye O si rorun gan. Sugbon agbudo lo ogbon roi. Otan Awon eyan ton l'ogbon wan si gba iwaasu wa sugbon ti awan fe kan yanwan je, bawo ni wa sele ni igbala? nigbana oma soro lati le dawonloju sugbon awon ton ni okan toda,wan si gba imoye Krsna. Beeni

Jaya-gopāla: ti eyan ba fi awon nkan aye yi fi se ise fun Oluwa, se nkan na ma ya si mimo?

Prabhupāda: rara. Te ba lo agbara yin fi se nkan, nkan na ma ya si mimo Ti eyan ba fi iṣuu kọpa fi kan ina mọnamọna, isuu kopa na ba di ina. gege na ti eyan ban sse ise fun Krsna, lesekese oun na a ni iwa bi Krsna Iwe Bhagavad-gītā so wipe : māṁ ca 'vyabhicāreṇa bhakti-yogena yaḥ sevate. sevate. Sa guṇān samatītyaitān brahma-bhūyāya kalpate (BG 14.26). "Enikeni to ba s'ise funmi" lesekese lo ma kuro ni ipo ile-aye yi, asi wa sori ipo Brahman" Brahma-bhūyāya kalpate. teba si fi agbara yin fi s'ise fun Krsna se rope agbara ti aye yi wanbe? Rara gege bi awon eso. Elomi re rowipe Nibo ni Prasad wa? BAwo ni eleyi se je prasada, awon na man ra eso ni ile wa Rara. Nitoripe awa ti fi s'ebo fun krsna eso na ti ya si mimo Abajade na? Ti eyan ba je Krsna Prasad eyan na ma ni ilosiwaju ni imoye Krsna ti ologun ba fun yin ni ogun, ati ti eyin fun ara yin ba logun, ioyato ma wa Apeere imi ni bi awon nkan aye yi le di mimo fun apeere, ti enikan ma mu wara topoo ki inu bere sini runmo, asi lo ba ologun gege bi awon Veda se so, wan fun yin ni nkan to ni wara ounje lati wara lo je. Wara die pelu ogun na ma je ko tan aisan yin latin wara loti bere, wara na lo ma fi ipaari si kilode? nkan ti ologun so ni yen Gege na, gbobo nkan ni imoye to ga, kosi nkan to je nkan aye yi Laaro yi mo fun awon ni apeere Oorun pelu kurukuru nigbati kurukuru jade koseni to le ri Oorun awon eyan ti ogbon a sowipe, Ko s'oorun. kurukuru nikan lo wa" Eyan to logbon asi so wipe, Oorun ran sugbon kurukuru ti bo ooju wa" gege na,ti eyan ba ni oye pe gbogbo nkan aye wa labe agbara Krsna, kosi nkan to je t'aye yi Ironu okan wa pe afe di oga, itanran-ẹni eke niyen Nkan ton se idabo lori asepo wa pelu krsna die die Ele mo wipe Sevonmukhe hi jihvādau svayam eva sphuraty adaḥ (Brs. 1.2.234). Teba si ni ilosiwaju ninu ise na, gbogbo nkan a ye yin bi agabra yin se yaasi mimo.