YO/Prabhupada 0272 - Eto Bhakti gaju ounkoun ninu aye yi



Lecture on BG 2.7 -- London, August 7, 1973

Gege na, awon ise iranu ton se sugbon eyan to ba ni okan rere, Eyan na leni oye itumo aye ati bi asele gbe ninu aye yi Kini idi ile-aye yi, kilo opin re. Ati ni oye Brahman ni opin ile-aye yi Brahma jānātīti brāhmaṇaḥ. Nitorina awon brahmana niwa to da gege na awon ksatriya. guṇa-karma-vibhāgaśaḥ ni wan je Eyan gbudo mu Guna sinu iroyin na Nitorina Krsna sowipe: catur vārṇyaṁ mayā sṛṣṭaṁ guṇa-karma-vibhāgaśaḥ (BG 4.13). Gbogbo wa tini guna kan tabi ikeji. O si le gan Sugbon eyan le i idari lori awon guna na lesekese. Bawo na? pelu ilana bhakti Sa guṇān samatītyaitān brahma-bhūyāya kalpate (BG 14.26). teba si mu ise bhakti-yoga yi ni pataki, koni si anfanni mo lati awon amuye meta wanyi, okanrere, ìjánu, ati aimokan iwe Bhagavad gita no si so wipe: māṁ ca avyabhicāriṇī bhakti-yogena sevate. Enikeni toba sise fun Olorun avyabhicāriṇī, laisi iyapa, eyan bayi māṁ cāvyabhicāriṇī yogena, māṁ ca avyabhicāreṇa yogena bhajate māṁ sa guṇān samatītyaitān (BG 14.26). lesekese loma ni idari lori gbogbo awon amuye ile-aye Ise ifarafun Olorun ti koja awon amuye ile-aye yi. Wan ti di giga nkan aye yi ko ni bhakti je. Nitorina, kosi beyan sele ni oye Krsna laisi bhakti Bhaktyā māṁ abhijānāti (BG 18.55). bhaktyā māṁ abhijānāti nikan pere. bibeko, kolosese Bhaktyā māṁ abhijānāti yāvan yas cāsmi tattvataḥ. ni otooro, ti eyan ba fe ni oye nkan ti Olorun je eyan gbudo gba saye ilana bhakti Nigbayen ni eyan le ni idari lori gbogbo nkan. Nitorina,Ninu iwe Śrīmad Bhāgavatam, Narada so wipe tyaktvā sva-dharmaṁ caraṇāmbujaṁ harer (SB 1.5.17). Enikeni toba fi ise toye kose sile, ise ton ti pe fun... svadharma ni nkan tan pe iru iwa beyen...itumo Svadharma ni ise onikaluku gege bi iwa re seje. svadharma niyen wan si ti pin awon brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya, śūdra,pelu guṇa-karma-vibhāgaśaḥ (BG 4.13), Nibi Arjuna si wipe, kārpaṇya-doṣopahataḥ-svabhāvaḥ (BG 2.7). ksatriya nimo je Osi ye pe " Nkan timon se ko da. Mio fe jagun" nitorina, kārpaṇya-doṣa lo je. nkan alaun Eyan to lowo tio fe na owo na, alahun ni enina je, kṛpaṇatā. Ipo meji ni awan eyan bosi ninu aye yi, brāhmaṇa ati śūdra. Itumo brahmana ni wipe alaun ko lo je. Osini nkan to da gan ni ile-aye yi, ara eda- eniyan Iyi ti ara wa ni kosi aduro owo to lera. Sugbon ko si fe lo dada O telorun lati ma wo " Mo si lewa gan". Otan egbudo lo ara teni dada.. Nkan to je brahmana niyen