YO/Prabhupada 0276 - Ise Guru ni lati funwa ni Krishna, kole funwa ni awon nkan aye yi



Lecture on BG 2.7 -- London, August 7, 1973

Imoye to ye ke wa niyen. Bi eyan sele ri guru to daju ati bawo lo sele teriba fun Kon se pe, moni guru lati le ma beere nkan lowo re. " guru mi ejoo moni aisan bai bai, sele funmi ni . Beeni, wa gba> Iru guru yen ko, teba ni aisan e lo ba Ologun. ise guru ko ni lati fun awon eyan l'ogun Ise guru ni lati fun wa ni Krsna Kṛṣṇa sei tomāra, kṛṣṇa dīte pāra. Vaisnava kan si gbadura pe " Oga, elesin Krsna le je" " eyin nikan lo le funmi ni Krsna teba fe". Ipo sisya niyen Ise Guru nibo sele fun yin ni Krsna, kon se awon nkan aye yi Fun awon nkan aye yi, opolopo ile-ajo lon ti ko fun awon nkan bayi teba fe Krsna, egbudo ni guru. Taloye ko gba guru?

tasmād guruṁ prapadyeta
jijñāsu śreya uttamam
śābde pare ca niṣṇātaṁ
brahmaṇy upasamāśrayam
(SB 11.3.21)

Tani awon ton ye kon gba guru? ẹṣọ aṣọ ko ni guru je. " Mo fe gba guru, tabi mo fe di guru" eyan to se pataki ni itumo Guru Tasmād guruṁ prapadyeta. Eyan gbudo wa guru. fun kini? Jijñāsu śreya uttamam eyan to fe mo nipa Olorun Kon se pe ke so guru di eto-aso.. gege na kon sepe agbudo gba guru. guru koni yen " Guru gbudo se nkan ti mo ba fe". Bee ko Eni to le fun e ni Krsna itumo Guru niyen. Nitoripe Krsna ni guru je. Kṛṣṇa sei tomāra Wan si salaaye ninu Brahma-saṁhitā. Vedeṣu durlabhaṁ adurlabhaṁ ātma-bhaktau (Bs. 5.33). Vedeṣu durlabhaṁ. ti eyan ba fe wa idi re Niotooro Imoye ni itumo Veda, sugbon kosi Imoye to koja Krsna Vedaiś ca sarvair aham eva vedyam (BG 15.15). Ilana to wa niyen teba fe ka awon Vedas fun ara yin, awon asiwere kan wa Wan si sowipe" Ale ni oye Veda fun ara wa. Iru oye wo leni nipa Veda? Bawo lese fe ni oye na? Veda si sowipe tad vijñānārthaṁ sa gurum eva abhigacchet (MU 1.2.12). Se teba ra iwe Veda kan, se bi eyan sele ni oye Veda niyen?7 nkan alaiwọn ko ni Veda je Kosenikeni tole ni oye Veda laidi brahmana Nitorina, wan si ti fi ihamọ pe, lai di brhamana eyan ogbudo ka Veda Iranu lo je. Iru oye wo lefeni nipa Veda? Nitorina lehin igbati Vyasadeva paari pelu awon Veda merin, osi pin wan si merin. lati be ni Mahabharata ti jade Nitoripe oro Veda soro lati ni oye Strī-śūdra-dvija-bandhūnāṁ trayī na śruti-gocarāḥ (SB 1.4.25). fun awon obirin, awon śūdras, anti awon dvija bandhu Kosi bi wan sefe ni oye Veda Gege na gbogbo asiwere wanyi to je pe dvija-bandhu ati sudra lon je rara, ko le sese eyan gbudo ni awon iwa brahmana satyaṁ śamo damas titiksva ārjavaṁ jñānaṁ vijñānam āstikyaṁ brahma karma sva-bhāva... (BG 18.4) bibeko iru oye wo ni eyan ma ni nipa Veda? Iranu Nitorina Veda sowipe tad vijñānārthaṁ sa gurum (MU 1.2.12), eyan gbudo gba guru lati ni oye Veda Kini Veda? Vedaiś ca sarvair aham eva vedyam (BG 15.15) Itumo Veda ni wipe " agbudo ni oye Krsna" Ke si teriba fun. Imoye Veda niyen Nisin Arjuna ti sowipe " Moti teriba fun yin" Mio ni bayin soro mo bi egbe Nkan to da lo so, sugbon ironu t'aye yi niyen O si ronu wi pe praduṣyanti kula-striyaḥ (BG 1.40). Nkan t'aye yi niyen Sugbon imoye Veda ti mimo lo je, uttamam. Tasmād guruṁ prapadyeta jijñāsu śreya uttamam (SB 11.3.21). śreya leleyi. Uttamam. Yac chreya syāt niścitaṁ. idojukọ ko soro iyipada Krsna asi fu ni ilana nisin Sarva-dharmān parityaja mām ekaṁ śaraṇaṁ vraja. lehin na bahūnāṁ janmanām ante jñānavān māṁ prapadyate (BG 7.19).

Nitorina lati le ni ipo to gaju ni ile-aye yi eyan gbudo teriba fun Krsna tabi awon alabasepo re lehin na ile-aye re ani ilosiwaju. Ese pupo