YO/Prabhupada 0281 - Eranko ni eda eyan, sugbon eranko oniipin lo je



Lecture on BG 7.2 -- San Francisco, September 11, 1968

Yaj jñātvā neha bhūyo 'nyaj jñātavyam avaśiṣyate Itumo Bhūyo ni wipe ati mo gbogbo nkan tani lati mo. sugbon ibeere towa ni wipe kilode ti awon eyan oni oye nipa Krsna Ibeere to si daju niyen Krsna si ti daun ni ese-iwe to tele

manuṣyāṇāṁ sahasreṣu
kaścid yatati siddhaye
yatatām api siddhānāṁ
kaścin māṁ vetti tattvataḥ
(BG 7.3)

Manuṣyāṇāṁ sahasreṣu. Okurin merin ototo lowa. Gege bi ase mo nipa isogbe aye yi, sugbon lori awon isogbe-orun imi aimoye orisirisi okurin lowa. nibi tawa kojo si gan, Okurin at'Obirin towa nibi po gan sugbon gbogbo wan yato si ra wan teba si jade s'ita, orisirisi lo wa teba lo si Orile-ede imi - India, Japan, ati China - ema ri orisirisi nibe Nitorina iwe mimo sowipe, manuṣyāṇāṁ sahasreṣu (BG 7.3), laarin gbogbo awon orisirisi eyan to wa kaścid yatati siddhaye, iwonba die lon ni oye imoye aye yi.

Nitoripe eranko oniipin ni Okurin je. Eda oniipin ni Okurin je, sugbon eranko oniipin sugbon nkan toda ni aye Okurin ni wipe, o le se iyato laarin nkan to da ati eyi to buru Osi l'ogbon ju awon eranko lo Ni ojo eni, awon ile-eko ti di iranu, akeko ton fun awon eyan leni jo akeko fun awon eranko Itumo akeko eranko niwipe awon o mo ju kan jeun, kon se asepo laarin okurin ati obirin, kon si gbej ara wan.. Ka jeun, ka sun, kase asepo, ka si gbeja ara wa, nkan tema ri laarin awon erank niyen. Kosi iyato Wansi ni igbese lati gbeja ara wan, lati fi sun, lati fi ni asepo teyin ba fe ni asepo pelu iyawo yin, ema lo sinu yara to da, nibi ti eyan kankan osi sugbon awon aja ma se tiwan lori titi. sugbon abajade ibe nkankanna ni gege na nitoripe ale ni asepo ninu yara iyen o wipe awujo eyan ti ni ilosiwaju Ilaju awon eranko niyen, otan awon aja na le gbeja ara awon laarin awon aja teba si ro pe etini iwari awon agbara átọ̀mù lati fi gbeja ara yin, ilosiwaju ko niyen je igbese lati gbjea ara wa lo wa.

Itu si wẹwẹ ile-aye Okurin mani ilosiwaju toba le se ibeere nipa idi fun ile-aye re " Tani mo je? Tani mi? Se arami nimo je? Kilode timo se wa sinu aye yi? Iru awon ibeere bayi loye ko ni Aami iyato pataki tose iyato fun awon eyan niyen Nitorina, lesekese ti eyan ma beere " Tani mi? to ba si tesiwaju, nijokan asi pade Olorun Nitoripe nkankanna loje pelu Olorun, gege bi ayẹwo loje fun Olorun nitorina manuṣyāṇāṁ sahasreṣu (BG 7.3). Laarin aimoye orisirisi Okurin, iwonba die lole ni anfanni lati mo Olorun kon sepe kan mo nipa Olorun nikan, sugbon wa si mo nipa ara wan sugbon toba si fe mo ara re asi wa si Olorun