YO/Prabhupada 0285 - Ko s'elomi tele nife fun ju Krishna ati ile re Vrndavana



Lecture -- Seattle, September 30, 1968

Krsna sin ma losi agbegbe, awon gopi ma si wani-ile Obirin lon je.. koye ki awon Obirin sise. Asa veda niyen oye kon wa ni-ile, ki baba, ati Oko wan tabi Omo-okurin bale toju wan koye kon jade, nitorina wan si joko si-ile sugbon Krsna si wan ninu àgbegbe, awon gopi ton wa ni-ile wan man ronu nipa Krsna " Oh, ese Krsna rirọ gan" sugbon nisin on fese rin lori ilele to le gan se awon okuta oni se ese re lese adibiwipe asi ni irora ton ba ti ronu bayi, wan bere sini sunkun. Krsna si gina gon si-ile, sugbon gbogbo nkan ti Krsna ban se wan sin ronu nipa re Itumo ife gidi re Kon sepe wan bere lowo Krsna " Krsna kilo muwa leni?" Kilo wa lapo re? je kin wo" rara. wan kon ronu nipa Krsna, bawo ni Krsna a se ni itelorun. wan ma mura dada nitoripe... wan si loba Krsna pelu aso to da lorun. " Inu krsna a dun lati ri wa" Inu Okurin tabi Obirin asi dun toba ri ololufe re pelu aso to da nitorina awon obirin gbudo mura dada ni asa Veda, oye ki awon obirin mura lati le fun oko wan ni itelorun Asa veda niyen. Ti oko re o ba sini ile, obirin na ogbudo mura dada Proṣita bhartṛkā. Orisirisi aso lowa fun awon obirin teba si ri aso towo eyan le mo eni toje eyan le mo pelu aso pe Obirin na ko ti l'Oko Pelu aso to wa na, asile mo pe Obirin ti fe Oko Pelu aso na asile mo pe opo loje eyan sile mo pelu aso towo pe Asewo ni obirin na gege aso se pataki. Proṣita bhartṛkā. Mio ni soro lori awon nkan ile-aye yi awan soro nipa eto ife ti Krsna timotimo ni ibasepo larin Krsna ati awon gopi pe Krsna na si so wipe " eyin gopi, mio l'agbara lati dapa gbogbo ife teti fun mi Olorun ni Krsna sugbon Krsna si di onigbese osi sowipe " Eyin gopi mi ko le se se lati son pada gbogbo ife teni funmi" ife to gaju ni ile-aye yi niyen Ramyā kācid upāsanā vrajavadhū.

Mo kon salaaye ise apinfunni ti Caitanya Osi funwa ni awon ilana toye ka tele, o sofun wa pe, eyan kan pere loye kani ife fun. Krsna ni eni na pelu ile Vrndavan awon gopi si ni apeere awon eyan ton ni ife to gaju fun fun orisirisi elesin lowa, awon gopi si wa lori ipo to gaju sugbon laarin awon gopi, Rādhārāṇī lo gaju nitorina koseni to le ni ife ju Rādhārāṇī lo Ramyā kācid upāsanā vrajavadhū-vargeṇa yā kalpitā, śrīmad-bhāgavatam amalaṁ purāṇam lati le ni akeko nipa Ife si Olorun, ogbudo wa awon iwe mimo ton soro nipa re. Caitanya Mahāprabhu so wipe, śrīmad-bhāgavatam amalaṁ purāṇam. Iwe aini abawọn lori eto ife fun Oluwa ni Śrīmad-Bhāgavatam je kosi ibomi ton salaaye bayi lati ibeereni wan salaaye bi asele ni'fe Oluwa awon tonti ka iwe Śrīmad-Bhāgavatam,, ema ri pe ese kini ninu apa kan so wipe janmādy asya yataḥ, satyaṁ paraṁ dhīmahi (SB 1.1.1). Ibere na sowipe " Mosi fe fun ise ifarahan mi si Oluwa lat'eni ti gbogbo aye yi tini ibimo" Janmādy asya yataḥ. wan s'alaaye.. teba fe ko besel ni'fe Krsna oye ke ka Śrīmad-Bhāgavatam. Sugbon teba fe ni oye Śrīmad-Bhāgavatam oye ke ka Bhagavad-gita gege na eka iwe Bhagavad-gita lati ni oye iwa awon eda tabi eni ti Oluwa je pelu ibasepo taani pelu e. lehin teba ti ni oye pe " Beeni Krsna nikan soso ni Ololufe mi" Lehin na elebere sini ka Śrīmad-Bhāgavatam.. Ona atiwole ni Bhagavad-gita gege bi awon omo-ile iwe ma se aseyori ninu idanwo lati wole si ile-iwe giga Gege eyan gbudo ni aseyori ninu idanwo basele le mo Oluwa, toba ka Bhagavad gita lehin na keka Śrīmad-Bhāgavatam... ile-iwe giga niyen teba fe nkan to ju ile-iwe giga lo, eleka iwe awon akeko Caitanya.