YO/Prabhupada 0289 - Enikeni to wa lati odo metalokan - nkankanna ni wan



Lecture -- Seattle, September 30, 1968

Prabhupāda: klode?

Obirin: Se nkankanna ni Rama je pelu Jesu?

Elesin: Se nkankanna ni Rama je pelu Jesu?

Prabhupāda: nkankanna ko sugon wan jora. awa o le sowipe nkankanna lon je, sugbon wan jora

Obirin: wan jora.

Prabhupada: beeni lori ipo mimo, gbogbo nkan lo jora ninu ile-aye yi na, ounkooun teba mu, fun igba die ni sugbon ni ijoba orun, gbogbo nkan si wa ni mimo gege na ni Ijoba orun, Olorun ati Omo-Okurin re, ati Ore Olorun, ati Ololufe Olorun Ipo kanna lon wa. nitorina wan jora

Obrin: Sugbon ninu Orile-ede India lon bi Rama si sugbon ni Orilede-ede Europe lon bi Jesu si Okurin meji toyato sugbon nkankanna lon je

Prabhupada: Beeni. Lojojumoo Orun man ran lojojumo ni Orile-ede India, ati Europe,tabi America Se iyen sowipe, lati waon Orile-ede wanyi ni Orun ti wa?

Obirin: Rara. Nkan ti mo f so ni wipe...

Prabhupad:Nitorina? bose je niyen Imoye wa niyen, wanti ko wa pe Alalgbara ni Olorun je gege bi Orun na, eyan le ri lati gbogbo awon Orile-ede na ni gbogbo ile-aye yi, Orun kan pee lani Koseni tole sowipe " Orun America leleyi, tabi ti India gege na boya Jesu tabi Rama tabi Krsna, enikeni toba t'orun wa Nkankana ni wan. kosi yato sugon iyato towa niwipe ni Orile-ede yin iwonba Orun ton ran ko po sugbon ni ilu bi tawa, Orun si po gan Se iyen wipe iba Orun ti yipada? bi awon sen ri gba niyen oyi-oju aye ni orile-ede yin si kun gan nitorina roun ko le fibe ran nibi sugbon agbara orun sin wole gege bi Orile-ede se je, tabi isogbe-orun tewa, Olorun a si farahan wan, sugobn kosi yato Nibi eyin faso bora nitori otutu Sugbon Ni Orile-ede India Oru si po ga, awon eyan lo afefe kilode ti oyi-ojuaye yato si ara wan? Nitorina ounkooun ti Jesu, tabi Krsna tabi Rama ba so iyato ma wa gege bi ilu na se je, tabi awo eyan to wan be, iyato to wa ni yen Nkan tele ko omode, o le soro lati baba omo na A le fun omode lati mo nipa oro asepo laarin Okurin ati Obirin sugbon teba salaaye fun Okurin to dagba oma ye Omode na to ba si dagba oun na ma ni oye gege na kosi bi gbogbo sele ni oye gbogboo nkan ninu igba ototo ni wa si so awon iwe bibeli tabi Bhagavad-gita iyato wa ninu igba ton si fun wa Bibeko, nkankana ni imoye na Bibeli sowipe ka nife Olorun, Bhagavad-gita si so be, Kosi yato