YO/Prabhupada 0296 - Botilejepe wan kan Jesu Kristi , sugbon ko si yipada lori ipinnu re



Lecture -- Seattle, October 4, 1968

Eri si wa ninu Veda nipa Olorun Nigbogbo awon iwe mimo,eri si wa nipa Olorun tabi awon alabasepo re gege bi Jesu kristi, oun na si fun wa ni Oye nipa Olorun wan si fi ku pa sugbon ko yipada lori imoye to gbe wa gege na awa na ni eri lati awon Veda lati awon eyan pataki lehin na, tin ba sowipe kos'olorun, tabi Olorun ti ku" , iru okurin wo ni mo je? Esu lon huwa bayi. Awon nikan ni wan ko lati gba... Esu ni odi keji Budha, Eyan to l'ogon ni itumo Budha Ni iwe Caitanya-caritāmṛta, wa so wipe kṛṣṇa ye bhaje se baḍa catura. enikeni to bani ifarasi Krsna tosi niife re, tosi yin logo Ni ibere ijosin loje, l'opin ife ni Ijosin.

iti matvā bhajante māṁ budhā. Enikeni to mope Eledumare ni Krsna je

īśvaraḥ paramaḥ kṛṣṇaḥ
sac-cid-ānanda-vigrahaḥ
anādir ādir govindaḥ
sarva-kāraṇa-kāraṇam
(Bs. 5.1)

Sarva-kāraṇa: gbogbo nkan aye yi lo nidi ati eri teba fe wadi gbogbo nkan ayeyi ema paari si Krsna Sarva-kāraṇa-kāraṇam. Ati Vedānta says, janmādy asya yataḥ (SB 1.1.1). Kosi besele sowipe nkan dede da ara re. Iranu niyen Gbogbo nkan loni Orisun. Gbogbo nkan. Ogbon niyen ema ronu bi awon oni sayensi ni ojo eni iru imoye bayi ko sogbon nibe tinba bere lowo awon oni sayensi kini orisun nkan baibai, kosi bosele daun Oye ka wadi na... timio bale wadi fun arami, oye kin tele awon ton mo... Mahājano yena gataḥ sa panthāḥ (CC Madhya 17.186). Agbudo tele awon ācāryas teba je Onigbagbo etele Jesu Kristi Osowipe "Olorun nbe". Egba be Osiwipe "Nkan ti Olorun da niyen" "Osowipe Mosi fe ki iseda yi farahan, osi sele" awa na si gba bayi pe Oluwa lo da ile-aye yi Ninu Bhagavad-gita na Krsna sowipe ahaṁ sarvasya prabhavo (BG 10.8), "Emi ni Orisun gbogbo nkan" Olorun ni orisun gbogbo agbaye, Sarva-kāraṇa-kāraṇam: (Bs. 5.1)

Agbudo tele iwa awon eyan pataki ati ka awon iwe mimo oyeka tele iwa wan Imoye Krsna si rorun ati se. kosi isoro teba fe mo nipa Olorun wanti slaaye gbogbo nkan ninu Bhagavad-gita ati Śrīmad-Bhāgavata. wansi ti sallaye ninu Bibeli ati Koran Kolesi iwe mimo laisi Olorun sugbon nisin wansi ti da awon nkan sile sugbon nigbogbo awujo eda, eto Olorun wanbe oleyato si arawan nitori ilu tabi asiko sugbon ogbudo wa Oyeke ni oye nisin, jijñāsā. nitorina Vedānta-sūtra sowipe egbudo wadi nipa Olorun Iwadi na si se pataki gan