YO/Prabhupada 0298 - Eyan to l'anfaani ati sise fun Krishna, eyan bayi loni dúkìá to gaju



Lecture -- Seattle, October 4, 1968

Prabhupāda: se ni ibeere?

Viṣṇujana: bawo lasele sise fun Krsna?

Prabhupāda: pelu ijaya re (Erin, "Haribol") Teba ni anfanni lati sise fun Krsna, kosi dúkìá to dato Alaini opin ni Krsna. Iru ise wo ni eyan le sefun? Osi ni awon iranse tiolopin Ise wo lo fe lati emi at'eyin? Osi te arare lorun. Kosi ni iwulo fun isese kon kon sugbon teba fe sise fun, kole se ko ma gba. Ore-ofe re niyen bese l'anfaani to lati sise fun Krsna beenani, anfaani yi ma po si. Alainiopin Loje. oyeki anfanni teni lati di iranse na koma lopin. Gege na koni si idije. teba se sise si fun Krsna, gege na lase funyi logbon si se ti ri? Kosopin ni Ijoba Olorun na Kosopin si ise tele se, Anfanni lati sise na ni nkan to se pataki Tatra laulyam eka mūlyam. Idaun lati okanmi ko nimo fun yi, idaun ti Rūpa Gosvāmī ni mo fun yin O sowipe kṛṣṇa-bhakti-rasa-bhāvitā matiḥ krīyatāṁ yadi kuto 'pi labhyate: Eyin Okurin ati Obirin... Bawo nimo sele nife Krsna si.. Teba si ra eleyi, matiḥ," - Ogbon ni itumo re Ogbon to da niyen je, " bawo nimo sele di iranse Krsna.." Kṛṣṇa-bhakti-rasa-bhāvitā matiḥ.Itumo Matih ni Ogbon lati mo oe mo fe diiran se Krsna eba le ra iru okan bayi, ejo e fowo ra lesekese Ibeere toma tele niwipe " Elo lema ta? semo? Beeni mo ma, Elo loje? Laulyam, ANfanni lati se. Otan Laulyam ekaṁ mūlyam. " Na janma koṭibhis sukṛtibhir labhyate. Anfanni lati di iranse Krsna kosinibe lati aimoye ibimo teba si ni die ninu anfanni yi , "bawo nimo sele di irnase Krsna? Egbudo mowipe eyan to s'orire bieyin kosi iwonba die ninu anfanni yi " bawo ni mosele di Iranse Krsna?" O si dara ga. Krsna a fun yi l'ogbon.

teṣāṁ satata-yuktānāṁ
bhajatāṁ prīti-pūrvakam
buddhi-yogaṁ dadāmi tam...
(BG 10.10)

"Enikeni toban sise pelu ife fun Krsna, alisi iranu Krsna leni oye gbogbo nkan. Asi funi ni imoyelati to sara. " Omomi ese bai bai" Toba sise bayi kini abajade na? Yena mām upayānti te: Oma pada si jioba orun mi ere wo loma ni to ba losi be? Yad gatvā na nivartante tad dhāma paramaṁ mama (BG 15.6). Māṁ hi pārtha vyapāśritya ye 'pi syuḥ pāpa-yonayaḥ (BG 9.32). Duḥkhalayam aśāśvatam (BG 8.15). wan si po gan. Ejo e ka Bhagavad-gītā. e yin ma ni imoye nipa sayeni Oluwa. Imoye soso to wa fun awon eyan niyen.

Gege na anfanni lati di iranse Krsna ni nkan l'eyin gbudo ni. ki anfanni na si tobi si anfanni na si ma posi bi ife yi fun Krsna sen posi " Bawo nimosele sise fun Krsna?" latokan yin laisi agidi itumo re niwipe teyan obanife fun Krsna, bawo ni anfanni na ma posi? nkan tema finife Krsna si po gan. nialakoko Sravaṇaṁ kīrtanam. Sravaṇaṁ, igboran ati Orin kiko ke gboran nipa Krsna, nipa Bhagavad-gita, nipa Śrīmad-Bhāgavatam kesi korin. Ibere niyen. lehinna

śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ
smaraṇaṁ pāda-sevanam
arcanaṁ vandanaṁ dāsyaṁ
sakhyam ātma-nivedanam
(SB 7.5.23)

Awon ilana mesan wanyi asi funyin ni oye ema ni ilosiwaju ninu oye Krsna. Aye yin asini aseyori Se Ibeeremi wa? egbiyanju lati ni oye na kon se nkan tama se pelu agidi asi logobn, Krsna ti funwa logbon erori wo, teba fe ni oye nipa re ejeki ibeere yin funyin ni iranlowo lati mosi, ema saafile ibeere meji lowa. ti keji kole fun e ni iranlowo Teba fe salo, Krsna asi fun e ni iranlowo lati saalo teba si fe gba Krsna sokan, asi fun e ni iranlowo lati lese nkan meji ton sele niyen, e se bese fe si Ye yathā māṁ prapadyante tāṁs tathaiva bhajāmy aham (BG 4.11). gege bi iwa yin se wa gege na ni iranlowo Krsna ma wa Opolopo awon alakowe lofe gbagbe Krsna Ni apa Kesan ninu iwe Radhakrishnan, Krsna sowipe man-manā bhava mad-bhakto mad-yājī māṁ namaskuru (BG 18.65). itumo to fun si da, sugbon o sowipe ema teriba si Krsna. setiri bayi. Gbogbo anfani to se lati fi kowe na ti baje, bawo leyan sele gbagbe krsna teyan bafe gbagbe Krsna, Krsna na asi fun ni Ogbon latifi gbagbe re. Kosi beyan na sele ni oye Krsna sugbon teyan ba fe ranti Krsna, Krsna asi fun logbon lati ni oye nipa re Krsna niyen. eyan lese bose wun sugbon teba gbagbe krsna egbudo sise fun maya, sugbon teba nife Krsna maya ma saalo