YO/Prabhupada 0306 - We Should Submit Our Doubtful Questions



Lecture -- Seattle, October 2, 1968

Prabhupada: Se ibeere kankan wa? Lati awon eniyan apejo. Awa si fe ke biwa ni ibeere, teba ni ibeere kankan, nipa oun ta so, ele biwa. Tad viddhi praṇipātena paripraśnena sevayā (BG 4.34). Gbogbo nkan, teba fe ni oye na, Oyeka beere nipa awon nkan ti o ye wa. Se ri bayi. Kilode?

Okurin: Se'yan le ni imoye ti wan o le fi oro fi salaaye? tabi, se ibasọrọ kankan wa toje wipe, awa o le fi oro fi salaaye, toje wipe, bi ohun lasan lo je? Boya bi ohun oṁ. Se ibasoro kankan wa toje wipe eyin at'emi nikan lole ni oye nipa re, tabi laarin emi ati awon aburo okurin mi, tabi, gbogbo wa? Se iriri kankan wa toje wipe... Se nkan imi wa to ju gbogbo oro yi ten so?

Prabhupada: Beeni, Hare Krsna ni yen.

Okurin: Hare Krsna.

Prabhupad: Beeni.

Okurin: Sele salaaye si? Sele sofunmi be leyi seje? Bawo lasele se ni gbogbo igba? Bawo lasele soro ninu ede yi lai soro ninu ede-geesi nikan?

Prabhupada: A le da ohun ninu ede orisirisi. kosi nkankan to baje to baje wipe ninu ede Sanskrit lale da ohun si nikan. Ele se ohun yi ninu ohun geesi na. Se nkan tole niyen? Awon okurin yi, awon na man so ohun Hare Krsna yi. Kosi nkan to le nibe. Ohun ton jade ni nkan pataki. Koni nkankan lati se pelu eni to soro na. gege bi duuru, teba te ohun "dung" ma jade. Ko ba je omo-ilu America tabi India ton te tabi Hindu tabi Musulman, ohun kanna ni gbogbo wan. Gege na duuru yi, Hare Krsna, teba te, ohun re ma jade. Otan. kilode?

Okurin (2): Seyin man joko lati ṣaṣaro? Kileyin man se si okan yin to batin lo kakari? Seyin man ronu nkan? Seyin ma fi sori nkan tabi ema jeko rin lo bosefe?

Prabhupada: Nialakoko esofun mi kini itumo ṣaṣaro teyin so?

Okunrin (2): Ka joko jeje lai soro.

Prabhupada: Huh?

Tamala Krsna: Ka joko jeje lai soro.

Prabhupada: Ka joko jeje. Se iyen sese? Seyin roe nkan tale se niyen?

Okurin (2): Teba feti si nkan t'oakn yin ban so.

Prabhupada: Okan wan sisie ni gbogbo igba.

Okurin: a mabayin soro.

Prabhupada: bawo lesele joko jeje? Okan wan sa kaakiri. Seyin tini iriri kankan pe okan yin o sise mo teba joko sibi kan? teyin ban sun, okan yin sise. Ema ma laala. Ise okan wa niyen. Igbawo leyin wa mowipe okan wa ma dake?

Okurin(2): Nkan tin mofe moniyen.

Prabhupada: Beeni. gege na okan wa o le dake lailai. Egbudo fi okan yin si nkan. ṣaṣaro niyen.

Okurin (2): Ki lale fun lati se.

Prabhupada: Beeni. Krsna niyen. Agbudo gbokan le Krsna, Olorun gbogbo agbaye. Okan wa nikan ko lama fun ni ise se, sugbon gbogbo iye-ara wa na. Nitoripe okan wa n'sise pelu awon iye ara.