YO/Prabhupada 0315 - We are So Stubborn, We are Trying to Forget Krishna Again and Again



City Hall Lecture -- Durban, October 7, 1975

Eyin Okurin at'Obirin, mofe dupe lowo yin tesi wa si apejo wa yi. Emi ko nimo da egbe yi. Krsna fun ara re loda egbe na, lasiko to pe seyin. Lalakoko osi soror Bhagavad-gita yi fun orisa-orun. gege bi Apa- kerin iwe Bhagavad0gita se so,

imam vivasvate yogam
proktavan aham avyayam
vivasvan manave prahur
manur iksvakave 'bravit
(BG 4.1)
evam parampara-praptam
imam rajarsayo viduh
(BG 4.2)

Taba siro odun Ori-ojo Manu, iyen bosi Eggbaarun ogoji odun. Kasi sowipe egbaarun ogoji odun lehin, O soro Bhagavad-git ayi si orisa-orun, Vivasvan. Oruko orisa orun ni Vivasvan. Omo re ni Manu, Vaivasvata Manu... Omo re Iksvaku, eyan alakoko ninu ile-Oba Surya-vamsa, ninu ibe ni Oluwa Ramacandra ti wa, iksvaku... Gege na ele ri wipe o ti pe ti imoyr Krsna yi tin wa. Sugbon Krsna sowipe, evam parampara-praptam imam rajarsayo viduh (BG 4.2): " Teletele awon rajarsis man gba imoye yi lati awon agba Imoye Bhagavad-gita niyen. Sugbon Krsna sowipe yogo nasto parantapa. Nisin odun egberun marun seyin nigbati Krsna salaaye fun Arjuna lori ile-ogun Kuruksetra, kosi mo boya oye ko ja tabi rara, lati je ko ja, o soro yi fun. Odun egberun maarun seyin lo soro Bhagavad-gita yi. osi sowipe " Ilana ton fi fun oro yi teletele lati awon agba si eleomi ti daaru; Nitorin ni mosen tunso fun e, ki awon eyan ba le ko lati oro yi, imoye Krsna."

gege na ni odun egberun marun to koja, wan salaaye fun Arjuna, awa sini oror yi. Sugbon leyokan si , wan ti baaje. Nitoripe awon o gba lati on aton ye kon gba, wan ti baaje, nitorina lose daaru. Nitorina na, ni odun ogorun maarun seyin, Sri Caitanya Mahaprabhu na wa lati ko Bhagavad=gita yi bi elesin. Sri Caitanya Mahaprabhu, nkankana loje pelu Krsna. gege bi Krsna, Eledumare gbogbo aye, osi fun wan ni ilana toye ka tele, sarva-dharman parityajya mam ekam saranam vraja (BG 18.66), sugbon koye awon eyna. Nitorin nisin, ni odun ogorun marun tokoja, Oluwa Caitanya Mahaprabhu, Krsna fun ara re, si wa gege bu elesin fun ara. Gege na Caitanya Mahaprabhu ni Krsna. Awon iwe mimo ti salaaye nipa oro yi:

krsna-varnam tvisakrsnam
sangopangastra-parsadam
yajnair sankirtanaih prayair
yajanti hi su-medhasah
(SB 11.5.32)

Gege na egbe imoye Krsna yi, egbe Sri Caitanya Mahaprabhu loje. Krsna fun ara re ni Caitanya Mahaprabhu fun ara re. Gege na Krsna si ni ore-ofe to po fun awon eyan aye isisn. Osi fe kon wa sori ipo imoye Krsna Sugbon ijogobn wa po, awa o fe ranti re mo.