YO/Prabhupada 0330 - Everyone Individually Has to Take Care of Himself



Lecture on BG 1.26-27 -- London, July 21, 1973

Tawa ban rowipe mole wa lalaafia ninu ile aye yi, pelu iranlowo awujo timo wa, awon oremi, ife mi, ilu mi, oniselu mi ati ipo timoni," Rara, sa, kolese se. Kolese se. Egbudo toju ara yin. Awon nkan bi awujo,ore, ife, ile, ko sin nkna ton le se fun yin. Nitoripe ewa labe idimu maya. Daivī hy eṣā guṇamayī mama māyā duratyayā (BG 7.14).

prakṛteḥ kriyamāṇāni
guṇaiḥ karmāṇi sarvaśaḥ
ahaṅkāra-vimūḍhātmā
kartāham iti manyate
(BG 3.27)

ewa labe idimu maya, eyin o ni ominiran kankan. kode seni kankan to ni ominiran yi lati funyin nigbala. Kolese se. Moti fun yi ni apeere yi tele, teyan ban ko lati wa oko afefe. te fo lo lori afefe, sugbon teba ni isoro kankan, kosi oko- afefe kankan to le ranyi lowo. Otan niyen. Nitorina oni-wako afefe gbudo se jeje lati toju ara re. gege na niinu ile-aye yi gbogbo eyan gbudo toju ara re. basele fun ni ominira lowo idimu maya. Egbe imoye Krsna wa niyen. Oluko le ko yin logbon. acarya le ko yin logbon pe "bayi yi losele fi toju ara re." sugbon lati jeko bosi, owo re lowa. teba sise na bose ye, ema niigbala. Bibeko, ti acarya ba fun yin ni ilana teyin o ba se bawo lesefe nigbala? O le fu yin ni gbala pelu ilana re, atio ore-ofe, sugbon egbudo gba ke mu ni pataki. isoro ti Arjuna ni leleyi. Isoro gbogbo eyan. Dehāpatya-kalatrādiṣu. Dehāpatya. Ara wa nitumo Deha. Omode nitumo Apatya. Iyawo nitumo kalatra. Dehāpatya-kalatrādiṣv ātma-sainyeṣv asatsv api (SB 2.1.4). Awa sin ronu pe awon olopa mi ma toju mi. Moni awon omo-okurin, baba agba mi, baba iyawo mi, aburo iyawo mi, awon ore mi ati ife mi." Gbogbo eyna ronu " ilu mi, awujo mi, imoye mi, oniselu mi." Rara. Kosi nkankan tole fun yin nigbala. Dehāpatya-kalatrādiṣu asatsu api. Fun igba die lon wa fun. Wan ma wa wansi lo. Asatsu api. Pramatto tasya nidhanaṁ paśyann api na paśyati. Enikeni toba feran oror, awujo, ore ati ife, pramatta lo je. Were nitumo Pramatta. Paśyann api na, tasya nidhanam. Kole riran. On ro pe " baba mi ti ku. Nigbati to mo kere baba mi toju mi, nisin to ti ku talo ma toju mi? Se baba wa laaaye lati toju mi? Talon toju mi? Iya mi n'toju mi. Nisin talo n'toju mi? Mosi ni awon omo okurin ati obirin, iyawo mi, sugbon mosi fi wanle. Nisin talon toju mi? Niooto oro Krsna lon toju wa nigbogbo igba. KOn se awujo yin, tabi ore tabi ife teni. Gbogbo e loma tan.