YO/Prabhupada 0336 - How is it, They are Mad After God?



Lecture on SB 1.2.5 -- Aligarh, October 9, 1976

Nisin ewa ni orile-ede yi, teba wa losi India niaye to kan, nitoripe egbudo para ara yi, teba wa losi India nko. Ele tun pada wa ninu isogbe awon orisa tabi laarin awon eranko. Nitoripe ko daju. Krsna sowipe tathā dehāntara-prāptir. iparo ara wa nitumo iku. sugbon iru ara wo lema ri gba, awon agbara to gaju wa lo lon seto na. sugbon eyin na le seto na. Gege bi teba se dada ninu idanwa lati di Dokita, o daju pe ele di dokita, esi le ri ise ninu ile-ise iwosan ijoba, sugbon awon olori eto iwosan lon ma yonju oro na, orisirisi nkan low aninu e. Gege na ara to kan, eyin ko lema wa yen sile. Awon olori lon ma yonju iyen. Karmaṇā daiva netreṇa jantur dehopapattaye (SB 3.31.1). awa gan o mo, nkan taye w ato kan ma je. Awa osi fe niidamu lori oror na. Agbudo gba ara to kan laehin igba taba fi eleyi sile.

Nitorina agbudo sisie fun. Itunmo ise yi ninu Bhagavad-gita niwipe yānti deva-vratā devān (BG 9.25). teba sise lati losi awon ijoba orun bi Candraloka, Suryaloka, Indraloka, Svargaloka, Brahmaloka, Janaloka, Maharloka, Tapoloka - wan po gan, aimoye. Teba fe losibe, ele bere sini sise bayi. Yānti deva-vratā devān pitṟn yānti pitṛ-vratāḥ. teba fe losi Pitrloka, ele losibe. teba fe losodo awon orisa ele so sibe. teba si fe duro sibi, ele duro na. Teba si fe pada si Goloka, Vrndavana, mad-yājino 'pi yānti mām (BG 9.25). Ele pada sile, si ijoba Olorun. O sese. Krsna sowipe tyaktvā dehaṁ punar janma naiti mām eti (BG 4.9). teba fe ele pada si ile, si ijoba Olorun, o sese. Awon eyan to logbon gbudon mo. Tin ba lo si devaloka, kini ijeere pe mo losi be. Tin balosi Pitrloka, kini ijeere pe mo losi be. in ma duro sibi, kini ijeere na. Tinba si pada siile si ijoba OLorun, kini ijeere na." TEba le pada si ijoba Oloruna, Krsna ti salaaaye ijeere towa nibe. Ijeere niwipe tyaktvā dehaṁ punar janma naiti (BG 4.9), eyin o ni pada sinu ile-aye yi mo. Ijeere to gaju niyren. Punar janma naiti mām eti.

mām upetya tu kaunteya
duḥkhālayam aśāśvatam
nāpnuvanti mahātmānaḥ
saṁsiddhiṁ paramāṁ gatāḥ
(BG 8.15)

Pipe to gaju niyen. Wansi sowipe, sa vai puṁsāṁ paro dharmo yato bhaktir adhokṣaje (SB 1.2.6). teba fe pada losi ile si ijoba Olorun, yato bhaktir adhokṣaje. egbudo gba ona yi, bhakti. Bhaktyā mām abhijānāti yāvān yaś cāsmi tattvataḥ (BG 18.55). kosi bese femo nipa Krsna, tabi Olorun lati ona karma, jnana, yoga. Kosona kankan toma to lati monipa Krsna. Nitorina egbudo gba ilana ti Krsna rti funwa yi. bhaktyā mām abhijānāti yāvān yaśs cāsmi tattvataḥ (BG 18.55). Nitprina awa o kin wo nu awon Krsna lila afi tobaje pe awon elesin lonse. lodo awon olorin ko. ewo niyen je. Caitanya Mahaprabhu o se bayi ri. Nitoripe af Bhakit nikan lole fun wa ni ogbon ati fi ni oye nipa Krsna. Yato bhaktir adhokṣaje (SB 1.2.6). laisi Bhakti, kole sese. Eyan gbudo gba ona bhakti yi toba fe pada si ijoba orun. Egbe imoye Krsna wa leleyi.

Egbe imoye Krsna wa yi sin ko awon eyna bonsele ni ilosiwaju ninu eto ise ifarasi Olorun ati bonsele pada si Ijoba Olorun. Ise to le koniyen. O rorun gan. Tio ba rorun bawo ni awon omi-ilu Europe ati America se mu ni pataki? Nitoripe odami loju wipe odun mewa seyin kin to da egbe yi opolopo ninu wan o mo nipa Krsna. Nisin gbogbo wan ti d'elesin Krsna. oya awon alufaa kristiani gan loju. Ni ilu Boston, alufaa Kristiani kan jewo wipe, awon omo-okurin wanyi, lat'odo wa lontin wa, lati esin Kristianni ati Jew Ki egbe yi to bere wan o tie fe ri wa, tabi kon bere nipa Olorun tabi kon wa sii ile-Olorun. Wan koju si bomi. Nisin wan ti sa tele Olorun bi were, bawo loseje? Oya wan lenu. Kilode? Nitoripe wan ti gba ilana yi. Ilan yi se pataki gan. Bhakti ko kin se nkan afori ro, nkan tale se to daju ni. Yato bhaktir adhokṣaje. teba fe gba ona bhakti yi nkan afori ro ko. egbudo se bose so. Yato bhaktir adhokṣaje. Ilana to wa ni

śravaṇaṁ kīrtanaṁ viṣṇoḥ
smaraṇaṁ pāda-sevanam
arcanaṁ vandanaṁ dāsyaṁ
sakhyam ātma-nivedanam
(SB 7.5.23)