YO/Prabhupada 0338 - What is the Value of this Democracy? All Fools and Rascals



Lecture on BG 1.31 -- London, July 24, 1973

Catur-vidhā bhajante māṁ sukṛtina. mimo nitumo Sukṛtina awon ton daju ninu eto ile-aye yi nitumo Krti. Awon ton sise ninu eto mimo lon pe ni sukkrti. Ise meji lowa; ise elese ati ise mimo. awon ton losi ile-adura tabi ile-ajosin, " O Olorun funmi l'ounje, tabi Olorun funmi lowo," tabi Olorun gbami lowo isoro aye mi, awon eyan mimo lonje. Awon elese o le lo ba Olorun, Krsna. Na māṁ duṣkṛtino mūḍhāḥ, prapadyante narādhamāḥ (BG 7.15). Awon ipo eyan bayi lon kere ju, maya ti yo ogbon opolo ori wan kuro awon bayi o le teriba fun Olorun. Nitorina lon seje duskrtina, elese. Mimo ni Krsna je sugbon osi fe ki gbogbo jeere. Alebu to ni niyem, er Arjuna. Owo ebi re. Ofe ni idunnu pelu awon awujo, ore ati ife. Nitorina lose sowipe na kāṅkṣe vijayam. Nkan ton pe ni vairagya niyen. Śmaśāna-vairāgya. wan pe ni Śmaśāna-vairāgya. Itumo Śmaśāna-vairāgya niwipe ni orile-ede India awon Hindu man fina j'oku wan. gege na awon ebi oku a mulo si ibi ton ma fina jo, ghata, nigbaton ba fian jo, gbogbo eyan to wanbe ba ya si mimo fun igba die na: " Oh, bi ara yi seri niyen, a sise fun ara yi.Nisin oti tan. wan ti sun ni na, kini ijeere to wa nibe? Iru vairagya yi, wa nbe. Sugbon lesekese to ba kuro ni ghata yi, asi pada si gbogbo nkan ton se tele. ninu smasana, ni ibi ton sun oko niina, a yasi mimo. lesekese toba pada sile abere sini wa owo, bawo ni mose fe r'owo, bawo ni mose fe r'owo, bawo ni mose fe r'owo. Iru vairagya yi lon pe ni śmaśāna-vairāgya, fun igba die. Kole di vairagi. od e sowipe na kāṅkṣe vijayam: (BG 1.31) " Mio fe ni isegun. Mio fe nkan bayi bayi." Fun igba die ni gbogbo eleyi. idajo fun igba die leleyi. Awon eyan yi feran eto ebi. Wan le sowipe, mio fe idunnu yi, mio fe ipo to da, isegun, mio fe" Sugbon gbogbo nkan bayi lofe. gbogbo e lofe. Nitoripe ko mo nkan to wa ninu sreyas. Krsna ni sreyas. niotooro teyan ba ni Krsna, tabi imoye Krsna, lehin na o le sowipe " Mio fe " Kilode ton ma sobayi? Kasowipe mo ni ijoba temi. Semi nimoni ijoba na? Rara. Ijoba Krsna ni. Nitoripe Krsna sowipe bhoktāraṁ yajña-tapasāṁ sarva-loka-maheśvaram (BG 5.29). Oun ni oludari , mole je iranse asoju re. Krsna fe ki gbogbo wa ni imoye re.

Gege na ise Oba ni lati je ki gbogbo eyan ni imoye Krsna Lehin ale sowipe o sise dada. Nitoripe awon Oba o se bayi mo nitorina ni kosesi awon Oba mo. gege na ibikibi ti Oba ba wa, gege bi ilu-geesi, ti Oba na ba ni imoye Krsna, to si di asoju Krsna, gbogbo ijoba re ma yipada. Nkan ta fe niyen. Nkan ti egbe imoye Krsna yi wa fun niyen. Awa o feran oro ijoba onibo. Kini ijeere ijoba onibo? ode ati asiwere nigbogbo wan. Wan si dibo fun ode kan lati di Olri gbogbo wan Ko da fun awon eyan rara. Awa o si fe oro ijoba onibo yi,nitoripe awon eyan yi o leeko. Ti Oba ba leeko... Ilana Oba niyen. Gege bi Yudhiṣṭhira Mahārāja tabi Arjuna. gbogbo awon Oba Rājarṣi. wan oe wan ni Rājarṣi.

imaṁ vivasvate yogaṁ
proktavān aham avyayam
vivasvān manave prāha
manur ikṣvākave 'bravīt
(BG 4.1)

Evaṁ paramparā-prāptam imaṁ rājarṣayo viduḥ (BG 4.2). Rājarṣayaḥ. Raja, Oba, obanikan ko, sugbon rsi, eyan mimo, gege bi Mahārāja Yudhiṣṭhira tabi Arjuna. Eyan mimo lonje. Eyan lasan ko niwan, wan o kin se awon oba amoti yo " Mo lowo to po. Eje kin moti kin si gbe awon asewo." Kon sebe. rsi niwan. Oba to je rsi. Iru oba ta fe niyen, rajarsi. Inu awon eyan ma dun. owe kan wa ni ede Bengali wipe, rājara pāpe rāja naṣṭa gṛhiṇī doṣe gṛhastha bhraṣṭa. ninu aye grhastha, aye onile, ti iyawo re o ba da, koseni toma ni idunnu ni ile na,ninu aye grhastha, onile. gege ba ninu ijoba, ti Oba ban se iranu, gbogbo eyan to wa ma jiya. Isoro to wa niyen.