YO/Prabhupada 0356 - We are not Working Whimsically. We are Taking Authoritative Version from Sastra



Lecture at World Health Organization -- Geneva, June 6, 1974

Prabhupāda: Ise ijoba ni lati ri wipe gbogbo eyan ni ise ton se. Ijoba to da niyen. Pe koseni to wa lai nise se. Ilana Veda niyen. Wan si pin awujo na si merin: brāhmaṇa, kṣatriya, vaiśya, śūdra. ise ijba lo je lati wo boya awon brahmana sise wan, tabi ksatriya se ise ksatriya, gege Vaisya... Gege na ise ijoba ni lati waadi si awonn eyan tio ni ise se. Wan de wa ona abayo si.

Alejo: Awon eyan na lonsi wa ninu ijoba.

Prabhupada: Eh?

Alejo: Awon onile, awon ton lowo, wan si lohun ninu ijoba.

Prabhupada: Rara. Ijoba tio da niyen.

Alejo: Beeni, otooro lee so.

Prabhupada: Ijoba tio da niyen. Bibeko, ise ijoba ni lari riwipe gbogbo eyan nise se.

Alejo: Nkan temi duro de niyen, ijo ti egbe imoye Krsna yi ma di egbe to ma yi awon nkan pada ninu awujo wa.

Prabhupada: Beeni. Iyipada nla loma je, nitoripe, awon Omo-okuron America ati Europu wanyi ti gba ise yi, motin ko wan, wan de ti gba, Mo si rope awon omo-okurin America ati europu logbon, wan de mu eto na ni pataki. Nisin ati sise fun odun marun, si mefa ati fe si gbogbo agbaye. mosin beere... moti darugbo.mole ku. Teba mu ise yi nipataki, a tesiwaju, iyipada na masele. nitoripe awa o se nkan to huwa. Awan sin mu awon nkan lati sastra. Lati te awon iwe jade ni ise tani se. Alaye to po wa. Ton ba ka awon iwe wan yi, gbogbo e ninu wan. wanti pe wa ninu awon ile-iwe giga ni America wanti ka awon iwe yi, osi tewan lorun. awa sin gbianju lati te awon ijuwe akosile wanyi, ise to daju gan, Sugbon ti awon omo-okurin ati obirin ba mu ise na nipataki, iyipda ma tibe jade