YO/Prabhupada 0365 - Don't Make It (ISKCON) a Stool Society - Make It a Honey Society



Lecture on SB 1.5.9-11 -- New Vrindaban, June 6, 1969

Gege na Nārada Muni ti fun wa ni imoran pe " Dharmādayaś ca artha. "Eti pin gbogbo awon Veda si awon ede to rorun, Puranas, lati fun wa ni oye nipa gbogbo e, Afikun si awon Veda nitumo Purana, latile salaye nipa awon imoye Veda ni otito. Gbogbo awon eda laye yi wa labe awon amuye iseda orisirisi. Awon imi wa ninu okunkun, tabi aimokan. Awon imi wa ninu ikanra. awon imi wa ninu pipo aimokan ati ikanra. Awon imi si wa ninu ina, tabi ori rire. Inu ipo kan ko ni gbogbo wan wa. Ipo orisirisi awon eyan lo wa. Gege bi ile-ikawe Hayagriva, orisirisi iwe lowa lori eto imoye. sugbon teba loba eyan lasan, ema ri awon iwe iranu bi itan ati imoye nipa imo ako ati abo, bi itowo onikaluku se ri niyen. bi itowo onikaluku se ri niyen; itowo orisirisi lowa. Nitoripe awa ni orisirisi ipo awon eyan. Ama salaaye ninu ese-iwe keji O sowipe, Nārada Muni,

na yad vacaś citra-padaṁ harer yaśo
jagat-pavitraṁ pragṛṇīta karhicit
tad vāyasaṁ tīrtham uśanti mānasā
na yatra haṁsā niramanty uśik-kṣayāḥ
(SB 1.5.10)

On fi gbogbo awon iwe ti Vyasadeva ko fi wera wan, pelu imoye Vedanta gan. O sowipe eleyi ni vāyasaṁ tīrtham. Vāyasaṁ tīrtham. Vāyasam itumo re ni eye kuroo. ati ibi ti eye kuroo feran lati lo. seyin ti ri awon eye kuro? orile-ede India ni awon eye kuroo to po. Ni orilede yin, awon kuroo o fi be.. Sugbon ni India wan feran awon nkan iranu. Awon eye kuroo. ema ri wan ninu ile-idoti. wan yo gbogbo idoti yi jade wan de bere sini wa nkan toni ikunmu tabi awon nkan toti jeera. gege bi awon esinsin. Wan joko sori igbe. Mākṣikaṁ bhramarā icchanti. sugbon oyin yato. ninu awon eranko, eyin na leri iyato. Awon oyin o le wa sibi ti'gbe wa. awon esinsin na o le losi bi ti oyin wa. Gege na awon iyasoto wan yi wa ninu awon eye, aawon eranko, awon eda. kosi bi awon eyan lasan sefe wa sinu imoye Krsna. Seri bayi? Nitoripe wanti gba ikeko lati d'esinsin, wan feran igbe. Seri bayi? ikeko asiko tawayi fe ko awon eyan lati d'esinsin, lori igbe. ibi ko, imoye Krsna. Sugbon teba se ni ile-oyin. awon ton wa oyin wan riwipe "nkan leleyi je." Seri bayi? Ema je ko di awujo igbe. Seri bayi? ejeko di awujo t'oloyin. e fun awon eyan ton wa oyin laaye. Ema tan awon eyan je. Wan ma wa. Nisin Narada Muni sowipe " Eti ko awon iwe to po gan, nkan to da gan niyen. kini'di fun? dharmādayaḥ ni ero to wa leyin re. Eyin sin ko awon eyan ni awon ofin mimo." wan pe ogun, viṁśati, dharma-śāstrāḥ. Manu-saṁhitā, Ofin Parāśara Muni, awon asa awujo eda, orisirisi nkan. awon alufaa orisirisi lo ko awon iwe wanyi, sugbon Vyasadeva ti ko wan po lati le lo wan dada. kobale ye awon eyan. Oti salaaye awon iwe wanyi fun lilo gbogbo agbaye eda. bonsele yasi mimo, bonsele ni ilosiwaju ninu oro aje, bi wan sele ni oye nipa igbala, bonsele gbadun ara wan pelu iwa to da e wo inu awon iwe Vyasadeva, ema ri pe o soro lori orisiri nkan... Bi awon ton jeran nisin. Vyāsadeva ti fun wan ni ilana nkan ton ma se, ninu tāmasika-purāṇa, Purana fun awon eyan tio ma nkankan. Ko f'eyan kankan sile. O ti ko awon iwe yi to je pe, enikeni to ban ka wan.. Gege bi ile-iwe orisiri kilasi lowa ati awon iwe orisirisi lowa fun awon eyan wanyi. Gege na, Vyasadeva ti ko gbogbo Veda wanyi ni ona to da ton pe ni Puranas enikeni le gun ipo to gaju to ban ka awon iwe wanyi. Fun apeere awon eyan ton feran oti mimu, eran jije, ati imo ako ati abo - nitoripe awon nkan je bi asa adayeba. Loke vyavāyāmiṣa-madya-sevā nityā hi jantor na hi tatra codanā (SB 11.5.11). kosi di pe afe wa 'yan to ma ko wa. Koseni to ba wa'yan lati ko bonse ni asepo pelu obirin koseni to ma wa'yan loati ko bonsen m'oti. Seyin o ri awon ton moti, se lesekese lon d'abe? Kosejo ile-iwe eko giga lati m'oti.. tabi kon sowipe mu LSD yi bayi. Rara. Nkan adayeba loje. Lati m'oti, LSD,gāñjā, pān, oh, o rorun gan lati bere. Lati ni imo ako ati abo... Loke vyavāya... nkan adayeba loje. Lesekese lon sele. Kosejo.. Kini idi fu iwe kika lori awon eto wanyi? Ogbon to wa ninu iwe kole to. Sugbon awon eyan o mo. Nigbati Vyasadeva sowipe, eyin o gbudo ni asepo afi teyin ba ti se igbe yawo, itumo re niwipe agbudo ni ihamo. itumo re niwipe agbudo ni ihamo. Eyin o le se imo ako ati abo ni sekuse. Eyin ni iyawo kan tabi oko kan, ihamo na niyen je: lati ni omode nikan ni imo ako ati abo. Awon nkan to po. sugbon ihamo gbudo wa. Konsepe "nitoripe moti fe'yawo nisin moti ni ero fun imo ako ati abo." Rara,rara. Itumo igbeyawo ko niyen. Itumo igbeyawo ko niyen. Ihamo gbudo wa. Lati mu awon eyan wa sori ipo to gaju ni'di fun awujo Veda, sugbon wan gbudo fi ipaari si awon iwa iranu. Lesekese ko, sugbon die die. Gege na awon eyan ton feran eran jije. " O da be." Awon iwe mimo Veda sowipe, " O da. E le jeran. Sugbon e gbudo sebo pelu eranko na niwaju orisa Kali ke to je." Bayi awonn to feran eran jije o le ni ibanuje