YO/Prabhupada 0378 - The Purport to Bhuliya Tomare



Purport to Bhuliya Tomare

orin ti Bhaktivinode Ṭhākura ko nipa ona lati gba t'awa bafe teriba. Ati gbo orisirisi nkan to po nipa pe agbudo teriba. nibi awon orin wa tole ko wa basele teriba. Gege na Bhaktivinode Ṭhākura sowipe bhuliyā tomāre, saṁsāre āsiyā, " Olorun mi, moti wa sinu ile aye yi nitoripe mo gbagbe Olorun. latigba ti mo ti debi, moti jiya gan, aimoye igba seyin, ninu orisirisi ara eda. Gege na, moti wa teriba fun yin, mosi ti wa fun yin gbogbo iroyin ijiya mi sin yin. Ni alakoko mo bosinu oyun iya mi." Jananī jaṭhare, chilāma jakhona. " Nigbati mo wan be, mosi fun pa ninu apo oyn na, mosi gbe ninu oyun iya mi. Nigbana mosi ri yin. Lehin igbana, mi o si ri E mo. Nigbana mosi ri yi die. Nigbana mosi rowipe, "takhona bhāvinu, janama pāiyā, " Mosi rowioe nigbayi, mole jade kuro ninu oyun iya mi, Masi sise pelu gbogbo okan mi ninu ise Olorun, ma s'adura s'Olorun. Mio sini wa ninu ile-aye yi mo, nitoripe isoro re ti poju. nisin mofe sise fun yin, mofe sise ninu ise ifarafun Olorun, kin bale jade kuro ninu maya yi. Sugbon leyin igba ton bimi ton," janama hoilo, paḍi' māyā-jāle, nā hoilo jñāna-lava, "lesekese ti mo jade kuro ninu oyun iya mi, maya, agbara aimokan si mumi, mosi gbagbe pe mo wa ninu ipo to buru bayi, mosin gbadura pel'ekun s'Olorun, pe nigbayi tin ba jade moma sise fun. Sugbon gbogbo ogbon yi si sonu nigbaton bimi." Ipo to kan ni ādarera chele, sva-janera kole. " Lehin na mosi di omode gbogbo awon eyan sin fim sori ese wan, mosi rowipe, " Ile aye yi dara gan, gbogbo eyan feran mi." Lehin na mo rowipe, "Ile aye yi da gan." Ādarera chele, sva-janera kole, hāsiyā kāṭānu kāla. " Nitoripe kosi isoro kankan. Lesekese tin ba ni isoro die, gbogbo eyan loma sa wa ranmilowo. Mosi rowipe ile aye yi ma lo bayi titi. mosi lo asiko mi ni ilokulo pe mon rerin, erin yi si fun awon ebi mi ni'telorun wansi toju mi. Mosi rowipe " Ile aye leleyi." Janaki... janaka jananī-snehete bhuliyā, saṁsāra lāgilo. " Nigbana awon ebi mi si toju mi gan. Mosi rowipe ile aye yi da gan." Krame dina dina, bālaka hoiyā, khelinu bālaka-saha. " Die die mo da gba, mosi bere sini sere pelu awon ore mi, aye si dara nigba yen. Leyin igba die nigbati mosi l'ogbon wan fimi si ile iwe,. Mosi bere sini kawe gan. Lehin na, " vidyāra gaurave, bhrami' deśe deśe, dhana uparjana kori. " Mosi ni igberaga to po.. " Adajo ni Bhaktivinode Ṭhākura je. Wansi mu latibi kan sikeji. O sin salaaye ile aye re, vidyāra gaurave, " Nitoripe mosi keeko die, wansi mu mi lo latibikan sikeji, mosin pa owo to da. Mo bere sini rowipe, " Nkan to da leleyi." Vidyāra gaurave, bhrami' deśe deśe, dhana uparjana kori. Sva-jana pālana, kori eka-mane, " ise kan soso ti moni nigbayen ni lati toju ara mi, lati toju awon ebi mi, lati jeki inu wan dun. Ipinnu kan soso timo ni laye yi niyen nigbayen." Bārdhakye ekhona, bhakativinoda. Nisin Bhaktivinode Ṭhākura, niojo arugbo re, kāṇdiyā kātara ati, "Nisin moti riwipe moma fi gbogbo awon nkan wanyi sile, Masi fi wan sile, lati gba ara eda imi. Nitorina, mi o mo iru ara eda wo ti mole ni. Nitorina, mosen sukun, ibanuje si po lokan mi." Bārdhakye ekhona, bhakativinoda, kāṇdiyā kātara ati, " Ibanuje po lokan mi." Nā bhajiyā tore, dina bṛthā gelo, ekhona ki. " Lai s'adura si yin, lai sise fun yin, moti lo asiko mi ni ilokulo. Mio mo nkan timolese mo. Nitorina moti teriba."