YO/Prabhupada 0402 - The Purport to Vibhavari Sesa



Purport to Vibhavari Sesa

Orin Bhaktivinoda Ṭhākura leleyi. On bere lowo gbogbo awon eyan kon ji laaro kutu. Vibhāvarī śeṣa, ale ti tan, āloka-praveśa, ina orun ti jade, jisin egbodo dide. Nidrā chāri uṭha jīva, ema sun mo. Aye asa Veda niyen. Eyan ogbodo sun ju igba t'olrun ba jade. Ogbodo ji ki orun to jade. nkan to da fun ilera to da. Beena lesekese teyan ba kuro lori akete, eyan gbodo korin oruko mimo Olorun. nibi o ti fun wa nimoran, bolo hari hari, nisin ekorin Hare Krsna mantra, mukunda murāri, oruko orisirisi Krsna.

Itumo Mukunda ni eni ton funwa nigbala. Itumo Murari, Oruko Krsna, ni eni toje ota si esu tone ni Mura. Rāma ni oruko imi fun, Rāma, Kṛṣṇa. Hayagrīva, eda kanna pelu Krsna ni Hayagrīva. Beena Nṛsiṁha, Nara-hari, idaji-kiniun, idaji-okurin, Nṛsiṁha-deva. Vāmana, nṛsiṁha vāmana, śri-madhusūdana. Madhusūdana, Esu Madhu ati Kaiṭabha, won fe gbe Brahma mi lehin igba to pari iseda yi, sugbon won si pa won. Nitorina oruko imo fun Krsna ni Madhusudana. Oruko Madhusūdana yi si wa ninu Bhagavad-gītā nibi to po. Ota Madhu nitumo Madhusūdana.. Ore at'ota ni Krsna je. Ore loje si gbogbo wa, sugbon enikeni toba huwa ota si, asi sebi ota s'eni na. Kon se ota seni kankan, sugbon teyan ba fe ri b'ota, asi huwa bi ota si eni na. Pipe oro niyen. Awon esu fe ri Krsna bi ota, lati fun awon es ni itelorun, asi farahan si won bi ota won, lati pa won, lehin na asi fun nigbala. Itan akoko idaraya ti Krsna niyen, madhusūdana brajendra-nandana śyāma. Niotooro Olorun o l'oruko, nitori awon ise re ni awon oruko yi ti wa. Gege bi won se fun ni Madhusūdana nitori esu Madhu to pa.

beena, wan si mo bi brajendra-nandana, omo vraja, vṛndāvana, nitoripe o farahan bi omo Yasoda ati Nanda Mahārāja, brajendra-nandana. Śyāma, ara re si dudu, nitori na lon sen pa ni Śyāmasundara. Pūtanā-ghātana, kaiṭabha-śātana, jaya dāśarathi-rāma. beena nitoripe o fi ku pa esu Pūtanā, oruko si di pūtanā-ghātana. Itumo Ghātana, apaniyan. Kaitabha-śātana, oun lon yo gbogbo awon alebu lori ona wa. Jaya-dāśarathi-rāma. Nitoripe o pa Rāvaṇa,won yin logo,jaya dāśarathi. itumo Dāśarathi niwipe: Dāśaratha ni baba re, beena oun ni dāśarathi, dāśarathi-rāma. Yaśodā-dulāla govinda-gopāla. Omo iya Yasoda to dara nitumo Yaśodā-dulāla. Govinda-gopāla, oun ni oluso awon maalu, Govinda, ton fun awon maalu ni igbadun. Vṛndāvana-purandara, olori ile Vrnadavan. Oun lo fa gbogob eyan mora ni ilu Vrndavana. Rāvāṇāntakara gopī-priya-jana, osi nife to po fun awon gopi, gopi-priya. Rādhikā-ramaṇa, nitoripe O gbadun lati wa pelu Rādhārāṇī, nitorina ni oruko re se je Rādhikā-ramaṇa. Bhuvana-sundara-bara. Beena awon gopi to po sini ifarafun, itumo re niwipe gbogbo agbaye sini ifarasi. Koseni to lewa ju Krsna lo ninu agbaye yi tabi nibikibi, nitorina lon sen pe ni bhuvana-sundara-bara. Olori nitumo Bara. Rāvāṇāntakara, mākhana-taskara, gopī-jana-vastra-hari.