YO/Prabhupada 0404 - Take this Sword of Krishna Consciousness - Simply with Faith you Try to Hear



Lecture on SB 1.2.16 -- Los Angeles, August 19, 1972

Beena śuśrūṣoḥ, śuśrūṣoḥ śraddhadhānasya (SB 1.2.16). awon ton gboran pelu igbagbo, śraddhadhāna... Ādau śraddhā. laini igbagbo kosi besele ni ilosiwaju. Ibeere ile aye mimo niyen. Ādau śraddhā. Imoye Krsna yi sin lo dada nibi. O si da gan. Won waasu dada." Awon eyan sin yin ise wa logo. Taba si tesiwaju bayi, inu won ma dun siwa. Nkan ton oe ni'gbagbo niyen. Itelorun yi lon pa ni śraddhā, śraddhadhānasya. Ti awon eyan o ba tie paara po pelu wa, ton sowipe "Oh, o da gan.. awon eyan yi da gan." Nigbami ninu awon iwe iroyin awon eyan man ko wipe " awon Hare Krsna yi da gan.. Iru awon eyan tafe leleyi." riri awon eyan yi na da Teyan na o ba wa, ti ko ba gbo, to kon sowipe "O da gan. Iyen na da." Gege bi awonb omode, oun na sin gbiyanju lati dide pelu ohun isere re. mo riri. ati ibere aye. Boya eni na mo tabi ko mo, kosi nkan to baje. Moriri yi na ti to lati fun ni ile aye mimo. O si dara gan. Śraddhā. Ti awon eyan yi o ba funwa ni idamu, ton si ni ifarasi, " Oh, won se nkan to da..." Beena ilosiwaju iwa yi nitumo ilosiwaju ninu ile aye mimo, otan. Lori ipo orisirisi lowa.

Beena śuśrūṣoḥ śraddhadhānasya vāsudeva-kathā-ruciḥ. ninu ese iwe to koja, wanti salaaye, yad anudhyāsinā yuktāḥ. eyan gbodo sise, ton ronu nigba gbogbo. Ida niyen. Ida imoye Krsna te gbodo mu dani. Lehin na e le ni igbala. Ele ge awon sorapo pleu ida yi. Bawo lasele gba ida yi? Won ti juwe ilana na nibi, e gbiyanju lati gbo pelu igbagbo. ema ri Ida na gba. Otan. Niotooro,egbe imoye Krsna wa yi tin tesiwaju. Atin ri ida yi gba die die, lati igboran lasan. Nigbati mo bere egbe yi ni ilu New York gbogbo yin mo wipe mio ni ida kankan. Gege bi awon elesin imi, won ma mu iwe esin wonb loowo kan, ati Ida loowo keji: " E gba iwe esin yi, bibeko, ma ge ori yin kuro." Iwaasu imi to wa niyen. Emi na mosi ni ida temi sugbon iru ida bayi ko. Ida timo ni - lati fun awon eyan l'aye lati gbo. Otan.

Vāsudeva-kathā-ruciḥ. Beena lesekese tonba gba ruci... Ruci. Itowo nitumo Ruci. "Ah, iroyin nipa Krsna leleyi, mofe gbo." teba se bayi ema ri ida yi gba. Ida yi wa lowo yin. Vāsudeva-kathā-ruciḥ. ruci yi ma wa fun tani? Itowo yi? Nitoripe bi moti salaaye tele, gege bi itowo suga Gbogbo wa lamo wipe o dun, sugbon teba fun eni toni aarun jaundice lara, toba towo a koro lenu e. gbogbo wa la mowipe suga dun, sugbon arakurin yi to ni aarun, jaundice, suga ma koro lenu e. Gbogbo wa lamo bee. Oto oro ni. Beena ruci, ife okan lati gbo nipa vāsudeva-kathā, kṛṣṇa-kathā, awon eyan pelu aarun ile aye yi, kosi bonsele towo. ruci yi, itowo. lati ni itowo yi awon ise t'alakoko wa. Kini yen? T'alakoko ni riri: Nkan to da leleyi." Ādau śraddhā, śraddadhāna. Beena śraddhā, riri yi, ibeere leleyi. Lehin na sādhu-saṅga (CC Madhya 22.83). "Awon eyan yi, won korin ati won soro nipa Krsna. Eje kin lo joko kin gbo si." Nkan ton pe ni sādhu-saṅga. Awon ton pe ni olufokansi, agbodo ni asepo pleu won. Ipo keji leleyi. Bhajana-kriya ipo keta niyen. ti awon eyan bati ni asepo pelu awon olufokansi, lehin na won ma bere sini ronu pe, " Oye k'emi na di akeko?" Beena ati gba won ibẹwẹ, " Prabhupada, edakun eje kin di akeko si yin." Ibeere bhajana kriya niyen, Itumo Bhajana-kriyā niwipe awa sise fun Olorun. Ipo keta leleyi.