YO/Prabhupada 0408 - Ugra-karma Means Ferocious Activities



Cornerstone Laying -- Bombay, January 23, 1975

gege bi awa sen soro nipa awon ile-ise. wanti juwe awon ile-ise ninu Bhagavad-gita bi ugra-karma. Itumo Ugra-karma ni ise pelu iwa-ipa. lati ni ọna ijẹẹmu agbodo ni oun tale fi toju ara wa. Āhāra-nidrā-bhaya-mai... Awon ohun ini fun ara wa. Krsna ti salaaye wipe, annād bhavanti bhūtāni (BG 3.14). Ounje nitumo Anna - Awa o lese aimani. Annād bhavanti bhutani. Awa si leri awon ounje wanyi lori oko wa. Nibomi, Krsna salaye wipe, kṛṣi-go-rakṣya-vāṇijyaṁ vaiśya-karma svabhāva-jam (BG 18.44). Ale gbin ounje to po fun itoju ara wa, ile si po gan laye tawayi. Moti se irin ajo si gbogbo awon ilu ninu agbaye yi fun igba merinal. Ni odun mejo to koja seyin, moti se irin ajo si gbogbo ilu laye yi. Moti riwipe ile to po gan wa, ni pataki ni Africa, Australia ati America, asi le gbin ounje tole boo gbogbo agbaye yi lona mewa. Lona mewa. koni sejo pe ko s'ounje. Sugbon isoro towa niwipe ati pin ile yi, "Ile mi leleyi." Elomi a sowipe, " Ameria leleyi, ilu mi," " Australia leleyi, ilu mi "Africa leleyi, ilu mi," " India leley ilu mi." Eto " temi" ati " emi" Janasya moho 'yam ahaṁ mameti (SB 5.5.8). Itanra eni leleyi, pe "emi" ati " temi." " Ara mi nimi ati ohun elo mi leleyi." Nkan ni itanraeni ton pe ni itanra eni leleyi. tawa basi joko lori ipo itanra eni yi awa o da ju awon eranko lo.

yasyātma-buddhiḥ kuṇape tri-dhātuke
sva-dhīḥ kalatrādiṣu bhauma ijya-dhīḥ
yat-tīrtha-buddhiḥ salile na karhicij
janeṣu abhijñeṣu sa eva go-kharaḥ
(SB 10.84.13)

Maalu nitumo Go, ketekete nitumo kharah. awon ton rowipe ara won ni won, ahaṁ mameti (SB 5.5.8), kosi iyato laarin awon eyan wanyi ati keteket ati maalu, awon eranko. Nan ton sele niyen. Mio fe gba asiko to po lowo yin sugbon mofe gbiyanju lati fi ye yin, kini idi fun egbe imoye Krsna yi. Idi fun egbe imoye Krsna yi ni lati fun awon eyan nigbala, kon ma d'eranko, maalu tabi ketekete. Egbe wa niyen. Wanti da awujo wa sile.. Gege bi Bhagavad-gita se so, awujo awon eranko tabi ausra, awujo awon asura, pravṛttiṁ ca nivṛttiṁ ca janā na vidur āsurāḥ lo bere. Awon asura tabi esu won o mo bonsele fun ara won ni ilana lati de ipo aye to wa pipe, pravṛtti, ati nivṛtti, ati eyi to da ati eyi tio da fun wa. Ile aye eda... gbogbo wa lamo, " Eleyi da funmi, eleyi o da funmi." Beena āsurāḥ janā, awon ton j'esu won o mo, iyato laarin "nkan to da ati nkan tio da funmi." Pravṛttiṁ nivṛttiṁ ca janā na vidur āsurāḥ, na śaucaṁ nāpi cācāraḥ: "Kosi wipe won wa ni mimo, tabi pe won ni iwa to da." Na satyaṁ teṣu vidya...:" kosi oto oro kankan laye won." Iwa asura niyen. Ati gbo aimoye igba " asura," "awujo asura," " Awujo esu,". Ibere re leleyi.

pravṛttiṁ ca nivṛttiṁ ca
janā na vidur āsurāḥ
na śaucaṁ nāpi cācāro
na satyaṁ teṣu...
(BG 16.7)

Satyam, kos'oto kankan. Ipo kini aye ni aye brahmana. Satyaṁ śaucaṁ tapo. satyam ni ibere. Ninu aye awon asura kos'oto, awon eda lati ipo kini ninu awujo eda, awon brahmana, satyaṁ śaucaṁ tapo ni won, ati titikṣa ārjavaḥ āstikyaṁ jñānaṁ vijñānam. Ipo kini aye niyen. Beena egbe imoye krsna wa, fe da ipo awon okurin lati ipo kini, Okurin lati ipo kini pelu satyaṁ śaucaṁ tapo śamaḥ damaḥ titikṣaḥ. Awujo awon eyan pelu iwa mimo. Orile-ede India si le fun gbogbo agbaye ni'wa mimo yi. Anfanni India to dara niyen. Nitoripe ni awon Orile ede n'ita India, āsuri-janā and ugra-karma ni gbogbo won. Awon ile-ise ati awon ugra-karma ti wa lati awon ilu geesi. sugbon awon eyan o le ni idunnu kankan bayi. wanti salaaye ninu ori iwe merin-le logun ninu iwe Bhagavad-gita. Duṣpūra akaṅkṣa. Kosi bi ife okan won sele ni itelorun pelu ilosiwaju ile aye. Won o mo. Won ti gbagbe. Beena awa ti yan ilu Bombay. Bombay ni ilu ni India toni ilosiwaju ju awon ilu toku lo. Awon eyan nibi si da, wansi feran nkan esin. Wansi l'ola gan. wan le gba nkan wanyi ni pataki. Nitorina mofe da egbe wa nibi, Bombay, lati pin egbe imoye Krsna yi kakiri. botilejepe isoro to po ti wa ninu anfaani mi, sugbon ise Krsna loje. Asi ni ilosiwaju ijokan. Ipile ile yi, lati odun meji seyin lonti se, sugbon isoro to po gan wa lati asura jana. Nisin, bakana tabi keji, ati ni itura die lowo awon isoro wanyi. beena awa ti wa bere kiko ile-ajosin yi loni toje ojo to dara, inu mi si dun pe eti wa ranwa lowo.